Jump to content

Angelina Jolie

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Angelina Jolie
Jolie ní ọdún 2014
Ọjọ́ìbíAngelina Jolie Voight
4 Oṣù Kẹfà 1975 (1975-06-04) (ọmọ ọdún 49)
Los Angeles, California, U.S.
Orúkọ mírànAngelina Jolie Pitt
Ọmọ orílẹ̀-èdè
  • United States
  • Cambodia
Iṣẹ́òsèbínrìn[1]
oludari fíímù[2]
Ìgbà iṣẹ́1982–present
Works Awọn Akojọ
Olólùfẹ́
Àwọn ọmọ6
Parent(s)Marcheline Bertrand
Jon Voight
Àwọn olùbátan
  • James Haven
  • Barry Voight
  • Chip Taylor
AwardsAwọn Akojọ

Angelina Jolie[3] ( /ˈl/; tí orúkọ àbìsọ rẹ̀ ń jẹ́ Angelina Jolie Voight[4] ní kíkún, wọ́n bi ní ọjọ́ kẹrìn, Oṣù Kẹfà ọdún 1975). Ó jẹ́ òṣerébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà. Bákan náà ni ó tún jẹ́ olótùú eré àti ẹlẹ́yinjú àánú. Ó ti gba àmì ẹ̀yẹ oríṣiríṣi bí Ebun Akademi àti Golden Globe Awards mẹ́ta léra wọn. Òun ni wọ́n kà sí òṣèrébìnrin tí owó rẹ̀ wọ́n jù ní Hollywood.

Jolie kọ́kọ́ farahàn lórí tẹlifíṣàn gẹ́gẹ́ bí òṣerémọdé pẹ̀lú bàbá rẹ̀ Jon Voightínú kópa nínú eré

rẹ̀ nípa ti wọ́n kópa

Lookin' to Get Out (1982Ó, Ó sì bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ eré ṣíṣe ní pẹrẹu pẹ̀lú ṣíṣe àwọn fíìmù alábọ́dé bi Cyborg 2 (1993), ti o si bere si n fara han ninu awon ere olokan-o-jokan leyin igba naa bi, Hackers (1995). O si tun kopa ninu ere ayelujara bi George Wallace (1997) ati Gia (1998). O si gba ani-eye Ebun Akademi fun osere amugbalegbe to dara julo fun ipa re ti o ko ninu onise Girl, Interrupted ti odun 1999.

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Colon, Beatriz (August 24, 2022). "Angelina Jolie's latest outing with rarely seen daughter Vivienne amid lawsuit revelation - details". HELLO!. Retrieved August 26, 2022. 
  2. "Angelina Jolie: I had my ovaries removed, preventively". CBS News. March 24, 2015. Retrieved August 26, 2022. 
  3. Respers France, Lisa (April 16, 2019). "Angelina Jolie and Brad Pitt are legally single". CNN. Archived from the original on May 24, 2021. Retrieved February 8, 2022.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. "Angelina Jolie". Biography. 2018-03-27. Retrieved 2022-08-22.