Oníṣe:Demmy/Sandbox/page

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Ẹ kú àbọ̀ si Wikipedia

Wikipedia je ibi ti a ti le ri orisirisi ayoka ka nipa opolopo imo ni ede yoruba.

Iye awon ayoka ti o wa lowolowo bayi je 31,947

Biology - Physiki - Kemistry - Geography - Mathematiki - Ọnà


Àyọkà Ọ̀sẹ̀ Yí
Nnaji.jpg

Genevieve Nnaji (pípè /n'nɑːdʒɪ/, ọjọ́ìbí May 3, 1979 ní Mbaise, Ipinle Imo, Nigeria), jẹ́ òṣèré filmu ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà. Ní 2005 ó gba Ẹ̀bùn Akadẹ́mì Filmu ilẹ̀ Áfríkà gẹ́gẹ́ bíi Òṣèré Obìnrin Tódárajùlọ.Ìlú Èkó ni Genevieve Nnaji ti dàgbà.

Ìkẹrin nínú àwọn ọmọ méjọ, ọ̀mọ̀wé ni àwọn òbí rẹ̀. Bàbá rẹ̀ siṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi onímọ̀ iṣẹ́-ẹ̀rọ (engineer) nígbàtí ìyá rẹ̀ sì jẹ́ olùkọ́. Ò lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Methodist Girls College ní Yaba, lẹ́yìn rẹ̀ ó tẹrísí Yunifásítì ìlú Èkó. Níbẹ̀ lówà tó ti bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣiṣẹ́ díèdíẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi òṣèré ni Nollywood. (Ekunrere...)

Wikipedia

Àdàkọ:POTD/2019-10-19


  1. ddf

President of Austria