Jump to content

Mo'Nique

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Mo'Nique
An African American female with dark brown hair that reaches her shoulders. She is wearing a short sleeved light pink dress and a ring on her left hand. She is holding a greenish-blue statue that has a bronze plank with her right hand. In the background, there is an orange wall with logos and writing, such as the words "tbs" and "TNT" (which has a circle around it).
Mo'Nique at the 2010 16th Screen Actors Guild Awards
Ọjọ́ìbíMonica Imes
11 Oṣù Kejìlá 1967 (1967-12-11) (ọmọ ọdún 57)
Woodlawn, Baltimore County, Maryland
Orúkọ mírànMo
Iṣẹ́Actress
Comedienne
Talk show host
Author
Ìgbà iṣẹ́1999–present
Olólùfẹ́Mark Jackson (m. 1997–2001)
Sidney Hicks (m. 2006–present)
Websitemoniqueworldwide.com

Monica Imes (ojoibi December 11, 1967), to gbajumo bi Mo'Nique, je àlawada ati óṣere lóbinrin ara Amerika to gba Ebun Akademi bi Obinrin Osere Keji Didarajulo[1][2].

Igbèsi Àyè Arabinrin naa

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Mo'Nique ni a bini Woodlawn, Baltimore County ni Maryland. Óṣere lobinrin naa jẹ ọmọ Alice Imes (Engineer) ati Steven Imes (Ólúbadamọran ti ogun)[3].

Ki Mo'Nique to di Óṣère lóbinrin ni ó ṣiṣẹ gẹgẹbi Customer Service Representative ni Ilè iṣẹ ẹrọ imulèwọ MCI ni Hunt Valley, Maryland. Mo'Nique fẹ accountant Kenny Mung fun igbà rànpẹ. Óṣèrè lobinrin naa fẹ Mark Jackson ni ọdun 1991 di 2001 ti wọn si bi ọmọ ọkunrin meji; Mark Eric Jackson Jr. ati Shalon Calvin Jackson. Mo'Nique bi Ibeji ọkunrin meji Jonathan ati David Hicks ni óṣu October ọdun 2005 fun Sidney Hicks ti wọn si fẹ ara wọn ni ọdun 2006[4].

Mo'Nique jade ni Milford Mill High School ni ilu Baltimore County ni ọdun 1985 ati Ilè iwè giga ti Morgan. Óṣere lóbinrin naa jẹ ẹni to kawe ja ni ọdun 1987 ni Institute Iróyin ti Maryland[5].

Ipa Óṣere lobinrin ninu Èrè Àgbèlèwó

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Ọdun Akọlè Ipa Óṣèrè lobinrin ninu èrè àgbèlèwó Akiyesi
2000 3 Strikes Dahlia
2001 The Queens of Comedy Herself
Baby Boy Patrice
Two Can Play That Game Diedre
2002 Half Past Dead Twitch's Girl
2004 Soul Plane Jamiqua
Hair Show Peaches
Garfield: The Movie Rat Role deleted in final cut of the film
2005 Shadowboxer Precious
Domino Lateesha Rodriquez
2006 Farce of the Penguins Vicky Voice
Irish Jam Psycho
Phat Girlz Jazmin Biltmore
Beerfest Cherry
2008 Welcome Home, Roscoe Jenkins Betty
2009 Stepping: The Movie Aunt Carla
Precious Mary Lee Johnston Won the Academy Award for Best Supporting Actress[6]
2014 Blackbird Claire Rousseau
2015 Bessie Ma Rainey
2016 Interwoven Barbara
Almost Christmas Aunt May
2022 The Reading Emma Leeden Post-Production
The Deliverance Post-Production
Ọdun Àkọlè Ipa Óṣere lobinrin ninu èrè àgbèlèwó Àkiyèsi
1999–2000 Moesha Nicole "Nikki" Parker 3 episodes)
2001 The Hughleys Nicole "Nikki" Parker 1 episode)
2002 The Proud Family Boonnetta (voice) 1 episode)
2003 Good Fences Ruth Crisp Television film
2004 The Bernie Mac Show Lynette 1 episode)
1999–2004 The Parkers Nicole "Nikki" Parker 5 seasons, 110 episodes)
2005 Girlfriends Host/Herself Cameo (episode S5 E16)
2006 Rugrats Aunt Moo Direct-to-DVD episode "Tales from the Crib: Three Jacks and a Beanstalk"
2006 Nip/Tuck Evetta Washington 1 episode)
2007 Flavor of Love Girls: Charm School Host/Herself 11 episodes
2007 The Game Plus Size Actress, Host 2 episodes)
2007 The Boondocks Jamiqua (voice) 1 episode)
2007 Ugly Betty L'Amanda 1 episode)
2009–2011 The Mo'Nique Show Host/Herself 2 seasons, 251 episodes
2014 Love & Hip Hop: New York Host/Herself 2 episodes – Reunion Special)
2015 Bessie Ma Rainey Television film
  • 2019: Mo'Nique Does Vegas (held at SLS Las Vegas)[7]

Ami Ẹyẹ ati Idanilọla

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Mo'Nique gba Àmi ẹyẹ Akademi, Àmi ẹyẹ BAFTA, Àmi ẹyẹ Golden Globe, Àmi ẹyẹ Emmy, Àmi ẹyẹ Óṣere Screen Guild ati Àmi ẹyẹ Oscar[8][9].