Jump to content

Judi Dench

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Dame
Judi Dench
Judi Dench
Ọjọ́ìbíJudith Olivia Dench
9 Oṣù Kejìlá 1934 (1934-12-09) (ọmọ ọdún 89)
York, England
Ẹ̀kọ́Royal Central School of Speech and Drama
Iṣẹ́Actress
Ìgbà iṣẹ́1957–present
WorksList of Judi Dench performances
Olólùfẹ́
Michael Williams (actor)
(m. 1971; died 2001)
Àwọn ọmọFinty Williams
Àwọn olùbátan
  • Jeffery Dench (brother)
  • Emma Dench (niece)
  • Rebekah Elmaloglou (cousin)
  • Sebastian Elmaloglou (cousin)
AwardsList of awards and nominations received by Judi Dench

Judi Dench je Óṣèrè lóbinrin to gba Ebun Akademi bi Obinrin Osere Keji Didarajulo[1].

Ìgbèsi Àyè Àràbinrin naa

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Dench ni à bini Heworth Area ti York ni ọdun 1934 fun Eleanora Olive ati Reginald Arthur Dench to jẹ Dokita (1897-1964). Iya Óṣere lóbinrin naa wa lati iran irish ti a si bisi Dublin ṣugbọn baba rẹ wa lati iran èdè gẹẹsi to dagba si dublin to si ja ni Western Front ni Ógun Àgbayé Akọkọ[2]. Ni óṣu March ti ọdun 2013, Dench ni à ka gẹgẹ́bi ọkan lara awọn ààdọta to mọ àṣọ wọ julọ to si ti jù ọmọ ọdun ààdọta lọ[3]. Dench jẹ ólutilẹyin ati òlugbèja ti Liverpool ti bọọlu afẹsẹ̀gba F.C.

Dench fẹ̀ Michael Williams tò jẹ óṣèrè lọkunrin lati Liverpool ni ọdun 1971 ti wọn si bi ọmọ óbinrin Finty Williams (Óṣèrè lóbinrin) ni ọdun 1972[4]. Michael ku lori àisan jẹjẹrẹ ti lung ni ọdun 2001.

Lẹyin ọkọ Dench ni ò fẹ David Mills ni ọdun 2010[5][6]. Dench jẹ ẹni tò tako ọrọ nipa awọn óṣèrè lóbinrin to ti dagba ti wọn sin ṣiṣẹ.

Dench lọ si ilè iwe Mount to jẹ ilè iwè Quaker Independent ni York to si pada di Quaker. Óṣèrè lóbinrin naa lọsi ile iwe central fun ọrọ ati drama nibi to ti gba ẹbun èrè ṣiṣè mẹrin pẹlu Gold Medal gẹgẹbi àkẹẹkọ tò pègèdè ju[7][8][9].

Ami Ẹyẹ ati Idanilọla

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Dench gbà Àmi Ẹyẹ Akademi gẹgẹbi Óṣèrè lóbinrin to rani lọwọ julọ lori ipa rẹ gẹgẹbi Queen Elizabeth I ninu ere ifẹ, Ami Ẹyẹ Academy lori ere ti British mẹfa, Ami Ẹyẹ BAFTA, Ami Ẹyẹ Oscar, Ami Ẹyẹ Akademi Television ti British mẹrin, Ami Ẹyẹ Óṣèrè Screen Guild meji, Ami Ẹyẹ Tony ati Ami Ẹyẹ Laurence Olivier Meje. Dench ni à fi jẹ Officer ti Order ti British Empire ni ọdun 1970 ati Dame Commander ti Order ti British Empire ni ọdun 1988. Óṣèrè lóbinrin naa ti gba idanilọla ti Commonwealth ati degree[10][11][12][13].