Eva Marie Saint
Àdàkọ:Use American English Àdàkọ:Use mdy dates
Eva Marie Saint | |
---|---|
Saint c. 1951 | |
Ọjọ́ìbí | 4 Oṣù Keje 1924 Newark, New Jersey, U.S. |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Bowling Green State University |
Iṣẹ́ | Actress |
Ìgbà iṣẹ́ | 1946–2014, 2018 |
Olólùfẹ́ | |
Àwọn ọmọ | 2 |
Eva Marie Saint (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ Kẹ́rin Oṣù Kẹfà, Ọdún1924 ) jẹ́ Òṣèrè fíìmù Amẹ́ríkà, Tíátà àti Tẹlẹfísọ̀n. Ní fún ìgbà tó ju Ọgọ́jẹ Ọdún lọ, ó gba Àwọ́ọ̀dù Akadẹ́mì àti Primetime Emmy Award, pẹ̀lú yíyàn fún Golden Globe Award àti British Academy Film Awards lẹ́ẹ̀mejì. Lẹ́yìn ikú Olivia de Havilland ní ọdún 2020, Saint di Òṣèrè tó dàgbà jù tó ti gba Àwọ́ọ̀dù Akadẹ́mì àti Òṣèrè tó ṣekú láyé lára àwọn Òṣèrè tó gbajúmọ̀ nínu sinimá Golden Age of Hollywood.
Wọ́n bí sí New Jersey, ó dàgbà sí New York, Saint lọ sí Bowling Green State University àti wí pé ó bẹ̀rẹ̀ ìrìnàjò ayé rẹ̀ pẹ̀lú Òṣèré Tẹlẹfísọ̀n àti Rédíò ní 1940s. Lára àwọn iṣẹ́ àkọ́kọ́ tó ṣe tó gbajúmọ̀ ní: ipa tó kó gẹ́gẹ́ bí Thelma ní Hoorton Foote's The Trip to Bountiful (1953).
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ Ayé rẹ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Saint ní Ọjọ́ Kẹ́rin oṣù Kéje, ọdún 1924,[1] ní Newark, New Jersey, sí ẹbí Quaker.[2] Ó lọ sí Bethlehem Central High School ní Delmar, New York, lẹ́gbẹ̀ẹ́ Albany, Ó ṣe tán ní ọdún 1942. Ó di ara hall of fame ilé-ìwé sẹ́kọ́ndírí ní ọdún 2006. Ó kọ́ ìmọ̀ Òṣèré ṣiṣẹ́ ní Bowling Green State University àti darapọ̀ mọ́ Delta Gamma Sorority. Ní àsìkò yìí, ó ṣe olórí Òṣèré ní Personal Appearance.[3] Tíátà tó ṣe ní ọgbà Bowling Green tọ́ padà sọ lẹ́yìn rẹ̀.[4] Ó jẹ́ lára àwọn ẹgbẹ́ Tíátà ọlọ́lá tó kọ ara wọn jọ bíi ọmọ-ìyá,
Theta Alpha Phi,[5]àti wí pé òun ní ó ń tọ́jú rẹ́kọ̀dù fún àwọn àjọ ọmọ-ilé ìwé ní ọdún 19.. 4
Àwọn fíìmù ẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Hollywood Star Walk". LA Times. Retrieved April 22, 2022.
- ↑ Shindler, Merrill (1990-05-13). "Eva Marie Saint Finds TV Full of Contradictions". Chicago Tribune (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-28.
- ↑ "The Key 1944". BGSU Key Yearbooks. 1 January 1944. Retrieved 24 July 2020.
- ↑ "Eva Marie Saint receives Lifetime Achievement Award from alma mater". Bowling Green State University (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-29.
- ↑ "Bee Gee News May 30, 1945". BG News (Student Newspaper). 30 May 1945. Retrieved 24 July 2020.