Oníṣe:Demmy/Sandbox/AyokaOse

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Africa (orthographic projection).svg

Áfríkà ni orile keji titobijulo ati toni awon eniyan julo lagbaye leyin Asia. Ni bi 30.2 egbegberun km² (11.7 million sq mi) lapapo mo awon erekusu to sunmo, ile re je 6% apapo gbogbo oju Aye ati 20.4% gbogbo ile Aye. Pelu egbegberunkeji kan eniyan (ni 2009, e wo tabili) ni awon agbegbe 61, eyi je bi 14.72% gbogbo iye eniyan Agbaye. Ni ariwa re ni Okun Mediterraneani wa, si ariwailaorun re ni Ilaodo Suez ati Okun Pupa wa legbe Sinai Peninsula, si guusuilaorun re ni Okun India, ati si iwoorun re ni Okun Atlantiki wa. Afrika ni orile-ede 54 lapapo mo Madagascar, opolopo erekusu ati orile-ede Olominira Sahrawi Arabu Toseluaralu, to je omo egbe Isokan Afrika botilejepe Morocco lodi si eyi.

Afrika, agaga gbongan apailaorun Afrika, je gbigba lopolopo latowo awon awujo onisayensi pe ibe ni ibi ti awon eniyan ti bere ati Hominidae clade (great apes), gege bi o se han pelu iwari awon hominids pipejulo ati awon babanla won, ati awon ti won wa leyin won ti won peju bi odun legbegberun meje seyin – lapapomo Sahelanthropus tchadensis, Australopithecus africanus, A. afarensis, Homo erectus, H. habilis and H. ergaster – pelu eyi to pejulo ninu won Homo sapiens (eniyan odeoni) ti o je wiwari ni Ethiopia to je odun bi 200,000 seyin.

Afrika bo ibiagedemeji mole, o si ni orisirisi awon agbegbe ojuojo; o je orile kan soso to gun lati agbegbe apaariwa aloworo de apaguusu alaworo.

Afri ni oruko awon eniyan ti won gbe ni Ariwa Afrika leba Carthage. Oruko awon wonyi je siso mo "afar" ti awon Finiki, to tumosi "eruku", sugbon ero 1981 kan ti so pe o wa lati oro ede Berber ifri tabi Ifran totumosi "iho", ni tokasi awon ti ungbe inuiho ni oruko Banu Ifran lati Algeria ati Tripolitania (Eya Berber ti Yafran).

Labe ijoba awon Ara Romu, Carthage di oluilu Igberiko Afrika, to tun je kikomo apa eba odo Libya oni. "-ka" ("ca") to je ilemeyin Afrika je awon Ara Romu to tokasi "orile-ede tabi ile". Bakanna, ile-oba Musulumi ayeijoun Ifriqiya to wa leyin, ti a mo loni bi Tunisia, na tun lo iru oruko yi. (ìyókù...)Máápù Áfríkà

Áfríkà ni orílẹ̀ kejì tótóbijùlọ àti tóní àwọn ènìyàn jùlọ láàgbáyé lẹ́yìn Ásíà. Pẹ̀lú ààlà ilẹ̀ tó tó 30.2 ẹgbẹgbẹ̀rún km² (11.7 ẹgbẹgbẹ̀rún sq mi) lápapọ̀ mọ́ àwọn erékùṣù tó súnmọ́ ibẹ̀, ilẹ̀ rẹ̀ jẹ́ 6% nínú àpapọ̀ gbogbo ojúde Ayé ati 20.4% gbogbo ile Aye. Pẹ̀lú ẹgbẹgbẹ̀rúnkejì 1 eniyan (ní ọdún 2009, ẹ wo tabili) nínú àwọn agbègbèilẹ̀ 61, èyí ṣàṣirò fún 14.72% gbogbo iye àwọn ènìyànÀgbáyé. Ní àríwá rẹ̀ ni Òkun Mẹditéránì wà, sí àríwáìlàorùn rẹ̀ ni Ìladò Suez àti Òkun Pupa wà nítòsí Sìnáì, sí gúsùìlaòrùn rẹ̀ ni Òkun Índíà, àti sí ìwọ̀ọrùn rẹ̀ ni Òkun Atlántíkì wà. Áfríkà ní àwọn orílẹ̀-èdè 54 lápapò mọ́ Madagáskàr, ọ̀pẹ̀ erékùṣù àti Orílẹ̀-èdè Olómìnira Áràbù Sàhráwì, tó jẹ́ ọmọẹgbẹ́ Ìṣọ̀kan Áfríkà bótilẹ̀jẹ́pẹ́ Mòrókò lòdì sí èyí.

Áfríkà, àgàgà àringbàngàn apáìlàorùn Áfríkà, jẹ́ gbígbàgbọ́ gidigidi ní àwùjọ sáyẹ́nsì bíi orísun àwọn ọmọnìyàn àti ẹ̀ka ẹ̀dá Àwọn Irúọmọnìyàn (Hominidae) (àwọn Òbọ Únlá), gẹ́gẹ́bí ó ṣe hàn pẹ̀lú ìwárí awon irúọmọnìyàn àtètèjùlọ àti àwọn babaúnlá wọn, àti àwọn tí wọ́n wá lẹ́yìn wọn tí wọn jẹ́ bíi ẹgbẹgbẹ̀rún méje ọdún sẹ́yìn – lápapọ̀mọ́ Sahelanthropus tchadensis, Australopithecus africanus, A. afarensis, Homo erectus, H. habilis and H. ergaster – pẹ̀lú Homo sapiens (eniyan odeoni) àtètèjùlọ tó jẹ́ wíwárí ní Ethiopia tó jẹ́ ọdún bíi 200,000 sẹ́yìn.

Áfríkà fẹ̀ kákiri orí agedeméjì, ó sì ní ọ̀pọ̀ àgbègbè ojúọjọ́ ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀; òhun ni orílẹ̀ kan soso tó gùn láti ibi alọ́wọ́rọ́ apáàríwá dé ibi aláwọ́rọ́ apágúsù.

Afri ni orúkọ àwọn ènìyàn tí wọ́n gbé ní Àríwá Áfríkà nítòsí Kártágò. Àwọn wọ̀nyí tanmọ́ "afar" èdè àwọn Finísíà, tó túmòsí "eruku", sùgbọ́n àbárò 1981 kan ti sọ pé ó wá láti ọ̀rọ̀ èdè àwọn Berber ifri tabi Ifran tótúmọ̀sí "iho", láti tókasí àwọn tí úngbé inúihò. Áfríkà tàbí Ifri tàbí Afer ni ọrúkọ Banu Ifran láti Àlgéríà àti Tripolitania (ẹ̀yà Berber ti Yafran).

Lábẹ́ ìjọba àwọn ará Rómù, Kártágò di olúìlú Ìgbèríko Áfríkà, tó tún jẹ́ mímúpọ̀mọ́ apá etíomi Líbyà òní. Àlẹ̀mẹ́yìn "-ka" ("ca") àwọn ará Rómù tókasí "orile-ede tabi ile". Ilẹ̀ọba àwọn Musulumi Ifrikiya tó wá lẹ́yìn rẹ̀, Tùnísíà òdeòní, náà tún lo irú orúkọ yìí.

Áfríkà àṣiwájú aláàmúsìn ṣe é ṣe kí ó ní orílẹ̀ìjọba àti ìṣèjọba ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ tó ju 10,000 lọ, tí wọ́n ní oríṣiríṣi irú àgbájọ olóṣèlú àti ìjọba. Nínú àwọn wọ̀nyí ni àdìpọ̀ abáratan kékeré àwọn aṣọdẹ bíi àwọn San ní apágúsù Áfríkà; titobi, awon adipo adimule bi awon idipo ibatan ebi awon elede Bantu ni apaarin ati apaguusu Afrika, awon adipo ibatan adimule gidigidi ni Ibi Iwo Ori Afrika, awon ileoba Saheli titobi, ati awon ilu-orilejoba ati awon ileoba aladawa bi ti awon Yoruba ni Iwoorun Afrika, ati awon ilu oja etiodo awon Swahili ni Ilaorun Afrika. (ìyókù...)Máápù Áfríkà

Áfríkà ni orílẹ̀ kejì tótóbijùlọ àti tóní àwọn ènìyàn jùlọ láàgbáyé lẹ́yìn Ásíà. Pẹ̀lú ààlà ilẹ̀ tó tó 30.2 ẹgbẹgbẹ̀rún km² (11.7 ẹgbẹgbẹ̀rún sq mi) lápapọ̀ mọ́ àwọn erékùṣù tó súnmọ́ ibẹ̀, ilẹ̀ rẹ̀ jẹ́ 6% nínú àpapọ̀ gbogbo ojúde Ayé ati 20.4% gbogbo ile Aye. Pẹ̀lú ẹgbẹgbẹ̀rúnkejì 1 eniyan (ní ọdún 2009, ẹ wo tabili) nínú àwọn agbègbèilẹ̀ 61, èyí ṣàṣirò fún 14.72% gbogbo iye àwọn ènìyànÀgbáyé. Ní àríwá rẹ̀ ni Òkun Mẹditéránì wà, sí àríwáìlàorùn rẹ̀ ni Ìladò Suez àti Òkun Pupa wà nítòsí Sìnáì, sí gúsùìlaòrùn rẹ̀ ni Òkun Índíà, àti sí ìwọ̀ọrùn rẹ̀ ni Òkun Atlántíkì wà. Áfríkà ní àwọn orílẹ̀-èdè 54 lápapò mọ́ Madagáskàr, ọ̀pẹ̀ erékùṣù àti Orílẹ̀-èdè Olómìnira Áràbù Sàhráwì, tó jẹ́ ọmọẹgbẹ́ Ìṣọ̀kan Áfríkà bótilẹ̀jẹ́pẹ́ Mòrókò lòdì sí èyí.

Áfríkà, àgàgà àringbàngàn apáìlàorùn Áfríkà, jẹ́ gbígbàgbọ́ gidigidi ní àwùjọ sáyẹ́nsì bíi orísun àwọn ọmọnìyàn àti ẹ̀ka ẹ̀dá Àwọn Irúọmọnìyàn (Hominidae) (àwọn Òbọ Únlá), gẹ́gẹ́bí ó ṣe hàn pẹ̀lú ìwárí awon irúọmọnìyàn àtètèjùlọ àti àwọn babaúnlá wọn, àti àwọn tí wọ́n wá lẹ́yìn wọn tí wọn jẹ́ bíi ẹgbẹgbẹ̀rún méje ọdún sẹ́yìn – lápapọ̀mọ́ Sahelanthropus tchadensis, Australopithecus africanus, A. afarensis, Homo erectus, H. habilis and H. ergaster – pẹ̀lú Homo sapiens (eniyan odeoni) àtètèjùlọ tó jẹ́ wíwárí ní Ethiopia tó jẹ́ ọdún bíi 200,000 sẹ́yìn.

Áfríkà fẹ̀ kákiri orí agedeméjì, ó sì ní ọ̀pọ̀ àgbègbè ojúọjọ́ ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀; òhun ni orílẹ̀ kan soso tó gùn láti ibi alọ́wọ́rọ́ apáàríwá dé ibi aláwọ́rọ́ apágúsù.

Afri ni orúkọ àwọn ènìyàn tí wọ́n gbé ní Àríwá Áfríkà nítòsí Kártágò. Àwọn wọ̀nyí tanmọ́ "afar" èdè àwọn Finísíà, tó túmòsí "eruku", sùgbọ́n àbárò 1981 kan ti sọ pé ó wá láti ọ̀rọ̀ èdè àwọn Berber ifri tabi Ifran tótúmọ̀sí "iho", láti tókasí àwọn tí úngbé inúihò. Áfríkà tàbí Ifri tàbí Afer ni ọrúkọ Banu Ifran láti Àlgéríà àti Tripolitania (ẹ̀yà Berber ti Yafran).

Lábẹ́ ìjọba àwọn ará Rómù, Kártágò di olúìlú Ìgbèríko Áfríkà, tó tún jẹ́ mímúpọ̀mọ́ apá etíomi Líbyà òní. Àlẹ̀mẹ́yìn "-ka" ("ca") àwọn ará Rómù tókasí "orile-ede tabi ile". Ilẹ̀ọba àwọn Musulumi Ifrikiya tó wá lẹ́yìn rẹ̀, Tùnísíà òdeòní, náà tún lo irú orúkọ yìí.

Áfríkà àṣiwájú aláàmúsìn ṣe é ṣe kí ó ní orílẹ̀ìjọba àti ìṣèjọba ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ tó ju 10,000 lọ, tí wọ́n ní oríṣiríṣi irú àgbájọ olóṣèlú àti ìjọba. Nínú àwọn wọ̀nyí ni àdìpọ̀ abáratan kékeré àwọn aṣọdẹ bíi àwọn San ní apágúsù Áfríkà; àwọn àdìpọ̀ dídìmúlẹ̀ bi awon asọèdè Bantu ní àringbàngàn àti apágúsù Áfríkà, àwọn àdìpọ̀ abáratan dídìmúlẹ̀ gidigidi ní Ibi Ìwo Orí Áfríkà, àwọn ileoba Ṣàhẹ́lì gbàngbà, àti àwọn ìlú-orílẹ̀-èdè aládàáwà àti àwọn ilẹ̀ọba bíi ti àwọn Yorùbá ní Ìwọ̀orùn Áfríkà, àti àwọn ìlú ọjà etíomi àwọn SwahiliIlaorun Afrika. (ìyókù...)Àwòrán Júpítérì

Júpítérì ni plánẹ̀tì karùún láti ọ̀dọ̀ Òrùn àti plánẹ̀tì tótóbijùlọ nínú Sístẹ̀mù Òrùn. Ó jẹ́ òmìrán ẹ̀fúùfù tó ní ìsúpọ̀ tó fi díẹ̀ dín ju ìkan-nínú-ìdálẹ́gbẹ́rùún ìsúpọ̀ Òrùn lọ sùgbọ́n ìsúpọ̀ lọ́nà méjì àti àbọ̀ ti ìsúpò gbogbo àwọn plánẹ̀tì yìókù nínú Sítẹ̀mù Òrùn lápapọ̀. Júpítérì jẹ́ kìkósọ́tọ̀ bíi òmìrán ẹ̀fúùfù lápapọ̀ mọ́ Sátúrnù, Úránù àti Nẹ́ptúnù. Lápapọ̀, àwọn plánẹ̀tì mẹ́rẹ̀rin yìí jẹ́ pípè nígbà míràn bíi plánẹ̀tì Jofia.

Àwọn atòràwọ̀ ayéijọ́un mọ Júpítérì, bẹ́ ẹ̀ sìni ó jẹ́ gbígbà nínú ẹ̀sìn àti àṣà àwọn ènìyàn ìgbà náà. Àwọn ará Rómù sọ orúkọ rẹ̀ fún òsa Rómù tó únjẹ́ Júpítérì. Láti Ayé, Júpítérì le ní ìhàn ìtóbi −2.94, èyí só di ohun tómọ́lẹ̀jùlọ kẹta ní ojúsànmọ̀ àṣálẹ lẹ́yìn Òsùpá àti Àgùàlà. (Mársì áà le mọ́lẹ̀ bíi Júpítérì fún ìgbà díẹ̀ tó bá wà ní ààyè kan pàtó lórí ojúọ̀nàìyípo rẹ̀.)

Júpítérì jẹ́ ṣíṣàjọsínú pẹ̀lú háídrójìn tí ìkan-nínú-ìdámẹ́rin ìsúpọ̀ sì jẹ́ hélíọ̀m; bákannáà ó tún ṣe é ṣe kó ní inúàrin oníàpáta apilẹ̀sè wíwúwo. Nítorípé ó ún yírapo kíákíá, àwòrán Júpítérì jẹ́ bíi òbìrìkìtì afẹ̀lẹ́ẹ̀gbẹ́ (ó wú díẹ̀ síta ní agedeméjì rẹ̀). Afẹ́fẹ́ojúọ̀run òde rẹ̀ jẹ́ yíyàsọ́tọ̀ sí orísirísi ẹ̀gbẹ́ ní ojúibigbọọrọ ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀, tó ún fa ìjì àti ìṣe rudurudu lẹ́ẹ̀gbẹ́ àwọn bodè tó únkanra wọn. Esi eyi ni Great Red Spot, iji omiran kan to ti je mimo lati orundun 17k nigbati o koko je riri pelu teleskopu. To yika planeti yi ni sistemu oruka planeti ati igberinojuorun alagbara. Be si tun ni o ni awon osupa 63, ninu won ni awon osupa gbangba merin ti won unje awon osupa Galilei ti won koko je wiwari latowo Galileo Galilei ni 1610. Ganymede, eyi totobijulo ninu awon osupa yi ni diamita totobiju planet Mercury lo.

Júpítérì ti je wiwakiri ninu lopolopo igba pelu oko-ofurufu roboti, agaga nigba awon iranlose ifokoja Pioneer ati Voyager ati leyin won pelu Galileo orbiter. Oko iwadi to pese lo si Júpítérì ni oko-ofurufu to unlo si en:Pluto, en:New Horizons ni opin February 2007. Oko iwadi yi lo iwolura lati odo Júpítérì lati fun ni isare pupo. Awon iwakiri ojowaju ninu sistemu Jofia ni wiwa omi ti tinyin bo mole ninu osupa Europa. (ìyókù...)Máápù Áfríkà

Áfríkà ni orílẹ̀ kejì tótóbijùlọ àti tóní àwọn ènìyàn jùlọ láàgbáyé lẹ́yìn Ásíà. Pẹ̀lú ààlà ilẹ̀ tó tó 30.2 ẹgbẹgbẹ̀rún km² (11.7 ẹgbẹgbẹ̀rún sq mi) lápapọ̀ mọ́ àwọn erékùṣù tó súnmọ́ ibẹ̀, ilẹ̀ rẹ̀ jẹ́ 6% nínú àpapọ̀ gbogbo ojúde Ayé ati 20.4% gbogbo ile Aye. Pẹ̀lú ẹgbẹgbẹ̀rúnkejì 1 eniyan (ní ọdún 2009, ẹ wo tabili) nínú àwọn agbègbèilẹ̀ 61, èyí ṣàṣirò fún 14.72% gbogbo iye àwọn ènìyànÀgbáyé. Ní àríwá rẹ̀ ni Òkun Mẹditéránì wà, sí àríwáìlàorùn rẹ̀ ni Ìladò Suez àti Òkun Pupa wà nítòsí Sìnáì, sí gúsùìlaòrùn rẹ̀ ni Òkun Índíà, àti sí ìwọ̀ọrùn rẹ̀ ni Òkun Atlántíkì wà. Áfríkà ní àwọn orílẹ̀-èdè 54 lápapò mọ́ Madagáskàr, ọ̀pẹ̀ erékùṣù àti Orílẹ̀-èdè Olómìnira Áràbù Sàhráwì, tó jẹ́ ọmọẹgbẹ́ Ìṣọ̀kan Áfríkà bótilẹ̀jẹ́pẹ́ Mòrókò lòdì sí èyí.

Áfríkà, àgàgà àringbàngàn apáìlàorùn Áfríkà, jẹ́ gbígbàgbọ́ gidigidi ní àwùjọ sáyẹ́nsì bíi orísun àwọn ọmọnìyàn àti ẹ̀ka ẹ̀dá Àwọn Irúọmọnìyàn (Hominidae) (àwọn Òbọ Únlá), gẹ́gẹ́bí ó ṣe hàn pẹ̀lú ìwárí awon irúọmọnìyàn àtètèjùlọ àti àwọn babaúnlá wọn, àti àwọn tí wọ́n wá lẹ́yìn wọn tí wọn jẹ́ bíi ẹgbẹgbẹ̀rún méje ọdún sẹ́yìn – lápapọ̀mọ́ Sahelanthropus tchadensis, Australopithecus africanus, A. afarensis, Homo erectus, H. habilis and H. ergaster – pẹ̀lú Homo sapiens (eniyan odeoni) àtètèjùlọ tó jẹ́ wíwárí ní Ethiopia tó jẹ́ ọdún bíi 200,000 sẹ́yìn.

Áfríkà fẹ̀ kákiri orí agedeméjì, ó sì ní ọ̀pọ̀ àgbègbè ojúọjọ́ ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀; òhun ni orílẹ̀ kan soso tó gùn láti ibi alọ́wọ́rọ́ apáàríwá dé ibi aláwọ́rọ́ apágúsù.

Afri ni orúkọ àwọn ènìyàn tí wọ́n gbé ní Àríwá Áfríkà nítòsí Kártágò. Àwọn wọ̀nyí tanmọ́ "afar" èdè àwọn Finísíà, tó túmòsí "eruku", sùgbọ́n àbárò 1981 kan ti sọ pé ó wá láti ọ̀rọ̀ èdè àwọn Berber ifri tabi Ifran tótúmọ̀sí "iho", láti tókasí àwọn tí úngbé inúihò. Áfríkà tàbí Ifri tàbí Afer ni ọrúkọ Banu Ifran láti Àlgéríà àti Tripolitania (ẹ̀yà Berber ti Yafran).

Lábẹ́ ìjọba àwọn ará Rómù, Kártágò di olúìlú Ìgbèríko Áfríkà, tó tún jẹ́ mímúpọ̀mọ́ apá etíomi Líbyà òní. Àlẹ̀mẹ́yìn "-ka" ("ca") àwọn ará Rómù tókasí "orile-ede tabi ile". Ilẹ̀ọba àwọn Musulumi Ifrikiya tó wá lẹ́yìn rẹ̀, Tùnísíà òdeòní, náà tún lo irú orúkọ yìí.

Áfríkà àṣiwájú aláàmúsìn ṣe é ṣe kí ó ní orílẹ̀ìjọba àti ìṣèjọba ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ tó ju 10,000 lọ, tí wọ́n ní oríṣiríṣi irú àgbájọ olóṣèlú àti ìjọba. Nínú àwọn wọ̀nyí ni àdìpọ̀ abáratan kékeré àwọn aṣọdẹ bíi àwọn San ní apágúsù Áfríkà; àwọn àdìpọ̀ dídìmúlẹ̀ bi awon asọèdè Bantu ní àringbàngàn àti apágúsù Áfríkà, àwọn àdìpọ̀ abáratan dídìmúlẹ̀ gidigidi ní Ibi Ìwo Orí Áfríkà, àwọn ileoba Ṣàhẹ́lì gbàngbà, àti àwọn ìlú-orílẹ̀-èdè aládàáwà àti àwọn ilẹ̀ọba bíi ti àwọn Yorùbá ní Ìwọ̀orùn Áfríkà, àti àwọn ìlú ọjà etíomi àwọn SwahiliIlaorun Afrika. (ìyókù...)Wikipedia:Àyọkà ọṣẹ̀ 5 ọdún 2011

Flag of Bangladesh.svg

Bangladẹ́shì, fun ibise gege bi orile-ede Olominira Araalu ile Bangladesh je orile-ede kan ni Guusu Asia. O ni bode mo India ni gbogbo awon egbe re ayafi fun bode kekere mo Burma (Myanmar) ni guusuilaorun ati mo Ebado Bengal ni guusu. Lapapo mo ipinle West Bengal ni India, o je agbegbe eya-ede Bengal. Oruko Bangladesh tumosi "Orile-ede ile Bengal" ni ede ibise Bengal. Awon bode Bangladesh lowolowo loni je didasile pelu ipinya Bengal ati India ni 1947, nigbati agbegbe na di egbe apailaorun orile-ede tuntun Pakistan. Sugbon, o pinsoto lati egbe apaiworun pelu 1,600 km (994 mi) ile India. Nitori idawaloto oloselu ati ede ati aisi okowo to fa isodi awon araalu si Iwoorun Pakistan, to fa ogun fun ilominira ni 1971 ati idasile orile-ede Bangladesh. Leyin ilominira orile-ede tuntun yi koju iyan, ajalu eda ati aini togbale, ati wahala oselu ati igbajoba ologun. Ipadade oseluaraalu ni 1991 mu itoro ati idagbasoke okowo wa. Bangladesh ni orile-ede keje to lopo eniyan julo ati ikan ninu awon orile-ede to lopo eniyan kikijulo laye pelu osuwon aini giga. Sibesibe, GDP ti enikookan ti di emeji lati 1975, be sini osuwon aini ti re bi 20% lati ibere awon odun 1990. Bangladesh je ikan ninu awon orile-ede ti a npe ni okowo "Next Eleven". Dhaka, oluilu re, ati awon gbongan igboro ilu miran kopa ninu idagbasoke yi. Fun jeografi, orile-ede yi gba ile olora Delta Ganges-Brahmaputra be sini oun ni omoyale lododun ojo monsoon ati iji birikiti. Bangladesh ni ile yepe eti-odo to gunjulo laye ni ti Cox's Bazaar. Oselu re ni oseluaralu ile-asofin. Bangladesh je ikan ninu Ajoni awon Orile-ede, OIC, SAARC, BIMSTEC, ati D-8. Gege bi Banki Agbaye se sakiyesi ninu Oro nisoki Orile-ede re ni July 2005, Bangladesh ti ni ilosiwa gidi ni idagbasoke eniyan ni apa imookomooka, idogba ako/abo ni ile-eko ati iresile ipoju awon eniyan. However, Bangladesh si nkoju awon isoro nla, ajakale iwaibaje awon oloselu ati osise ijoba, economic competition relative to the world, serious overpopulation, widespread poverty, and an increasing danger of hydrologic shocks brought on by ecological vulnerability to climate change. (ìyókù...)Wikipedia:Àyọkà ọṣẹ̀ 7 ọdún 2011

Wikipedia:Àyọkà ọṣẹ̀ 8 ọdún 2011

Wikipedia:Àyọkà ọṣẹ̀ 9 ọdún 2011

Wikipedia:Àyọkà ọṣẹ̀ 10 ọdún 2011

Àwòrán Júpítérì

Júpítérì ni plánẹ̀tì karùún láti ọ̀dọ̀ Òrùn àti plánẹ̀tì tótóbijùlọ nínú Sístẹ̀mù Òrùn. Ó jẹ́ òmìrán ẹ̀fúùfù tó ní ìsúpọ̀ tó fi díẹ̀ dín ju ìkan-nínú-ìdálẹ́gbẹ́rùún ìsúpọ̀ Òrùn lọ sùgbọ́n ìsúpọ̀ lọ́nà méjì àti àbọ̀ ti ìsúpò gbogbo àwọn plánẹ̀tì yìókù nínú Sítẹ̀mù Òrùn lápapọ̀. Júpítérì jẹ́ kìkósọ́tọ̀ bíi òmìrán ẹ̀fúùfù lápapọ̀ mọ́ Sátúrnù, Úránù àti Nẹ́ptúnù. Lápapọ̀, àwọn plánẹ̀tì mẹ́rẹ̀rin yìí jẹ́ pípè nígbà míràn bíi plánẹ̀tì Jofia.

Àwọn atòràwọ̀ ayéijọ́un mọ Júpítérì, bẹ́ ẹ̀ sìni ó jẹ́ gbígbà nínú ẹ̀sìn àti àṣà àwọn ènìyàn ìgbà náà. Àwọn ará Rómù sọ orúkọ rẹ̀ fún òsa Rómù tó únjẹ́ Júpítérì. Láti Ayé, Júpítérì le ní ìhàn ìtóbi −2.94, èyí só di ohun tómọ́lẹ̀jùlọ kẹta ní ojúsànmọ̀ àṣálẹ lẹ́yìn Òsùpá àti Àgùàlà. (Mársì áà le mọ́lẹ̀ bíi Júpítérì fún ìgbà díẹ̀ tó bá wà ní ààyè kan pàtó lórí ojúọ̀nàìyípo rẹ̀.)

Júpítérì jẹ́ ṣíṣàjọsínú pẹ̀lú háídrójìn tí ìkan-nínú-ìdámẹ́rin ìsúpọ̀ sì jẹ́ hélíọ̀m; bákannáà ó tún ṣe é ṣe kó ní inúàrin oníàpáta apilẹ̀sè wíwúwo. Nítorípé ó ún yírapo kíákíá, àwòrán Júpítérì jẹ́ bíi òbìrìkìtì afẹ̀lẹ́ẹ̀gbẹ́ (ó wú díẹ̀ síta ní agedeméjì rẹ̀). Afẹ́fẹ́ojúọ̀run òde rẹ̀ jẹ́ yíyàsọ́tọ̀ sí orísirísi ẹ̀gbẹ́ ní ojúibigbọọrọ ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀, tó ún fa ìjì àti ìṣe rudurudu lẹ́ẹ̀gbẹ́ àwọn bodè tó únkanra wọn. Esi eyi ni Great Red Spot, iji omiran kan to ti je mimo lati orundun 17k nigbati o koko je riri pelu teleskopu. To yika planeti yi ni sistemu oruka planeti ati igberinojuorun alagbara. Be si tun ni o ni awon osupa 63, ninu won ni awon osupa gbangba merin ti won unje awon osupa Galilei ti won koko je wiwari latowo Galileo Galilei ni 1610. Ganymede, eyi totobijulo ninu awon osupa yi ni diamita totobiju planet Mercury lo.

Júpítérì ti je wiwakiri ninu lopolopo igba pelu oko-ofurufu roboti, agaga nigba awon iranlose ifokoja Pioneer ati Voyager ati leyin won pelu Galileo orbiter. Oko iwadi to pese lo si Júpítérì ni oko-ofurufu to unlo si en:Pluto, en:New Horizons ni opin February 2007. Oko iwadi yi lo iwolura lati odo Júpítérì lati fun ni isare pupo. Awon iwakiri ojowaju ninu sistemu Jofia ni wiwa omi ti tinyin bo mole ninu osupa Europa. (ìyókù...)Àwòrán Júpítérì

Júpítérì ni plánẹ̀tì karùún láti ọ̀dọ̀ Òrùn àti plánẹ̀tì tótóbijùlọ nínú Sístẹ̀mù Òrùn. Ó jẹ́ òmìrán ẹ̀fúùfù tó ní ìsúpọ̀ tó fi díẹ̀ dín ju ìkan-nínú-ìdálẹ́gbẹ́rùún ìsúpọ̀ Òrùn lọ sùgbọ́n ìsúpọ̀ lọ́nà méjì àti àbọ̀ ti ìsúpò gbogbo àwọn plánẹ̀tì yìókù nínú Sítẹ̀mù Òrùn lápapọ̀. Júpítérì jẹ́ kìkósọ́tọ̀ bíi òmìrán ẹ̀fúùfù lápapọ̀ mọ́ Sátúrnù, Úránù àti Nẹ́ptúnù. Lápapọ̀, àwọn plánẹ̀tì mẹ́rẹ̀rin yìí jẹ́ pípè nígbà míràn bíi plánẹ̀tì Jofia.

Àwọn atòràwọ̀ ayéijọ́un mọ Júpítérì, bẹ́ ẹ̀ sìni ó jẹ́ gbígbà nínú ẹ̀sìn àti àṣà àwọn ènìyàn ìgbà náà. Àwọn ará Rómù sọ orúkọ rẹ̀ fún òsa Rómù tó únjẹ́ Júpítérì. Láti Ayé, Júpítérì le ní ìhàn ìtóbi −2.94, èyí só di ohun tómọ́lẹ̀jùlọ kẹta ní ojúsànmọ̀ àṣálẹ lẹ́yìn Òsùpá àti Àgùàlà. (Mársì áà le mọ́lẹ̀ bíi Júpítérì fún ìgbà díẹ̀ tó bá wà ní ààyè kan pàtó lórí ojúọ̀nàìyípo rẹ̀.)

Júpítérì jẹ́ ṣíṣàjọsínú pẹ̀lú háídrójìn tí ìkan-nínú-ìdámẹ́rin ìsúpọ̀ sì jẹ́ hélíọ̀m; bákannáà ó tún ṣe é ṣe kó ní inúàrin oníàpáta apilẹ̀sè wíwúwo. Nítorípé ó ún yírapo kíákíá, àwòrán Júpítérì jẹ́ bíi òbìrìkìtì afẹ̀lẹ́ẹ̀gbẹ́ (ó wú díẹ̀ síta ní agedeméjì rẹ̀). Afẹ́fẹ́ojúọ̀run òde rẹ̀ jẹ́ yíyàsọ́tọ̀ sí orísirísi ẹ̀gbẹ́ ní ojúibigbọọrọ ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀, tó ún fa ìjì àti ìṣe rudurudu lẹ́ẹ̀gbẹ́ àwọn bodè tó únkanra wọn. Esi eyi ni Great Red Spot, iji omiran kan to ti je mimo lati orundun 17k nigbati o koko je riri pelu teleskopu. To yika planeti yi ni sistemu oruka planeti ati igberinojuorun alagbara. Be si tun ni o ni awon osupa 63, ninu won ni awon osupa gbangba merin ti won unje awon osupa Galilei ti won koko je wiwari latowo Galileo Galilei ni 1610. Ganymede, eyi totobijulo ninu awon osupa yi ni diamita totobiju planet Mercury lo.

Júpítérì ti je wiwakiri ninu lopolopo igba pelu oko-ofurufu roboti, agaga nigba awon iranlose ifokoja Pioneer ati Voyager ati leyin won pelu Galileo orbiter. Oko iwadi to pese lo si Júpítérì ni oko-ofurufu to unlo si en:Pluto, en:New Horizons ni opin February 2007. Oko iwadi yi lo iwolura lati odo Júpítérì lati fun ni isare pupo. Awon iwakiri ojowaju ninu sistemu Jofia ni wiwa omi ti tinyin bo mole ninu osupa Europa. (ìyókù...)Máápù Áfríkà

Áfríkà ni orílẹ̀ kejì tótóbijùlọ àti tóní àwọn ènìyàn jùlọ láàgbáyé lẹ́yìn Ásíà. Pẹ̀lú ààlà ilẹ̀ tó tó 30.2 ẹgbẹgbẹ̀rún km² (11.7 ẹgbẹgbẹ̀rún sq mi) lápapọ̀ mọ́ àwọn erékùṣù tó súnmọ́ ibẹ̀, ilẹ̀ rẹ̀ jẹ́ 6% nínú àpapọ̀ gbogbo ojúde Ayé ati 20.4% gbogbo ile Aye. Pẹ̀lú ẹgbẹgbẹ̀rúnkejì 1 eniyan (ní ọdún 2009, ẹ wo tabili) nínú àwọn agbègbèilẹ̀ 61, èyí ṣàṣirò fún 14.72% gbogbo iye àwọn ènìyànÀgbáyé. Ní àríwá rẹ̀ ni Òkun Mẹditéránì wà, sí àríwáìlàorùn rẹ̀ ni Ìladò Suez àti Òkun Pupa wà nítòsí Sìnáì, sí gúsùìlaòrùn rẹ̀ ni Òkun Índíà, àti sí ìwọ̀ọrùn rẹ̀ ni Òkun Atlántíkì wà. Áfríkà ní àwọn orílẹ̀-èdè 54 lápapò mọ́ Madagáskàr, ọ̀pẹ̀ erékùṣù àti Orílẹ̀-èdè Olómìnira Áràbù Sàhráwì, tó jẹ́ ọmọẹgbẹ́ Ìṣọ̀kan Áfríkà bótilẹ̀jẹ́pẹ́ Mòrókò lòdì sí èyí.

Áfríkà, àgàgà àringbàngàn apáìlàorùn Áfríkà, jẹ́ gbígbàgbọ́ gidigidi ní àwùjọ sáyẹ́nsì bíi orísun àwọn ọmọnìyàn àti ẹ̀ka ẹ̀dá Àwọn Irúọmọnìyàn (Hominidae) (àwọn Òbọ Únlá), gẹ́gẹ́bí ó ṣe hàn pẹ̀lú ìwárí awon irúọmọnìyàn àtètèjùlọ àti àwọn babaúnlá wọn, àti àwọn tí wọ́n wá lẹ́yìn wọn tí wọn jẹ́ bíi ẹgbẹgbẹ̀rún méje ọdún sẹ́yìn – lápapọ̀mọ́ Sahelanthropus tchadensis, Australopithecus africanus, A. afarensis, Homo erectus, H. habilis and H. ergaster – pẹ̀lú Homo sapiens (eniyan odeoni) àtètèjùlọ tó jẹ́ wíwárí ní Ethiopia tó jẹ́ ọdún bíi 200,000 sẹ́yìn.

Áfríkà fẹ̀ kákiri orí agedeméjì, ó sì ní ọ̀pọ̀ àgbègbè ojúọjọ́ ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀; òhun ni orílẹ̀ kan soso tó gùn láti ibi alọ́wọ́rọ́ apáàríwá dé ibi aláwọ́rọ́ apágúsù.

Afri ni orúkọ àwọn ènìyàn tí wọ́n gbé ní Àríwá Áfríkà nítòsí Kártágò. Àwọn wọ̀nyí tanmọ́ "afar" èdè àwọn Finísíà, tó túmòsí "eruku", sùgbọ́n àbárò 1981 kan ti sọ pé ó wá láti ọ̀rọ̀ èdè àwọn Berber ifri tabi Ifran tótúmọ̀sí "iho", láti tókasí àwọn tí úngbé inúihò. Áfríkà tàbí Ifri tàbí Afer ni ọrúkọ Banu Ifran láti Àlgéríà àti Tripolitania (ẹ̀yà Berber ti Yafran).

Lábẹ́ ìjọba àwọn ará Rómù, Kártágò di olúìlú Ìgbèríko Áfríkà, tó tún jẹ́ mímúpọ̀mọ́ apá etíomi Líbyà òní. Àlẹ̀mẹ́yìn "-ka" ("ca") àwọn ará Rómù tókasí "orile-ede tabi ile". Ilẹ̀ọba àwọn Musulumi Ifrikiya tó wá lẹ́yìn rẹ̀, Tùnísíà òdeòní, náà tún lo irú orúkọ yìí.

Áfríkà àṣiwájú aláàmúsìn ṣe é ṣe kí ó ní orílẹ̀ìjọba àti ìṣèjọba ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ tó ju 10,000 lọ, tí wọ́n ní oríṣiríṣi irú àgbájọ olóṣèlú àti ìjọba. Nínú àwọn wọ̀nyí ni àdìpọ̀ abáratan kékeré àwọn aṣọdẹ bíi àwọn San ní apágúsù Áfríkà; àwọn àdìpọ̀ dídìmúlẹ̀ bi awon asọèdè Bantu ní àringbàngàn àti apágúsù Áfríkà, àwọn àdìpọ̀ abáratan dídìmúlẹ̀ gidigidi ní Ibi Ìwo Orí Áfríkà, àwọn ileoba Ṣàhẹ́lì gbàngbà, àti àwọn ìlú-orílẹ̀-èdè aládàáwà àti àwọn ilẹ̀ọba bíi ti àwọn Yorùbá ní Ìwọ̀orùn Áfríkà, àti àwọn ìlú ọjà etíomi àwọn SwahiliIlaorun Afrika. (ìyókù...)Wikipedia:Àyọkà ọṣẹ̀ 14 ọdún 2011

Wikipedia:Àyọkà ọṣẹ̀ 15 ọdún 2011

Wikipedia:Àyọkà ọṣẹ̀ 16 ọdún 2011

Wikipedia:Àyọkà ọṣẹ̀ 17 ọdún 2011

Wikipedia:Àyọkà ọṣẹ̀ 18 ọdún 2011

Wikipedia:Àyọkà ọṣẹ̀ 19 ọdún 2011

Wikipedia:Àyọkà ọṣẹ̀ 20 ọdún 2011

Wikipedia:Àyọkà ọṣẹ̀ 21 ọdún 2011

Wikipedia:Àyọkà ọṣẹ̀ 22 ọdún 2011

Wikipedia:Àyọkà ọṣẹ̀ 23 ọdún 2011

Àsìá Jamáíkà

Jamáíkà (pípè /dʒəˈmeɪkə/) je orile-ede erekusu ni Antilles Gbangba, to je 234 kilometres (145 miles) ni gigun ati bi 80 kilometres (50 miles) ni fife, ti isodipupo won je 11,100 km2. O budo sinu Okun Karibeani, bi 145 kilometres (90 miles) guusu Kuba, ati 190 kilometres (120 miles) iwoorun Hispaniola, erekusu to je ile fun awon orileabinibi-ileijoba Haiti ati Orile-ede Olominira Dominiki. Awon elede Arawak abinibi eya Taino ti won gbe nibe pe oruko erekusu ohun ni Xaymaca, to tumosi "Ile Igi ati Omi", tabi "Ile Isun Omi".

Nigba kan bi ini Spein ti won si pe ibe ni Santiago, ni 1655 o di ibiamusin Ilegeesi, ati leyin eyi o di ti Britani, toruko re n je "Jamaica". Pelu awon eniyan ti won to egbegberun 2.8, o je orile-ede keta eledegeesi to ni awon eniyan pipojulo ni orile àwon Amerika, leyin awon orile-ede Iparapo awon Ipinle ati Kanada. O wa ninu ile Ajoni pelu Queen Elizabeth II bi Olori Orile-ede. Kingston ni ilu titobijulo ati oluilu re.

Awon eya abinibi Arawak ati Taino ti won gbera lati Guusu Amerika budo sori erekusu na larin odun 4000 ati 1000 kJ. Nigbati Christopher Columbus de be ni 1494 o ba awon abule to ju 200 lo nibe ti won ni awon olori abule nibe. Ebado guusu Jamaika je ibi ti awon eniyan posijulo nigbana, agaga layika agbegbe ti a mo loni bi Old Harbour. Awon Tainos si je onibugbe Jamaika nigbati awon Geesi gba idari ibe. Jamaican National Heritage Trust nsise lati wari, ki won o si sakosile eri yiowu toba le wa nipa awon Taino/Arawak. Christopher Columbus gba Jamaica fun Spein leyin to bale sibe ni 1494. O se e se ko je pe ibi ti Columbus bale si ni Dry Harbour, loni to n je Discovery Bay. Maili kan ni iwoorun St. Ann's Bay ni ibi ibudo akoko awon ara Spein lori erekusu na, Sevilla, ti won pati ni 1554 nitori opo awon olosa ti won ja be. (tẹ̀síwájú...)
Máápù Áfríkà

Áfríkà ni orílẹ̀ kejì tótóbijùlọ àti tóní àwọn ènìyàn jùlọ láàgbáyé lẹ́yìn Ásíà. Pẹ̀lú ààlà ilẹ̀ tó tó 30.2 ẹgbẹgbẹ̀rún km² (11.7 ẹgbẹgbẹ̀rún sq mi) lápapọ̀ mọ́ àwọn erékùṣù tó súnmọ́ ibẹ̀, ilẹ̀ rẹ̀ jẹ́ 6% nínú àpapọ̀ gbogbo ojúde Ayé ati 20.4% gbogbo ile Aye. Pẹ̀lú ẹgbẹgbẹ̀rúnkejì 1 eniyan (ní ọdún 2009, ẹ wo tabili) nínú àwọn agbègbèilẹ̀ 61, èyí ṣàṣirò fún 14.72% gbogbo iye àwọn ènìyànÀgbáyé. Ní àríwá rẹ̀ ni Òkun Mẹditéránì wà, sí àríwáìlàorùn rẹ̀ ni Ìladò Suez àti Òkun Pupa wà nítòsí Sìnáì, sí gúsùìlaòrùn rẹ̀ ni Òkun Índíà, àti sí ìwọ̀ọrùn rẹ̀ ni Òkun Atlántíkì wà. Áfríkà ní àwọn orílẹ̀-èdè 54 lápapò mọ́ Madagáskàr, ọ̀pẹ̀ erékùṣù àti Orílẹ̀-èdè Olómìnira Áràbù Sàhráwì, tó jẹ́ ọmọẹgbẹ́ Ìṣọ̀kan Áfríkà bótilẹ̀jẹ́pẹ́ Mòrókò lòdì sí èyí.

Áfríkà, àgàgà àringbàngàn apáìlàorùn Áfríkà, jẹ́ gbígbàgbọ́ gidigidi ní àwùjọ sáyẹ́nsì bíi orísun àwọn ọmọnìyàn àti ẹ̀ka ẹ̀dá Àwọn Irúọmọnìyàn (Hominidae) (àwọn Òbọ Únlá), gẹ́gẹ́bí ó ṣe hàn pẹ̀lú ìwárí awon irúọmọnìyàn àtètèjùlọ àti àwọn babaúnlá wọn, àti àwọn tí wọ́n wá lẹ́yìn wọn tí wọn jẹ́ bíi ẹgbẹgbẹ̀rún méje ọdún sẹ́yìn – lápapọ̀mọ́ Sahelanthropus tchadensis, Australopithecus africanus, A. afarensis, Homo erectus, H. habilis and H. ergaster – pẹ̀lú Homo sapiens (eniyan odeoni) àtètèjùlọ tó jẹ́ wíwárí ní Ethiopia tó jẹ́ ọdún bíi 200,000 sẹ́yìn.

Áfríkà fẹ̀ kákiri orí agedeméjì, ó sì ní ọ̀pọ̀ àgbègbè ojúọjọ́ ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀; òhun ni orílẹ̀ kan soso tó gùn láti ibi alọ́wọ́rọ́ apáàríwá dé ibi aláwọ́rọ́ apágúsù.

Afri ni orúkọ àwọn ènìyàn tí wọ́n gbé ní Àríwá Áfríkà nítòsí Kártágò. Àwọn wọ̀nyí tanmọ́ "afar" èdè àwọn Finísíà, tó túmòsí "eruku", sùgbọ́n àbárò 1981 kan ti sọ pé ó wá láti ọ̀rọ̀ èdè àwọn Berber ifri tabi Ifran tótúmọ̀sí "iho", láti tókasí àwọn tí úngbé inúihò. Áfríkà tàbí Ifri tàbí Afer ni ọrúkọ Banu Ifran láti Àlgéríà àti Tripolitania (ẹ̀yà Berber ti Yafran).

Lábẹ́ ìjọba àwọn ará Rómù, Kártágò di olúìlú Ìgbèríko Áfríkà, tó tún jẹ́ mímúpọ̀mọ́ apá etíomi Líbyà òní. Àlẹ̀mẹ́yìn "-ka" ("ca") àwọn ará Rómù tókasí "orile-ede tabi ile". Ilẹ̀ọba àwọn Musulumi Ifrikiya tó wá lẹ́yìn rẹ̀, Tùnísíà òdeòní, náà tún lo irú orúkọ yìí.

Áfríkà àṣiwájú aláàmúsìn ṣe é ṣe kí ó ní orílẹ̀ìjọba àti ìṣèjọba ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ tó ju 10,000 lọ, tí wọ́n ní oríṣiríṣi irú àgbájọ olóṣèlú àti ìjọba. Nínú àwọn wọ̀nyí ni àdìpọ̀ abáratan kékeré àwọn aṣọdẹ bíi àwọn San ní apágúsù Áfríkà; àwọn àdìpọ̀ dídìmúlẹ̀ bi awon asọèdè Bantu ní àringbàngàn àti apágúsù Áfríkà, àwọn àdìpọ̀ abáratan dídìmúlẹ̀ gidigidi ní Ibi Ìwo Orí Áfríkà, àwọn ileoba Ṣàhẹ́lì gbàngbà, àti àwọn ìlú-orílẹ̀-èdè aládàáwà àti àwọn ilẹ̀ọba bíi ti àwọn Yorùbá ní Ìwọ̀orùn Áfríkà, àti àwọn ìlú ọjà etíomi àwọn SwahiliIlaorun Afrika. (tẹ̀síwájú...)Wikipedia:Àyọkà ọṣẹ̀ 26 ọdún 2011

Lógò Athens 2004

Àwọn Ìdíje Òlímpíkì Ìgbà Oru 2004, lonibise bi Awon Idije Olimpiadi 28k, je idije pataki akariaye oniere-idaraya pupo to waye ni Athens, Greece lati August 13 de August 29, 2004 pelu motto Welcome Home. Awon elere-idaraya 10,625 ni won kopa nibe, eyi fi 600 ju iye ti won reti lo, awonn wonyi je titele leyin pelu awon osise egbe 5,501 lati orile-ede 201. Idije 301 fun eso waye ninu awon ere-idaraya 28. Athens odun 2004 ni igba akoko lati igba Awon Idije Olimpiki Igba Oru 1996 ti gbogbo awo orile-ede ti won ni Igbimo Olorile-ede Olimpiki kopa. Bakanna o tun je igba akoko lati odun 1896 (leyin Idije 1906 to ti je riresile latigba na) ti awon Idije Olimpiki waye ni Girisi.

Athens je yiyan gegebi ilu agbalejo ninu Ipade 106k IOC to waye ni Lausanne ni September 5, 1997. Athens ti kuna idu re lodun meje seyin ni September 18, 1990 ninu Ipade 96k IOC ni Tokyo lati gbalejo Awon Idije Igba Oru 1996 eyi to sele ni Atlanta. abe idari Gianna Angelopoulos-Daskalaki, Athens mura fun idu miran, nigba yi fun eto lati gbalejo Awon Idije Igba Oru 2004. Iyorisirere ilu Athens lati gba awon Idije 2004 da lori ibebe Athens si itan Olimpiki ati itenu re mo ipa pataki ti orile-ede Girisi ati ilu Athens le ko nipa pipolongo iwa Olimpiki ati Isunkankan Olimpiki. Bakanna, ko ri bi idu won fun awon Idije 1996 to je fifi abuku kan fun ailojutu ati iyaju re - nibi ti idu na ko ni unkankan pato, to kan je pe o gbokan le itara ati ero okan pe eto ilu Athens ni lati gbalejo awon Idije ti ogorun odun; idu fun awon Idije 2004 je yiyin fun inirewesi ati ooto re, iranse re to lojutu, ati ekunrere eto idu re. Idu ti 2004 yanju awon isoro ti ti 1996 ko le yanju - pataki imura ilu Athens, idibaje afefeayika re, isuna re, ati ifoselu se ipalemo awon Idije. Iyorisirere Athens nigba to gbalejo Idije-eye Agbaye Ere Ori Papa 1997 losu kan ki idiboyan ilu agbalejo o to waye na tun se pataki nipa imura re lati gbalejo ere-idaraya akariaye. Eyi to tun fa ti won fi yyan ilu Athens ni itara larin awon omo egbe IOC lati da ogo Olimpiki pada si awon Idije, eyi ni won ro pe o sonu nigba Awon Idije Atlanta 1996 ti won fi abuku kan pe o ti je siseju lokowo. Nitorie, iyan Athens je bi ero pe yio yato si awon Idije 1996.

Leyin to ti lewaju ninu gbogbo awon iyipo idibo, Athens segun Rome laini inira nini ibo 5k to dopin. Cape Town, Stockholm, ati Buenos Aires, awon ilu meta miran ti won bo sinu iwe-kukuru IOC, je lile kuro ninu awon iyipo idibo seyin. Awon ilu mefa miran na tun se itoro, sugbon idu won je fifisile latowo IOC ni 1996. Awon ilu na ni Istanbul, Lille, Rio de Janeiro, San Juan, Seville, ati Saint Petersburg. (tẹ̀síwájú...)Lógò Athens 2004

Àwọn Ìdíje Òlímpíkì Ìgbà Oru 2004, oníbiṣẹ́ bíi Àwọn Ìdíje Òlímpíádì 28k, jẹ́ ìdíje pàtàkì akáríayé oníeré-ìdárayá púpọ̀ tó wáyé ní Athens, Gírìsì láti ọjọ́ 13 Oṣù Kẹjọ de ọjọ́ 29 Oṣù Kẹjọ, 2004 pẹ̀lú motto Welcome Home. Àwọn eléré-ìdárayá 10,625 ni wọ́n kópa níbẹ̀, èyí fi 600 ju iye tí wọ́n retí lọ, àwọn wọ̀nyí jẹ́ títẹlé lẹ́yìn pẹ̀lú àwọn òṣìṣẹ́ bíi 5,501 láti orílẹ̀-èdè 201. Àwọn ìdíje 301 fún ẹ̀ṣọ́ wáyé nínú àwọn eré-ìdárayá 28. Athens ọdún 2004 ni ìgbà àkọ́kọ́ láti ìgbà Àwọn Ìdíje Òlímpíkì Ìgbà Oru 1996 tí gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n ní Ìgbìmọ̀ Òlímpíkì Olórílẹ̀-èdè kópa. Bákannáà ó tún jẹ́ ìgbà àkọ́kọ́ láti ọdún 1896 (lẹ́yìn Ìdíje 1906 tó ti jẹ́ rírẹ̀sílẹ̀ látìgbà náà wá) tí àwọn Ìdíje Òlímpíkì wáyé ní Gírìsì.

Athens je yiyan gegebi ilu agbalejo ninu Ipade 106k IOC to waye ni Lausanne ni September 5, 1997. Athens ti kuna idu re lodun meje seyin ni September 18, 1990 ninu Ipade 96k IOC ni Tokyo lati gbalejo Awon Idije Igba Oru 1996 eyi to sele ni Atlanta. abe idari Gianna Angelopoulos-Daskalaki, Athens mura fun idu miran, nigba yi fun eto lati gbalejo Awon Idije Igba Oru 2004. Iyorisirere ilu Athens lati gba awon Idije 2004 da lori ibebe Athens si itan Olimpiki ati itenu re mo ipa pataki ti orile-ede Girisi ati ilu Athens le ko nipa pipolongo iwa Olimpiki ati Isunkankan Olimpiki. Bakanna, ko ri bi idu won fun awon Idije 1996 to je fifi abuku kan fun ailojutu ati iyaju re - nibi ti idu na ko ni unkankan pato, to kan je pe o gbokan le itara ati ero okan pe eto ilu Athens ni lati gbalejo awon Idije ti ogorun odun; idu fun awon Idije 2004 je yiyin fun inirewesi ati ooto re, iranse re to lojutu, ati ekunrere eto idu re. Idu ti 2004 yanju awon isoro ti ti 1996 ko le yanju - pataki imura ilu Athens, idibaje afefeayika re, isuna re, ati ifoselu se ipalemo awon Idije. Iyorisirere Athens nigba to gbalejo Idije-eye Agbaye Ere Ori Papa 1997 losu kan ki idiboyan ilu agbalejo o to waye na tun se pataki nipa imura re lati gbalejo ere-idaraya akariaye. Eyi to tun fa ti won fi yyan ilu Athens ni itara larin awon omo egbe IOC lati da ogo Olimpiki pada si awon Idije, eyi ni won ro pe o sonu nigba Awon Idije Atlanta 1996 ti won fi abuku kan pe o ti je siseju lokowo. Nitorie, iyan Athens je bi ero pe yio yato si awon Idije 1996.

Leyin to ti lewaju ninu gbogbo awon iyipo idibo, Athens segun Rome laini inira nini ibo 5k to dopin. Cape Town, Stockholm, ati Buenos Aires, awon ilu meta miran ti won bo sinu iwe-kukuru IOC, je lile kuro ninu awon iyipo idibo seyin. Awon ilu mefa miran na tun se itoro, sugbon idu won je fifisile latowo IOC ni 1996. Awon ilu na ni Istanbul, Lille, Rio de Janeiro, San Juan, Seville, ati Saint Petersburg. (tẹ̀síwájú...)Nelson Mandela

Nelson Rolihlahla Mandela (ọjọ́ìbí 18 Oṣù Keje 1918) jẹ́ Ààrẹ Gúúsù Áfríkà lati 1994 di 1999, beesini ohun ni Aare Guusu Afrika akoko to je didiboyan ninu idiboyan toseluarailu eto idibo gbogbo eniyan. Kí ó tó di ààrẹ, Mandela je alakitiyan olodi eto apartaidi, ati olori Umkhonto we Sizwe, to je apa ologun Kongresi Omoorile-ede ara Afrika (ANC). Ni 1962 o je fifofinmu, o si je didalebi iwa ote ati awon esun miran. Nitorie won so si ewon fun igba lailai. Mandela lo odun 27 ni ewon, o lo opo odun yi ni Erekusu Robben. Leyin ijowo re kuro logba ewon ni ojo 11 Osu Keji 1990, Mandela lewaju egbe oloselu re ninu awon iforojomitorooro to fa oseluarailu gbogbo eya waye ni 1994. Gege bi aare lati 1994 de 1999, o sise fun ifowosowopo. Ni Guusu Afrika, Mandela tun je mimo bi Madiba, oye ti awon alagba idile Mandela unlo. Mandela ti gba ebun topo ju 250 lo laarin ogoji odun, ninu won ni Ebun Nobel Alafia 1993.

Nelson Mandela je ara eka kekere iran oba Thembu, to joba ni awon agbegbe Transkei ni Igberiko Cape ti Guusu Afrika. O je bibi ni Mvezo, abule kekere kan to budo si agbegbe Umtata, to je oluilu Transkei. Baba unla-unla baba re Ngubengcuka (to ku ni 1832), joba gege bi Inkosi Enkhulu, tabi ọba awon Thembu. Ikan ninu awon omokunrin oba ohun to nje Mandela, ni baba unla re ati ibi ti oruko idile re ti wa. Sibesibe nitoripe o je omo Inkosi latodo iyawo iran Ixhiba (eyun "idile olowo osi", awon omoomo eka ebi oba re ko le gori ite ni Thembu. Baba Mandela, Gadla Henry Mphakanyiswa, je oloye ni ilu Mvezo. Sugbon nitori aigboran si ijoba alamusin lenu, won yo Mphakanyiswa kuro ni ipo oye re won si ko ebi re lo si Qunu. Sibesibe, Mphakanyiswa ko kose lati je omo egbe Igbimo Onimoran Inkosi, beesini o kopa gidi lat ri pe Jongintaba Dalindyebo gun ori ite Thembu. Lojowaju Dalindyebo san ore yi pada nipa gbigba Mandela sodo bi omo nigbati Mphakanyiswa ku. Baba Mandela fe iyawo merin, pelu won o bi omo metala (okunrin merin ati obinrin mesan). Oruko abiso re Rolihlahla tumosi "fa eka igi", tabi "onijangbon". Rolihlahla Mandela lo je omo akoko ninu ebi re to lo si ile-eko nibi ti oluko re Miss Mdingane ti fun ni oruko Geesi "Nelson". (ìtẹ̀síwájú...)Wikipedia:Àyọkà ọṣẹ̀ 30 ọdún 2011

Nelson Mandela

Nelson Rolihlahla Mandela (ọjọ́ìbí 18 Oṣù Keje 1918) jẹ́ Ààrẹ Gúúsù Áfríkà lati 1994 di 1999, beesini ohun ni Aare Guusu Afrika akoko to je didiboyan ninu idiboyan toseluarailu eto idibo gbogbo eniyan. Kí ó tó di ààrẹ, Mandela je alakitiyan olodi eto apartaidi, ati olori Umkhonto we Sizwe, to je apa ologun Kongresi Omoorile-ede ara Afrika (ANC). Ni 1962 o je fifofinmu, o si je didalebi iwa ote ati awon esun miran. Nitorie won so si ewon fun igba lailai. Mandela lo odun 27 ni ewon, o lo opo odun yi ni Erekusu Robben. Leyin ijowo re kuro logba ewon ni ojo 11 Osu Keji 1990, Mandela lewaju egbe oloselu re ninu awon iforojomitorooro to fa oseluarailu gbogbo eya waye ni 1994. Gege bi aare lati 1994 de 1999, o sise fun ifowosowopo. Ni Guusu Afrika, Mandela tun je mimo bi Madiba, oye ti awon alagba idile Mandela unlo. Mandela ti gba ebun topo ju 250 lo laarin ogoji odun, ninu won ni Ebun Nobel Alafia 1993.

Nelson Mandela je ara eka kekere iran oba Thembu, to joba ni awon agbegbe Transkei ni Igberiko Cape ti Guusu Afrika. O je bibi ni Mvezo, abule kekere kan to budo si agbegbe Umtata, to je oluilu Transkei. Baba unla-unla baba re Ngubengcuka (to ku ni 1832), joba gege bi Inkosi Enkhulu, tabi ọba awon Thembu. Ikan ninu awon omokunrin oba ohun to nje Mandela, ni baba unla re ati ibi ti oruko idile re ti wa. Sibesibe nitoripe o je omo Inkosi latodo iyawo iran Ixhiba (eyun "idile olowo osi", awon omoomo eka ebi oba re ko le gori ite ni Thembu. Baba Mandela, Gadla Henry Mphakanyiswa, je oloye ni ilu Mvezo. Sugbon nitori aigboran si ijoba alamusin lenu, won yo Mphakanyiswa kuro ni ipo oye re won si ko ebi re lo si Qunu. Sibesibe, Mphakanyiswa ko kose lati je omo egbe Igbimo Onimoran Inkosi, beesini o kopa gidi lat ri pe Jongintaba Dalindyebo gun ori ite Thembu. Lojowaju Dalindyebo san ore yi pada nipa gbigba Mandela sodo bi omo nigbati Mphakanyiswa ku. Baba Mandela fe iyawo merin, pelu won o bi omo metala (okunrin merin ati obinrin mesan). Oruko abiso re Rolihlahla tumosi "fa eka igi", tabi "onijangbon". Rolihlahla Mandela lo je omo akoko ninu ebi re to lo si ile-eko nibi ti oluko re Miss Mdingane ti fun ni oruko Geesi "Nelson". (ìtẹ̀síwájú...)Àsìá Jamáíkà

Jamáíkà (pípè /dʒəˈmeɪkə/) je orile-ede erekusu ni Antilles Gbangba, to je 234 kilometres (145 miles) ni gigun ati bi 80 kilometres (50 miles) ni fife, ti isodipupo won je 11,100 km2. O budo sinu Okun Karibeani, bi 145 kilometres (90 miles) guusu Kuba, ati 190 kilometres (120 miles) iwoorun Hispaniola, erekusu to je ile fun awon orileabinibi-ileijoba Haiti ati Orile-ede Olominira Dominiki. Awon elede Arawak abinibi eya Taino ti won gbe nibe pe oruko erekusu ohun ni Xaymaca, to tumosi "Ile Igi ati Omi", tabi "Ile Isun Omi".

Nigba kan bi ini Spein ti won si pe ibe ni Santiago, ni 1655 o di ibiamusin Ilegeesi, ati leyin eyi o di ti Britani, toruko re n je "Jamaica". Pelu awon eniyan ti won to egbegberun 2.8, o je orile-ede keta eledegeesi to ni awon eniyan pipojulo ni orile àwon Amerika, leyin awon orile-ede Iparapo awon Ipinle ati Kanada. O wa ninu ile Ajoni pelu Queen Elizabeth II bi Olori Orile-ede. Kingston ni ilu titobijulo ati oluilu re.

Awon eya abinibi Arawak ati Taino ti won gbera lati Guusu Amerika budo sori erekusu na larin odun 4000 ati 1000 kJ. Nigbati Christopher Columbus de be ni 1494 o ba awon abule to ju 200 lo nibe ti won ni awon olori abule nibe. Ebado guusu Jamaika je ibi ti awon eniyan posijulo nigbana, agaga layika agbegbe ti a mo loni bi Old Harbour. Awon Tainos si je onibugbe Jamaika nigbati awon Geesi gba idari ibe. Jamaican National Heritage Trust nsise lati wari, ki won o si sakosile eri yiowu toba le wa nipa awon Taino/Arawak. Christopher Columbus gba Jamaica fun Spein leyin to bale sibe ni 1494. O se e se ko je pe ibi ti Columbus bale si ni Dry Harbour, loni to n je Discovery Bay. Maili kan ni iwoorun St. Ann's Bay ni ibi ibudo akoko awon ara Spein lori erekusu na, Sevilla, ti won pati ni 1554 nitori opo awon olosa ti won ja be. (tẹ̀síwájú...)
Wikipedia:Àyọkà ọṣẹ̀ 45 ọdún 2011

Àsìá ilẹ̀ Índíà

Índíà, lóníbiṣẹ́ bi orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Índíà (Híndì: भारत गणराज्य Bhārat Gaṇarājya), jẹ́ orílẹ̀-èdè kan ní Gúúsù Ásíà. Òhun ni orílẹ̀-èdè keje tótóbijùlọ gégé bíi ìtóbi ìyaoríilẹ̀, orílẹ̀-èdè kejì tóní alábùgbé jùlọ pẹ̀lú iye bíi ẹgbẹgbẹ̀rúnkejì 1.18 àwọn ènìyàn, àti orílẹ̀-èdè òṣèlúaráàlú alábùgbé jùlọ lágbàáyé. O ja mo Okun India ni guusu, Okun arabu ni iwoorun, ati Ebado Benga ni ilaorun, India ni ile eti odo to je 7,517 kilometres (4,700 mi). O ni bode mo Pakistan ni iwoorun; Saina, Nepal, ati Bhutan si ariwa; ati Bangladesh ati Burma ni ilaorun. India wa nitosi Sri Lanka, ati Maldives ti won wa ni Okun India.

Gege bi ile Asa-Olaju Afonifoji Indus ati agbegbe ojuona owo latayeraye ati awon ile obaluaye, orileabe India je didamo fun ola aje ati asa re kakiri atigba to ti wa. Esin nla merin, Hinduism, Buddhism, Jainism ati Sikhism ni won bere latibe, nigbati Zoroasrianism, Esin Ju, Esin Kristi ati Imale de sibe ni egberundun akoko IO (CE) won si kopa ninu bi orisirisi asa agbegbe na seri. Diedie o je fifamora latowo British East India Company lati ibere orundun ikejidinlogun, o si di ile amusin Ile-oba Isodokan lati arin orundun ikandinlogun, India di orile-ede alominira ni 1947 leyin akitiyan fun isominira to se pataki fun isatako alaise jagidijagan kakiri.

India je orile-ede olominira kan to ni ipinle 28 ati awon agbegbe isokan meje pelu sistemu onileasofin oseluaralu. Okowo India ni okowo ikokanla titobijulo gege bi olorujo GDP lagbaye ati ikerin titobijulo gege bi ibamu agbara iraja. Otun je omo egbe Ajoni awon Orile-ede, G-20, BRIC, SAFTA ati Agbajo Owo Agbaye. India je orile-ede toni ohun-ijagun bombu inuatomu, o si ni ile-ise ologun ikewa ton nawojulo pelu ile-ise ologun adigun keji titobijulo lagbaye. Atunse okowo to bere lati 1991 ti so India di ikan ninu awon okowo to n dagba kiakia julo lagbaye; aimookomooka, iwa-ibaje, arun, ati aijeunkanu. Gege bi awujo esin olopolopo, eledepupo ati eleya eniyan pupo, India tun je ibugbe fun opolopo awon eran-igbe ni opolopo ibi alaabo. (tẹ̀síwájú...)

Wikipedia:Àyọkà ọṣẹ̀ 48 ọdún 2011

Wikipedia:Àyọkà ọṣẹ̀ 49 ọdún 2011

Àsìá Jamáíkà

Jamáíkà (pípè /dʒəˈmeɪkə/) je orile-ede erekusu ni Antilles Gbangba, to je 234 kilometres (145 miles) ni gigun ati bi 80 kilometres (50 miles) ni fife, ti isodipupo won je 11,100 km2. O budo sinu Okun Karibeani, bi 145 kilometres (90 miles) guusu Kuba, ati 190 kilometres (120 miles) iwoorun Hispaniola, erekusu to je ile fun awon orileabinibi-ileijoba Haiti ati Orile-ede Olominira Dominiki. Awon elede Arawak abinibi eya Taino ti won gbe nibe pe oruko erekusu ohun ni Xaymaca, to tumosi "Ile Igi ati Omi", tabi "Ile Isun Omi".

Nigba kan bi ini Spein ti won si pe ibe ni Santiago, ni 1655 o di ibiamusin Ilegeesi, ati leyin eyi o di ti Britani, toruko re n je "Jamaica". Pelu awon eniyan ti won to egbegberun 2.8, o je orile-ede keta eledegeesi to ni awon eniyan pipojulo ni orile àwon Amerika, leyin awon orile-ede Iparapo awon Ipinle ati Kanada. O wa ninu ile Ajoni pelu Queen Elizabeth II bi Olori Orile-ede. Kingston ni ilu titobijulo ati oluilu re.

Awon eya abinibi Arawak ati Taino ti won gbera lati Guusu Amerika budo sori erekusu na larin odun 4000 ati 1000 kJ. Nigbati Christopher Columbus de be ni 1494 o ba awon abule to ju 200 lo nibe ti won ni awon olori abule nibe. Ebado guusu Jamaika je ibi ti awon eniyan posijulo nigbana, agaga layika agbegbe ti a mo loni bi Old Harbour. Awon Tainos si je onibugbe Jamaika nigbati awon Geesi gba idari ibe. Jamaican National Heritage Trust nsise lati wari, ki won o si sakosile eri yiowu toba le wa nipa awon Taino/Arawak. Christopher Columbus gba Jamaica fun Spein leyin to bale sibe ni 1494. O se e se ko je pe ibi ti Columbus bale si ni Dry Harbour, loni to n je Discovery Bay. Maili kan ni iwoorun St. Ann's Bay ni ibi ibudo akoko awon ara Spein lori erekusu na, Sevilla, ti won pati ni 1554 nitori opo awon olosa ti won ja be. (tẹ̀síwájú...)
Àsìá ilẹ̀ Índíà

Índíà, lóníbiṣẹ́ bi Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Índíà (Híndì: भारत गणराज्य Bhārat Gaṇarājya), jẹ́ orílẹ̀-èdè kan ní Gúúsù Ásíà. Òhun ni orílẹ̀-èdè keje tótóbijùlọ gégé bíi ìtóbi ìyaoríilẹ̀, orílẹ̀-èdè kejì tóní alábùgbé jùlọ pẹ̀lú iye bíi ẹgbẹgbẹ̀rúnkejì 1.18 àwọn ènìyàn, àti orílẹ̀-èdè òṣèlúaráàlú alábùgbé jùlọ lágbàáyé. O ja mo Okun India ni guusu, Okun arabu ni iwoorun, ati Ebado Benga ni ilaorun, India ni ile eti odo to je 7,517 kilometres (4,700 mi). O ni bode mo Pakistan ni iwoorun; Saina, Nepal, ati Bhutan si ariwa; ati Bangladesh ati Burma ni ilaorun. India wa nitosi Sri Lanka, ati Maldives ti won wa ni Okun India.

Gege bi ile Asa-Olaju Afonifoji Indus ati agbegbe ojuona owo latayeraye ati awon ile obaluaye, orileabe India je didamo fun ola aje ati asa re kakiri atigba to ti wa. Esin nla merin, Hinduism, Buddhism, Jainism ati Sikhism ni won bere latibe, nigbati Zoroasrianism, Esin Ju, Esin Kristi ati Imale de sibe ni egberundun akoko IO (CE) won si kopa ninu bi orisirisi asa agbegbe na seri. Diedie o je fifamora latowo British East India Company lati ibere orundun ikejidinlogun, o si di ile amusin Ile-oba Isodokan lati arin orundun ikandinlogun, India di orile-ede alominira ni 1947 leyin akitiyan fun isominira to se pataki fun isatako alaise jagidijagan kakiri.

India je orile-ede olominira kan to ni ipinle 28 ati awon agbegbe isokan meje pelu sistemu onileasofin oseluaralu. Okowo India ni okowo ikokanla titobijulo gege bi olorujo GDP lagbaye ati ikerin titobijulo gege bi ibamu agbara iraja. Otun je omo egbe Ajoni awon Orile-ede, G-20, BRIC, SAFTA ati Agbajo Owo Agbaye. India je orile-ede toni ohun-ijagun bombu inuatomu, o si ni ile-ise ologun ikewa ton nawojulo pelu ile-ise ologun adigun keji titobijulo lagbaye. Atunse okowo to bere lati 1991 ti so India di ikan ninu awon okowo to n dagba kiakia julo lagbaye; sibesibe, aini si tun ba ja ati aimookomooka, iwa-ibaje, arun, ati aijeunkanu. Gege bi awujo esin olopolopo, eledepupo ati eleya eniyan pupo, India tun je ibugbe fun opolopo awon eran-igbe ni opolopo ibi alaabo. (tẹ̀síwájú...)
Wikipedia:Àyọkà ọṣẹ̀ 28 ọdún 2020