Jump to content

Jennifer Hudson

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jennifer Hudson
Jennifer Hudson
Ọjọ́ìbíJennifer Kate Hudson
12 Oṣù Kẹ̀sán 1981 (1981-09-12) (ọmọ ọdún 43)
Chicago, Illinois, U.S.
Ẹ̀kọ́Langston University
Kennedy-King College
Iṣẹ́
  • Singer
  • actress
Ìgbà iṣẹ́2004–present
Works
Alábàálòpọ̀
  • James Payton (1999–2007)
  • David Otunga (2007–2017)
Àwọn ọmọ1
AwardsList of awards and nominations received by Jennifer Hudson
Musical career
Irú orin
InstrumentsVocals
Years active2006–present
Labels
  • Arista Records
  • Arista
  • J Records
  • J
  • RCA Records
  • RCA
  • Epic Records
  • Epic
Associated actsNe-Yo
Websitejenniferhudson.com

Jennifer Hudson je osere lóbinrin ati akọrin to gba Ebun Akademi bi Obinrin Osere Keji Didarajulo[1].

Ìgbèsi Àràbinrin naa

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Hudson ni a bini óṣù september ọdun 1981 ni Chicago, Illinois. Jennifer ni a tọ ni ilana Baptist ni Englewood. Nigba ti jennifer pè ọmọ ọdun meje ni ó bẹrẹ sini kọrin pẹlu atilẹyin Iya Iya rẹ agba Julia[2]. Ni Óṣu January ọdun 2002, Óṣèrè lóbinrin naa sign recording contract rẹ̀ akọkọ pẹlù Record Righteous.

Ni ọdun 1999, Hudson fẹ James Payton ni ọmọ ọdun meji dinlóógun. Awọn mejeji pinya ni ọdun 2007. Ni ọdun 2008, óṣèrè lóbinrin naa fẹ David Otunga to si bi ọmọ ọkunrin David Daniel Otunga. Awọn mèjèji pinya ni ọdun 2017[3][4].

Jennifer kẹkọ ni Dunbar Vocational High School nibi to ti jade ni ọdun 1999 lẹyin rẹ ni óṣèrè lóbinrin naa lọsi ilè iwè giga Langston ṣugbọn ti o kurò nigba ọkan rẹ fasi ilé nibi o lọsi collegi Kennedy-King[5].

Ami Ẹyẹ ati Idanilọla

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Hudson jẹ óbinrin to kèrè ju ilẹ Africa-America keji lati gba Ami ẹyẹ entertainment America mẹrin to pataki EGOT (Ami ẹyẹ ti Emmy, Grammy, Oscar ati Tony)[6][7][8]. Óṣèrè lobinrin naa gba irawọ lori Hollywood Walk of Fame ni ọdun 2013[9][10].