Jump to content

Penélope Cruz

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Penélope Cruz
Penélope Cruz
Cruz at the 32nd Goya Awards
Ọjọ́ìbíPenélope Cruz Sánchez
28 Oṣù Kẹrin 1974 (1974-04-28) (ọmọ ọdún 50)
Alcobendas, Spain
Iṣẹ́
  • Actress
Ìgbà iṣẹ́1989–present
WorksPenélope Cruz filmography
Olólùfẹ́
Javier Bardem (m. 2010)
Àwọn ọmọ2
Àwọn olùbátanMónica Cruz (sister)
AwardsList of awards and nominations received by Penélope Cruz

Penélope Cruz jẹ óṣere lobinrin ilẹ spanish ti a bini ọjọ 28 óṣu April ni ọdun 1974. Óṣere lobinrin naa gba Ebun Akademi bi Obinrin Osere Keji Didarajulo[1].

Igbèsi Àyè Àràbinrin naa[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Cruz ni a bi si Alcobendas, Spain fun Encarna Sàchez (Ẹni tin ṣè irun) ati Eduardo Cruz (Olutaja ati Mechanic)[1]. Óṣere lobinrin naa dagba gẹgẹ̀bi Roman Catholic[2]. Cruz gba jumọ ijó, ó si kọ ballet fun ọdun mẹsan ni National Conservatory ti Spain.

Óṣere lóbinrin naa kẹkọ nipa ballet ilẹ spain fun ọdun meta ati theatre ni ilè iwè Cristina Rota fun ọdun mẹrin[3][4][5]. Lati kèkèrè, Cruz fẹran acting nigba ti ó ri èrè agbèlèwó "Tie Me Up! Tie Me Down! ni ọdun 1990[6]. Ni ọdun 2015, Baba Cruz ku ni ilè rẹ ni spain ni ọmọ ọdun mẹji lèèlagọta lóri aisan ọkan.

Ni óṣu july, ọdun 2010, Cruz fẹ óṣere lọkunrin ilẹ spanish Javier Bardem ti wọn si ọmọ ọkunrin Leo Encinas Cruz ni ọdun 2011 si Los Angeles ati ọmọ óbinrin Luna Encinas Cruz ni ọ̀dun 2013 si Madrid[2][7][8].

Ami Ẹyẹ ati Idanilọla[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Penèlope jẹ óṣèrè lobinrin ilẹ spanish kan ṣoṣó to ma kọkọ gba àmi ẹyẹ Akademi. Akademi ti motion picture Arts ati sciences fun Cruz ni Ami Ẹyẹ Akademi. Penèlope gba Ami Ẹyẹ Akademi Nomination Meji ti British lori èrè àgbèlèwo,Ami Ẹyẹ Nomination ti Golden Globe, Ami Ẹyẹ Nomination ti Emmy Primetime, Ami Ẹyẹ Nomination Maarun ti Óṣere Screen Guild ati Ami Ẹyẹ Nomination ti Goya[9][10].

Ni ọdun 2006, Cruz gba Ami Ẹyẹ gẹgẹbi Óṣere lobinrin to dara julọ ni Festival Cannes lori èrè agbèlèwó. Óṣèrè lobinrin naa gba Àmi Ẹyẹ BAFTA gẹgẹ̀bi óṣere lobinrin to dara julọ lori ipa rẹ ninu iranlọwọ[11].

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]