Miyoshi Umeki

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Miyoshi Umeki
Umeki in a publicity photo for Sayonara (1957)
Ọjọ́ìbíUmeki Miyoshi (梅木 美代志?)
(1929-05-08)Oṣù Kàrún 8, 1929
Otaru, Hokkaido, Empire of Japan
AláìsíAugust 28, 2007(2007-08-28) (ọmọ ọdún 78)
Licking, Missouri
Ọmọ orílẹ̀-èdèAmerican
Iṣẹ́Singer, actress
Ìgbà iṣẹ́1953–1972
Olólùfẹ́
Wynn Opie
(m. 1958; div. 1967)

Randall Hood
(m. 1968; died 1976)
Àwọn ọmọ1
AwardsAcademy Award for Best Supporting Actress

Miyoshi Umeki ti a bini ọjọ kẹjọ, óṣu May ni ọdun 1929 je óṣèrè lóbinrin to gba Ebun Akademi bi Obinrin Osere Keji Didarajulo[1][2].

Igbesi Àyè Óbinrin naa[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Miyoshi ni a bini Otaru, Hokkaido. Óṣèrè lobinrin naa jẹ ẹnì to kèrè ju larin awọn ọmọ mẹsan ti Baba rẹ bi (Oludasilẹ ilè iṣẹ to dalori irin)[3].

Lẹyin Ogun Àgbayè keji ni Umeki bẹrẹ irin ajó iṣẹ rẹ gẹgẹbi ólórin club alẹ ni japan nibi o tiló órukọ Nancy Umeki[4][5]. Igbèyawó akọkọ ni óṣèrè lobinrin naa ṣẹ pẹlu Oludari ẹrọ àgbèlèwo Frederick Winfield waye ni ọdun 1958 ti wọn si pinya ni ọdun 1967. Tọkọ Taya naa bi ọmọ ọkunrin kan Michael H. Opie ni ọdun 1964. Miyoshi fẹ ọkọ keji Randall Hood ni ọdun 1968 ti ọkọ naa ku ni 1976[6].

Miyoshi ku ni ọjọ kejidinlọgbọn, óṣu August ni ọdun 2007 ni ọmọ ọdun mèji din lọgọrin lori aisan jẹjẹrẹ[7]. Ọmọ ọkunrin óṣèrè lobinrin naa ti ójẹ ọlọpa ni Licking ku ni ọjọ kẹtadinlọgbọn óṣu August ọdun 2018[8].

Ami Ẹyẹ ati Idanilọla[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ọdun Àmi Ẹyẹ̀ Category Film Èsi
1958 Academy Awards Best Supporting Actress Sayonara Gbàá
1958 Golden Globe Awards Best Supporting Actress – Motion Picture Wọ́n pèé
1962 Best Actress in a Motion Picture – Musical or Comedy Flower Drum Song Wọ́n pèé
1970 Best Supporting Actress – Television The Courtship of Eddie's Father Wọ́n pèé
1959 Tony Award Best Performance by a Leading Actress in a Musical Flower Drum Song Wọ́n pèé

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]