Celeste Holm
Celeste Holm jẹ óṣèrè lóbinrin ti ere oritage, filmu ti ilẹ america ti a bini óṣu April, ọdun 1917 to si ku ni óṣu july, ọdun 2012[1].
Igbèsi Àyè Àrabinrin naa
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Celeste ni a bisi ilú Manhattan to si jẹ ọmọ ẹyọkan ṣoṣo ti Iya rẹ Jean Parke (Ólúkọwè) ati Baba rẹ Theodor Holm (Óniṣowo) bi[2].
Igbèyawọ Holm akọkọ waye ni ọdun 1936 pẹlu Ralph Nelson ti wọn si bi ọmọ ọkunrin kan;Ted Nelson[3].
Ni óṣu January ọdun 1940, Celeste fẹ̀ Francis Emerson Harding Davies (Ọmọ ijọ Roman Catholic) ti wọn si pinya ni ọdun 1945[4][5].
Lati ọdun 1946 si ọdun 1952, Holm fẹ A. Schuyler Dunning to si ọmọ ọkunrin kan fun; Daniel Dunning (Óniṣowó)[6].
Ni ọdun 1961, Holm fẹ óṣèrè lọkunrin Wesley Addy. Ọkọ naa ku ni ọdun 1996[7].
Ni óṣu April ọdun 2004, Holm fẹ ólórin ti Opera Frank Basile[8].
Ni ọdun 2002, óṣèrè lóbinrin wó óriṣiriṣi aisan bi Jẹjẹrẹ, Ulcer ati bẹbẹlọ[9][10].
Ni ọdun 2012, óṣèrè lóbinrin naa ni aisan ọkan to si yọri si iku rẹ ni ọjọ kẹta ni ilè rẹ ni Central Park West[11][12][13].
Ẹkọ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Celeste ti lọsi ilè iwè ni ilú Netherlands, France ati United States. Óṣèrè lóbinrin lọsi ilè iwe ti High lẹyin naa ló lọ si Francis W. Parker ni ọdun 1935. Celeste lọ si ilè iwè giga ti Chicago lati kọ drama[14].
Ami Ẹyẹ ati Idanilọla
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Celeste gba Ami Ẹyẹ ti Golden Globe, Daytime Emmy, Primetime Emmy ati Ebun Akademi bi Obinrin Osere Keji Didarajulo[15][16].
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ https://www.nytimes.com/2012/07/16/theater/celeste-holm-witty-character-actress-dies-at-95.html#:~:text=Celeste%20Holm%20was%20born%20in,King%20Olav%20V%20of%20Norway.)
- ↑ http://www.filmreference.com/film/4/Celeste-Holm.html
- ↑ https://www.thefamouspeople.com/profiles/celeste-holm-39702.php
- ↑ https://www.famoushookups.com/site/relationship_detail.php?name=Francis-Emerson-Harding-Davie&relid=24670&celebid=26426
- ↑ https://www.myheritage.com/research/record-10182-803506/francis-e-davies-in-biographical-summaries-of-notable-people
- ↑ https://web.archive.org/web/20090312035138/http://www.time.com/time/magazine/article/0,9171,806408,00.html
- ↑ https://web.archive.org/web/20090312035138/http://www.time.com/time/magazine/article/0,9171,806408,00.html
- ↑ https://www.nytimes.com/2011/07/03/nyregion/love-and-inheritance-celeste-holms-family-feud.html
- ↑ https://timenote.info/en/Celeste-Holm
- ↑ http://www.hollywoodsgoldenage.com/actors/celeste_holm.html
- ↑ https://www.nytimes.com/2012/07/16/theater/celeste-holm-witty-character-actress-dies-at-95.html
- ↑ https://web.archive.org/web/20120717053656/http://todayentertainment.today.msnbc.msn.com/_news/2012/07/15/12752807-oscar-winning-actress-celeste-holm-dies-at-95?lite
- ↑ https://web.archive.org/web/20200727183300/https://www.theoaklandpress.com/news/fire-at-de-niro-s-new-york-apartment-no-injuries/article_25f2c2e7-bdbd-551a-87e4-d56a7ed9e0c6.html
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2022-11-21. Retrieved 2022-11-21.
- ↑ https://m.imdb.com/name/nm0002141/awards
- ↑ https://www.emmys.com/bios/celeste-holm