Wikipedia:Àwùjọ Àwọn tí ó nífẹ sí Nàìjíríà
Èyí ni a ÀwùjọWiki, tí àwọn oǹkọ Wikipedia ti ń jíròrò bí wọ́n ṣe maa mú ìdàgbàsókè bá Àwọn àyọkà tí ó ní ṣe pẹ̀lú Nàijíríà. A kí àwọn oǹkọ̀wé tuntun káàbọ̀; ẹ jọ̀wọ́ ẹ darapọ̀ mọ́wa! |
Ẹkáàbọ̀ sí Àwùjọ Àwọn tí ó nífẹ sí àpilẹ̀kọ nípa ilẹ̀ Nàìjíríà ! Iṣẹ́ àkànṣe yí ni a gbà lérò láti fẹ̀ , ṣàtúntò, túnṣe, kí á sì túbọ̀ kọ nípa àwọn átíkù tó nííṣe pẹ̀lú orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láì fepo-bọyọ̀ rárá. A àgbà wípé iṣẹ́ àkànṣe yí yóò ran àwọn olùkọ́ Wikipedia tó kú lọ́wọ́ láti mọ ibi tí Iṣuẹ́ tún kù sí láti ṣe. Bóyá ẹ nífẹ̀ẹ́ l àti ran wá lọ́wọ́ lórí ohun-kóhun, ẹ jọ̀wọ́ ẹ fi ìbéèrè yín sí ojú ewé Ìbánisọ̀rọ̀ wa.
Àníyàn wa
[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwùjọ yí ni ó rànbwá lọ́wọ́ láti ṣe àmójútó akitiyan bí a ṣe ń mú ìdàgbàsókè, ṣíṣàtúńṣe àti àbójútó àwọn àpilẹ̀kọ tó níṣe pẹ̀lú orílẹ̀-èdè:
- Nàìjíríà
- Àwọn ìtàn ilẹ̀ Nàìjíríà
- Àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.
Àfojúsùn wa
[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àfojúsùn wa pín sí ọ̀nà méj:
- Àfojúsùn gbogbo gbo: èyí ni àfojúsùn nípa kíkọ àwọn átíkù (àpilẹ̀kọ) tí ó níṣe pẹ̀lú orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lápapọ̀.
- Àfojúsùn pàtàkì/gbọ̀ọ́n: èyí ni láti kọ nípa àṣàyàn àpilẹ̀ (átíkù) kan tàbí ọ̀pọ̀. Àwọn àfojúsùn méjèèjì òkè yí ni ẹnikẹ́ni le ṣe àtúnṣe sí nígbà tí a bá ti jíròrò lórí wọn ní pèpéle Ìjíròrò wa.
Àwọn ohun tí a fẹ́
[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Láti ri wípé gbogbo àwọn apilẹ̀kọ tí ó jẹ mọ́ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà wà ní that "àláfíà", sẹpẹ́ àti ní dédé.
- Kí a dẹ́kun tàbí mú àdínkù bá and accurate, minimising ìbaṣẹ́jẹ́ àti la lo àwọn ìkànì tí kò tọ́ bí ó ti wulẹ̀ kí ó mọ. Àwọn ìpènija tí a mẹ́nu bá yí ni ó jẹ́ ohun tí ó wọ́pọ̀ nínú àwọn àpilẹ̀kọ tí ó níṣe pẹ̀lú orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ìdí nìyí tí a fi mu ní ọ̀kúnkúndùn. Lára àwọn àfojúsùn wa náà ni:
- Dídá à wọn átíkù tí ó peregedé tí ó sì fi òtítọ́ ìtàn àti àṣà àwọn ọmọ orílẹ́-èdè Nàìjíríà hànde.
- Fífi ìbásepọ̀ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti àwọn orílẹ̀-èdè míràn nípa àṣà òun ìṣe hàn sí gbogbo àgbáyé.
- Kí á fẹsẹ̀ àwọn àpilẹ̀kọ tí ó rọ̀ mọ́ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà múlẹ̀ ṣinṣin, kí wọ́n sì wà ní ààtò tí ó tọ́.
- Kí á ṣe àfikún gbogbo ìròyìn pàá pàá jùlọ èyí tí ó tọ́ nípa àwọn obìnrin, àwọn aláìní tí wọ́n jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà hànde . Ẹ̀wẹ̀, àwọn ìró yí gbọdọ̀ ní ìtọ́kasí, ó w á kéré tán ìtàkùn ìjásóde tí ó lè fìdí ìròyìn, ìró tàbí ìṣẹ̀lẹ̀ nípa àwọn àpilẹ̀kọ wa gbogbo múlẹ̀.
- Kí á fẹsẹ̀ òfin, ìlànà, àti ìlò èdè abínibí múlẹ̀ nínú ìṣògbufọ̀ àti àpilẹ̀kọ ní gbogbo ọ̀nà. Ní
Àwọn Àfojúsùn pàtàkì
[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Bí ó bá wù wá, a lè dá àfojúsùn pàtàkì yí sílẹ̀ tàbí kí a paárẹ́ ìfilọ̀, èyí lè wáyé látàrí bí àwọn olùkópa bá ṣe ń kópa sí nínú iṣẹ́ àkànṣe náà. Àwọn àfojúsùn ní a ní láti ṣàgbéyẹ̀wò kí á sì ṣàfíkún wọn lẹ́yìn tí a bá jíròrò lórí wọn tan. Ilẹ̀kùn ṣá sílẹ̀ fún ẹnìkẹ́ni láti bá àbá wá kí á sì jọ ṣàgbéyẹ̀wò rẹ̀ órí pèpéle Ìjíròrò wa. Àfojúsùn wa pàtàkì jùlọ ni:
- Nàìjíríà gẹ́gẹ́ bí átíkù; átíkù yí ni púpọ̀ nínú tí wọn kò forúkọ wọn sílẹ̀ tàbí àwọn oníṣẹ́ titun ma ń bàjẹ́ẹ́ lọ́pọ̀ ìgbà nípa fífi ìtàkùn ìjálura tí kò tọ́ sànẹ̀, tàbí kí wọ́n ṣe ìròyìn ẹlẹ́jẹ̀ (tí kìí ṣòótọ́) kún àpilẹ̀kọ yí. Fúndí èyí, a ní láti ma ṣọ́ átíkù yí ní gbogbo ìgbà kí á sì ma ṣàtúnṣe rẹ̀ kí á lè dẹ́kun ìwà ìbàjẹ́ náà. Ọ̀pọ̀ ìkọminú ni àwọn alábàáṣe wa nílẹ̀ òkèrè ti mú wá lórí bí ìbàjẹ́ ṣe ń wáyé lórí átíkù yí, pàá pàá jùlọ nípa ṣíṣe ìyapa ẹnu lórí pàtó iye ènìyàn tí wà ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà nínú ètò ìkàniyàn olori-ò-jorí tí ó ti wáyé nílẹ̀ Nàìjíríà, (bóyá kí á sì dá átíkù sílẹ̀ fún ètò ìkàniyàn lọ́tọ̀?). Kò tan síbẹ̀, Bákan náà ni èyí rí pẹ̀lú àwọn ìlú ńlá ńlá ẹ̀sìn ìbílẹ̀ àwọn ìran ìran ni kò bójú mu tó.
- Ìtàn ilẹ̀ Nàìjíríà; àti àwọn tí awọn èyíbtí a ti sọ tẹ́lẹ̀ pẹ́lú àwọn tí afẹ́ mẹ́nu bà nísàlẹ̀ yí ni wọ́n jẹ́ ohun tí ó ńbtini lójú jọjọ.
- Àpilẹ̀kọ nípa Àtíkù Abubakar; ni ihà tí kálukú oníṣẹ́ Wikipedia kọ sí ìṣèlú pàá pàá jùlọ ọ̀gbẹ́ni náà ti ba àpilẹ̀kọ nípa arákùnrinnnáàbjẹ́ púpọ.
- Àpilẹ̀kọ nípa Lucky Igbinedion; ni kò láàáfíà rárá tí kò sì dàgbà sókè fún ọdún pípaẹ́.
- orúkọ èdè ìran kọ̀ọ̀kan nílẹ̀ Nàìjíríà láti ìkàní Ethnologue sí àwọn átíkù tó jẹ mọ́ abúlé àti ìletò ni kò sí àkórí fún.
Àwọn iṣẹ́ mìíràn tí a tún ní lọ́kàn
[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Bí ó ṣe jẹ́ wípé àwọn àpilẹ̀kọ tí ó jẹ mọ́ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni kò sí nínú àtò, èyí ó lè mú kí rí àtúnṣe. Bí a bá fi wọ́n sínú ààtò tí ó yẹ, ó dájú wípé wọn yóò tètè rí àtúnṣe tí ó tọ́.
- Olè fi Abala:Àkànṣe Wiki Nàìjíríà sí pèpéle ìbánisọ̀rọ̀ nípa àwọn àpilẹ̀kọ/átíkù tó jẹ mọ́ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kí wọ́n lè mọ̀ọ́ bẹ́ẹ̀.
Àwọn átíkù tí a fẹ́ kí ẹ bá wa kọ nìwọ̀nyí
[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Adamu Garba II, IT Entrepreneur and presidential aspirant of the 2019 general elections
- James Green Ugbaja Mbadiwe, business magnate and older brother of K.O. Mbadiwe
- Jídé Ògúnsànyà, Nigerian blogger
- Gozel Green, fashion designer
- Ugo Monye (fashion designer), fashion designer
- Ogugua Okonkwo, fashion designer
- Rudeboy (P-Square), singer & Producer.
- Mr P (P-Square), singer
- 2Shortz, rapper, singer
- Beverly Osu (Wikidata item), actress, model, video vixen, Big Brother Africa 2nd runner-up
- Ikechukwu Nnadi, hyper realist artist
- Adaure Achumba, CNN journalist
- Sean Amadi, MetroFM OAP
- Peruzzi (musician), DMW signed singer, songwriter and performer
- Nnamdi Ekeh, ecommerce entrepreneur, founder yudala.com, CEO Konga.com
- Vera Anenyeonu actress
- Saviour Laba, Software Engineer
- Arthur Unegbe, Nigerian Army's Quartermaster-General at the time of his assassination by January 15,1966 coup plotters
- Ralph Shodeinde, Deputy Commander of the Nigerian Military Training College when he was assassinated by Ìdìtẹ̀gbàjọba ọdún 1966
- Kur Mohammed, Chief of Staff of the Nigerian Army at the time of his assassination by January 15,1966 coup plotters
- Abogo Largema, Commander of the Nigerian Army's 4th Battalion in Ibadan at the time of his assassination by January 15,1966 coup plotters
- James Pam, Nigerian Army's Adjutant-General at the time of his assassination by January 15,1966 coup plotters
- Ministry of Power, Works, and Development
- Ministry Of Information
- Patrick Dele-Cole, Nigerian historian, former Ambassador of Nigeria to Brazil, and former Managing Director of The Daily Times
- Akinloyè Akínyẹmí implicated in a coup plot against the government of Ibrahim Babangida, and younger sibling of Bolaji Akinyemi
- Jones Arogbofa, former National Security Adviser to President Goodluck Jonathan
- Mamuda Yerima
- Mohammed Balarabe Haladu
- Julius Kosebinu Agbaje, first Nigerian Director of Standard Bank (later First Bank)
- Ademuyiwa Adebola Taofeek, Nigerian reporter, columnist
- Fúrá (Wikidata item), A well-known food for Fula and Hausa people
- Maitama Sule University Kano, A University in Kano state, former name North West University Kano.
- Àlìmájìrín, System of Islamic Education practised in Nigeria
- Zanna Bukar Dipcharima, 1st Republic Federal Cabinet Member
- Gambo Sawaba, Northern Elements Progressive Union politician
- Samuel Adémúlégún, Commander of the Nigerian Army's 1st Brigade in Kaduna when he was assassinated by January 15,1966 coup plotters
- Zakariya Maimalari, Commander of the Nigerian Army's 2nd Brigade in Lagos when he was assassinated by January 15,1966 coup plotters
- Conrad Nwawo, Nigerian Civil War veteran
- Federal Ministry of Petroleum Resources (Nigeria)
- Agho Obaseki, Iyase of Benin and political rival of the Oba of Benin
- Chukwudifu Oputa, Nigerian jurist and Head of the Oputa panel
- Ben Akabueze
- Harris Dzarma
- Peter Nwaoduah, Director General of the Nigeria State Security Service (SSS) under Ex Nigeria Head of State
- Fulani extremism
- Hausa Architecture
Àwọn átíkù tí wọ́n fẹ́ àtúnṣe
[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- P-Square
- Nigerian Military Training College
- Late General Sani Abacha
- Ibrahim Babangida
- Bolaji Akinyemi
Àwọn olùkópa
[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn Oníṣẹ́ àtìgbà-dégbà
[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Láti kópa nínú àwọn iṣẹ́ àkànṣe Wiki Nàìjíríà yí, ẹ ṣe àtúnkọ ojú ewé yí kí ẹ sì ṣàfikún wọ̀nyí: Wikitext #{{subst:me}}
. Ẹ ṣe àkọsílẹ̀ abala tí ó wù yín láti máa kópa lábẹ́ àtòjọ orúkọ àwọn Oníṣẹ́. Àwọn olùkópa tún ní láti fi Orúkọ ìdánimọ̀ Oníṣẹ́ wọn síbẹ̀. page. Ẹ lè wo àpẹẹrẹ ìtàkùn yí clicking here kí ẹ lè fi sí abẹ́ ìṣọ́ yín.
Àmì ìdánimọ̀ àwọn Olùkópa
[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn olùkópa nínú iṣẹ́ àkànṣe Wiki Nàìjíríà ní láti ṣe àfikún àwọn Ìlà yí Wikitext sí ojú ewé wọ. Láti ṣe èyí, ẹ lo ìlànà yí user page Àdàkọ:Nobreak. Àdàkọ:Yytop Àdàkọ:Yycat Àdàkọ:Yy Àdàkọ:Yy Àdàkọ:Yy Àdàkọ:Yyend For other Nigeria user templates, see Àdàkọ:Nobreak.
- BLPs
- Àwọn orin
- Àwọn mìíràn ni
- Jaja ti Ìlú Òpóbo
- Bayajidda
- Iya Abubakar
- Area Boys
- Margaret Ekpo
- Evan Enwerem
- Arrow of God
- Alhassan Dantata
- Bolaji Akinyemi
- Ilẹ̀ Ọba Nri
- Ìyábọ̀ Ọbásanjọ́-Bello
- Usman Nagogo
- John Ezzidio
- Ìwa-kùsà ní orílẹ̀-ẹ̀dè Nàìjíríà àti Àjọ tí ó ńnrí ìwa-kùsà kóòlù nílẹ̀ Nàìjíríà
- Arthur's Day
- Stephanie Okereke
- Half of a Yellow Sun
- Femi Robinson
- Fredrick Obateru Akinruntan
- Ìlà kíkọ ní ilẹ̀ Yorùbá
- Ọdún Ìgògò
- Ìwòyè-Kétu
- National Association of Seadogs
- Mahmood Yakubu
- Zuriel Oduwole
- Isaac Folorunso Adewole
- Josiah Ransome-Kuti
- Felicity Okpete Ovai
- Priscilla Nzimiro
- Remi Sonaiya
- Humblesmith
- Harcourt Whyte
- Greater Port Harcourt
- Season of Crimson Blossoms
Àwọn ohun èlò
[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ìgbéléwọ̀n
[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn Gbàgede
[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Gbàgede àwọn Átíkù gbogbo gbò:
- {{Àwọn Olórí ilẹ̀ Nàìjíríà}}
- {{Àwọn amúgbá-lẹ́gbẹ́ Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà}}
- {{Ààrẹ Ilé Aṣòfin àgbà ilẹ̀ Nàìjíríà}}
- {{Agbẹnusọ Ilé Ìgbìmọ̀ àṣòfin}}
- {{Àwọn Gómìnà tó wà nípa lọ́wọ́}}
- {{Àwọn ìpínlẹ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà}}
- {{Ilé ẹjọ́ gíga-jùlọ ti ilẹ̀ Nàìjíríà}}
- {{Máápù àwọn ìpínlẹ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà}}
Fún àwọn átíkù tí wọ́n dá wà (stub)s, nínú àwọn àpilẹ̀kọ tí a ti mẹ́nu bà tí wọ́n sì nílò kí a fẹ̀ wọ́n lójú síwájú si, ẹ fi ọ̀kan nínú àwọn ìtàkùn yí sí irúfẹ́ átíkù bẹ́ẹ̀ lábẹ́.
- {{Nigeria-stub}}
- {{Nigeria-bio-stub}}
- {{Nigeria-ethno-group-stub}}
- {{Nigeria-footyclub-stub}}
- {{Nigeria-geo-stub}}
- {{Nigeria-hist-stub}}
- {{Nigeria-party-stub}}
Ẹ lè lo ìlànà ìbánisọ̀rọ̀ fún ojú-ewé àwọn átíkù *{{Iṣẹ́ àkànṣe Wikipedia Yorùbá}}
Bí ẹ bá fẹ́ bá àwọn oníṣẹ́ tí wọ́n nífẹ̀ẹ́ sí iṣẹ́ àkànṣe Wikipedia Yiruba, ẹ kàn sí wọn lórí: {{Oníṣẹ́ Iṣẹ́ Àkànṣe Wikipedia Yorùbá}}, ìyẹn tí ẹ bá jẹ́ ọ̀kan lára wọn. Àmọ́ tí ẹ bá jẹ́bọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ẹ lè lo ìtàkùn yí láti fi kan sí wọn
- {{User Nigeria}}.
Àwọn Ìpínsísọ̀rí
[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Ìsọ̀rí ilẹ̀ Nàìjíríà àti àwọn abala mìíràn tí wọn kò to ni a tí lè rí àwọn ìpín sirọ̀rí Portal:Nigeria/Ìsọ̀rí. Tí ohun tí o ń wà kò bá sí ní abẹ́ ìpínsísọ̀rí yí, ẹ lè dá ìsọ̀tí mìíràn kalẹ̀ fun tàbí kí ẹ tún wo Ìsọ̀rí ilẹ̀ Afíríkà.
Àwọn ojú-èwe mìíràn
[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Átíkù ìfitónilétí
[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àdàkọ:Àwọn tábìlì Átíkù ìfitónilétí
Átíkù tó ń hooru
[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn ojú-ewé tí ó gbajúmọ̀
[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ojú-ewé tí ṣí kà jùlọ ní a lè rí ní orí ìtàkùn yí Wikipedia:WikiProject Nigeria/Ojú-ewé tó gbajúmọ̀ (tí a ń ṣe kòkárí rẹ̀ lóṣooṣù).
Àwọn iṣẹ́ àkànṣe ti Wikipedia tó kù
[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Commons and Wikinews[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
|
Wikipedias in Nigerian languages[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
|
Ààtò àwọn olùṣàtúnṣe
[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Oníṣe:WolterBot/ ìdarapọ̀ mọ́ àwọn olùṣàtúnṣe
Àwọn ojú-ewé tó farajọra
[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àdàkọ:Africa-related WikiProjects
Tools
[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ẹ wo: Wikipedia:Irinṣẹ́
Àdàkọ:Help navigation Àdàkọ:Wikipedia policies and guidelines Àdàkọ:WikiProject Footer