Jump to content

Lee Grant

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lee Grant
Grant in 1967
Ọjọ́ìbíLyova Haskell Rosenthal
October 31, during the mid-1920s[lower-alpha 1] (age 96–98).
New York City, U.S.
Iléẹ̀kọ́ gígaNeighborhood Playhouse School of the Theatre
Actors Studio
Iṣẹ́Actress and director
Ìgbà iṣẹ́1933–present
Olólùfẹ́
Arnold Manoff
(m. 1951; div. 1960)

Joseph Feury (m. 1970)
Àwọn ọmọ2, including Dinah Manoff

Lee Grant (orúkọ àbísọ ni Lyova Haskell Rosenthal tíwọ́n bí ní October 31, ní àárín 1920)[lower-alpha 1] jẹ́ òṣèré ilé Améríkà, Olùdarí Eré àti ẹni tí ó ń ṣe iṣé Documentary. Eré àkọkọ rẹ ní èyí tí o ṣe ọmọde tí ń Fẹ́wọ́ nínú eré Detective Story tí William Wyler ṣe Adarí eré náà ni 1951, àwọn tí wọn sì kópa náà ní Kiri Douglas àti Eleanor Parker. Ìkópa rẹ̀ ninu eré yìí ní ọ jẹ́ kí wọ́n yàn gẹ́gẹ́ bí Best Supporting Actresses lati lẹ̀ gba Àmì Ẹ̀yẹ Akádẹ́mì/ Oscar, ó sí gbà àmi ẹ̀yẹ Best Actress ní Cannes film Festivals Award. Ní ọdún 1952, ó wá lára àwọn mẹwàá tí Hollywood yóò fún ọdún méjìlá. Amò leyin èyí ní ó máa ń ṣe awọn eré ìtàgè kékéékèké tàbí iṣé Olúkóni ní ìgbà náà. Èyí náà mú kí óun àti ọkọ rẹ̀ wà ní ìpínyà. Ní àsìkò yìí Grant ṣe awọn eré ìtàgè. Ní ọdún 1963 ní Hollywood tó pé pada láti lè tẹsiwaju nínú iṣẹ eré rẹ̀ . Ó tí kópa nínú eré mọ́kànlèládọ́rin eré ọlọ́sọ́ọ̀sẹ̀ tí àkọlé rẹ ń jẹ́ Peyton Place lati ọdún 1965 sí 1966, àwọn eré mìíràn tí ó jẹ́ Olú òṣèré ní "Valley of Dolls" àti "In the heat of the Night ní 1967, àti Shampoo ní 1975, èyí tí o sí gbà àmi ẹ̀yẹ Oscar fún eré náà. Ní ọdún 1964 ó gbà Àmi ẹyẹ́ "Onje" fún ìkópa rẹ̀ nínú eré "The Maids. Nígbà tí ó ń ṣe iṣé eré gbogbo wọnyi ó wà lára àwọn tí wọ́n yàn ní ẹ̀mẹfà láti gba àmì ẹ̀yẹ "Emmy" ní ọdún 1966 sí 1933, èyí tí ó sí gbà Ẹbùn àmì ẹ̀yẹ náà ní ẹ̀ẹ̀mejì. Ní ọdún 1986, ọ darí òun àkójọpọ̀ kan Documentary tí àkọlé rẹ̀ jẹ́ "Down and Out ìn America" èyí tí ó wà ni ìsopọ̀ pẹlú Academy Awards for heat Documentary Feature, ní ọdún yẹn bákan náà ni ọ gba àmì ẹ̀yẹ Directires Guild Of America fún eré Nobody's Child.

Ìbẹ̀rẹpẹ̀pẹ̀̀́ Ayé[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Lee Grant tí àbísọ rẹ̀ njẹ Lyova Haskell Rosenthal[1][2] ní Manhattan, ó jẹ́ ọmọ kàn ṣoṣo tí Witia (nee Haskell), tí ó jẹ́ oṣiṣẹ ijoba tí ó ń mójú tó àwọn ọmọdé, tí bàbá rẹ̀ sí jẹ Abraham Wa. Rosenthal, tí ó jẹ́ Olùkọni àti Òǹtalẹ́. Wọn bí bàbá rẹ̀ sí Newyork, tí àwọn òbí rẹ̀ jẹ́ àwọn ará ìlú New, ìyá bàbá Lee grant jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Russia tí ó jé Jew.[3] Awọn Òbí rẹ̀ ń gbé 706 Riverside Drive ni Hamilton Heights ni Manhattan.[citation needed] Ọjọ́ ìbí Lee je àríyànjiyàn sùgbón oṣù tí wọn bí ní ọjọ kọkanlelógbọ̀n, oṣù kẹwàá tí ọdún tí wọn bí wá láàrin 1925 sí 1931, Amò gẹ́gẹ́ bí òun tí ìkànìyàn sọ, wọn bí Leè ní 1925 tàbí ,1926, ṣugbọn iṣẹ tí Grant Yan láàyò àti pé ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn tí wọn Yàn fún Àmì Ẹ̀yẹ Oscar wọn pinnu pé ọdún tí wọn bí máa jẹ 1927.[lower-alpha 1]

Grant kọ́kọ́ kọ orín àkọkọ ní Franco Leonil Oracohok ní Metropolitan Opera ni 1931.[4][5] and later joined the American Ballet as an adolescent.[6] Ó lọ sí ilé ẹkọ fún àwọn tí wọn ní ìfẹ fún iṣẹ ọnà Arts Students League of New York tí wọn pè ní Juliard School of Music, The High School of Music àti George Washington High School tí gbogbo àwọn ilé ẹkọ yìí wà ní New York. Grant jáde ilé ẹkọ gíga, lẹyìn tí ó jáde ní ọ gbà àmi ẹyẹ ẹkọ Ọ̀fẹ́ sí Neighborhood Playhouse School of the Theatre ní bí tí ó tí kò ní ọ̀dọ Sanford Meissner. Grant tún ni tẹ̀siwájú lẹnu ẹkọ rere ni Ita Hagen ní HB studio.[7] Lẹyìn èyí ó lọ sí Actors Studio ní New York.

Filmography[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Actress[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Year Film Role Notes
1951 Detective Story Shoplifter Cannes Film Festival Award for Best Actress
Nominated–Academy Award for Best Supporting Actress
Nominated–Golden Globe Award for Best Supporting Actress – Motion Picture
1953–1954 Search for Tomorrow Rose Peabody #1
1955 Storm Fear Edna Rogers
1959 Middle of the Night Marilyn
1963 The Balcony Carmen
An Affair of the Skin Katherine McCleod
1964 Pie in the Sky Suzy Filmed in 1962, but distribution problems postponed theatrical release until 1964. Retitled "Terror in the City".
The Fugitive Millie Hallop Episode: "Taps for a Dead War"
1965–1966 Peyton Place Stella Chernak Appeared in 71 episodes (August 19, 1965 – March 28, 1966)
Primetime Emmy Award for Outstanding Supporting Actress in a Drama Series
1967 Divorce American Style Dede Murphy
In the Heat of the Night Mrs. Leslie Colbert Nominated–Golden Globe Award for Best Supporting Actress – Motion Picture
Valley of the Dolls Miriam
The Big Valley Rosie Williams
1968 Buona Sera, Mrs. Campbell Fritzie Braddock
Judd, for the Defense Kay Gould Nominated–Primetime Emmy Award for Outstanding Lead Actress in a Limited Series or Movie
1969 The Big Bounce Joanne
Marooned Celia Pruett
1970 The Landlord Joyce Enders Nominated–Academy Award for Best Supporting Actress
Nominated–Golden Globe Award for Best Supporting Actress – Motion Picture
There Was a Crooked Man... Mrs. Bullard
1971 Columbo Leslie Williams Episode: "Ransom for a Dead Man"
Nominated–Primetime Emmy Award for Outstanding Lead Actress in a Limited Series or Movie
The Neon Ceiling Carrie Miller Primetime Emmy Award for Outstanding Lead Actress in a Limited Series or Movie
The Last Generation archive footage
Plaza Suite Norma Hubley
1972 Portnoy's Complaint Sophie Portnoy
1973 The Shape of Things Performer (and co-director) Nominated–Primetime Emmy Award for Outstanding Supporting Actress in Comedy-Variety, Variety or Music
1974 The Internecine Project Jean Robertson
1975 Shampoo Felicia Karpf Academy Award for Best Supporting Actress
Nominated–Golden Globe Award for Best Supporting Actress – Motion Picture
Fay Fay Stewart Nominated–Primetime Emmy Award for Outstanding Lead Actress in a Comedy Series
1976 Voyage of the Damned Lillian Rosen Nominated–Academy Award for Best Supporting Actress
Nominated–Golden Globe Award for Best Supporting Actress – Motion Picture
1977 Airport '77 Karen Wallace
The Spell Marilyn Matchett
1978 Damien: Omen II Ann Thorn
The Swarm Anne MacGregor
The Mafu Cage Ellen
1979 Backstairs at the White House Grace Coolidge TV miniseries
1979 When You Comin' Back, Red Ryder? Clarisse Ethridge
1980 Little Miss Marker The Judge
1981 Charlie Chan and the Curse of the Dragon Queen Mrs. Lupowitz
The Million Dollar Face Evalyna TV film
For Ladies Only Anne Holt TV film
1982 Thou Shalt Not Kill Maxine Lochman TV film
Visiting Hours Deborah Ballin
Bare Essence Ava Marshall TV film
1984 Billions for Boris Sascha Harris
Constance Mrs. Barr
Teachers Dr. Donna Burke
1985 Sanford Meisner: The American Theatre's Best Kept Secret Herself Documentary
1987 The Big Town Ferguson Edwards
1990 She Said No D.A. Doris Cantore TV film
1991 Defending Your Life Lena Foster
1992 Something to Live for: The Alison Gertz Story Carol Gertz TV film
Earth and the American Dream Narrator
Citizen Cohn Dora Marcus Cohn Nominated–Primetime Emmy Award for Outstanding Supporting Actress in a Miniseries or a Special
1996 It's My Party Amalia Stark
The Substance of Fire Cora Cahn
Under Heat Jane
2000 Dr. T & the Women Dr. Harper
The Amati Girls Aunt Spendora
2001 Mulholland Drive Louise Bonner
2005 The Needs of Kim Stanley Herself
Going Shopping Winnie

Director[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Year Production Notes
1973 The Shape of Things TV special
1975 For the Use of the Hall TV film
1976 The Stronger Short film
1980 Tell Me a Riddle Feature film
1981 The Willmar 8 Documentary film
1983 When Women Kill Documentary film (also narrator)
1984 A Matter of Sex TV film
1985 What Sex Am I? Documentary film (also narrator)
ABC Afterschool Special Episode: "Cindy Eller: A Modern Fairy Tale"
1986 Nobody's Child TV film
DGA Award for Outstanding Directorial Achievement in Dramatic Specials
Down and Out in America Documentary film (also narrator)
Academy Award for Best Documentary Feature
1989 Battered Documentary film (also narrator)
Staying Together Feature film
No Place Like Home TV film
1992 Women on Trial Documentary film (also narrator)
1994 Seasons of the Heart TV film
Following Her Heart TV film
Reunion TV film
1997 Say It, Fight It, Cure It TV film
Broadway Brawler unfinished film
1999 Confronting the Crisis: Childcare in America TV film
2000 American Masters Episode: "Sidney Poitier: One Bright Light"
The Loretta Claiborne Story TV film
2001 The Gun Deadlock TV film
2004 Biography Episode: "Melanie Griffith"
2000–2004 Intimate Portrait 43 episodes
2005 ... A Father... A Son... Once Upon a Time in Hollywood TV film

Awards and nominations[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Awards
Year Award Category Production Result
1952 Cannes Film Festival Best Supporting Actress Detective Story Gbàá
1952 Academy Awards Academy Award for Best Supporting Actress Detective Story Wọ́n pèé
1952 Golden Globe Awards Golden Globe Award for Best Supporting Actress - Motion Picture Detective Story Wọ́n pèé
1964 Obie Award Obie Award for Distinguished Performance by an Actress The Maids Gbàá
1966 Primetime Emmy Awards Primetime Emmy Award for Outstanding Supporting Actress in a Drama Series Peyton Place Gbàá
1967 Golden Globe Awards Golden Globe Award for Best Supporting Actress – Motion Picture In the Heat of the Night Wọ́n pèé
1968 Primetime Emmy Awards Primetime Emmy Award for Outstanding Lead Actress in a Limited or Anthology Series or Movie Judd, for the Defense Wọ́n pèé
1970 Academy Awards Academy Award for Best Supporting Actress The Landlord Wọ́n pèé
1970 Golden Globe Awards Golden Globe Award for Best Supporting Actress – Motion Picture The Landlord Wọ́n pèé
1971 Primetime Emmy Awards Primetime Emmy Award for Outstanding Lead Actress in a Limited or Anthology Series or Movie The Neon Ceiling Gbàá
1971 Primetime Emmy Awards Primetime Emmy Award for Outstanding Lead Actress in a Limited or Anthology Series or Movie Columbo Wọ́n pèé
1975 Academy Awards Academy Award for Best Supporting Actress Shampoo Gbàá
1975 Golden Globe Awards Golden Globe Award for Best Supporting Actress – Motion Picture Shampoo Wọ́n pèé
1975 Primetime Emmy Awards Primetime Emmy Award for Outstanding Lead Actress in a Comedy Series Fay Wọ́n pèé
1976 Academy Awards Academy Award for Best Supporting Actress Voyage of the Damned Wọ́n pèé
1976 Golden Globe Awards Golden Globe Award for Best Supporting Actress – Motion Picture Voyage of the Damned Wọ́n pèéItokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Roberts, Jerry. Encyclopedia of Television Film Directors, Scarecrow Press, 1st edition (June 5, 2009), Amazon Digital Services, Inc; ASIN: B009W3C7E8
  2. Katz, Ephraim. The Film Encyclopedia, Harper Perennial (1998) p. 552; ISBN 0-06-273492-X
  3. Profile, forward.com; accessed September 9, 2014.
  4. Olin Downes. The Opera: Scotti Cheered as Chim-Fen in "L'Oracolo"-Tribute to Mme. Jeritza in "Cavalleria." November 24, 1931. The New York Times. "Hoo-Chee...Lyova Rosenthal"
  5. "Movie Memory Lee Grant 1976". New York Daily News. December 1, 2002. http://www.nydailynews.com/movie-memory-lee-grant-1976-article-1.495393. 
  6. Gray, Spalding. Life Interrupted: The Unfinished Monologue, Random House (2005) p. 154
  7. HB Studio Alumni


Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref> tags exist for a group named "lower-alpha", but no corresponding <references group="lower-alpha"/> tag was found