Maureen Stapleton
Appearance
Lois Maureen Stapleton jẹ́ Òṣèré sinimá ágbéléwò tó gba Ámìn Ẹ̀yẹ Akádẹmì gẹ́gẹ́ bí òṣèrébìnrin aṣègbè fún olú ẹ̀dá ìtàn tó dára jù lọ.
Ìbẹ́rẹ́ ayé àti ètò ékọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Stapleton sí Troy, New York,tí awọn òbí rẹ̀ jẹ́ John P. Stapleton ati Irene (née Walsh).
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |