Jane Darwell

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àdàkọ:Use American English Àdàkọ:Use mdy dates

Jane Darwell
Darwell in the 1945 play
A Doll's House
Ọjọ́ìbíPatti Woodard
(1879-10-15)Oṣù Kẹ̀wá 15, 1879
Palmyra, Missouri, U.S.
AláìsíAugust 13, 1967(1967-08-13) (ọmọ ọdún 87)
Woodland Hills, California, U.S.
Resting placeForest Lawn Memorial Park, Glendale, California, U.S.
Iṣẹ́Actress
Ìgbà iṣẹ́1909–1964

Jane Darwell (tí orúkọ àbísọ rẹ̀ jẹ́ Patti Woodard; tí wọ́n bí ní Oṣù Kẹwàá ọjọ́ karùn-ún , Ọdún 1879 tí ó sì kú ní Oṣù kẹ́jọ ọjọ́ kẹtàlá , Ọdún 1967) jẹ́ Òṣèrè Amẹ́ríkà lórí orí-ìtàgé, fíìmù, àti tẹlẹfísọ̀n.[1] ó ṣe àfihàn ní fíìmù bí ọgọ́rùn-ún ní fún àsìkò sẹ́ńtúrí díẹ̀.

Ó jẹ́ òṣèrè tó gba Ebun Akademi bí Obìnrin Òṣèrè Kejì tó dára jù lọ.[2]


Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Obituary Variety, August 16, 1967.
  2. "Jane Darwell (1879-1967)". Find A Grave Memorial. Retrieved 2018-05-13.