Shelley Winters
Shelley Winters (August 18, 1920 – January 14, 2006) jẹ óṣere lobinrin to gba Ebun Akademi bi Obinrin Osere Keji Didarajulo[1].
Igbesi Aye Arabinrin naa
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Shelley Winters jẹ óṣere lobinrin ilẹ amẹrica ti iṣẹ rẹ lọ fun ọdun mẹwa lọnọ meje ti ó si ti yọju ni óriṣiriṣi èrè agbelewo.Shelley ni a bini Shirley Schrift ni St.Louis, ilẹ Missouri. Óṣere lobinrin naa jẹ ọmọ Rose (Akọrin ni St. Louis Municipal Opera Theatre) ati Jonas Schrift (Oluran àṣọ awọn ọkunrin) ti wọn si jẹ ijọ ẹlẹsin jew[2].
Shelley fẹ ọkọ lẹmẹrin;
- Captain Mack Paul Mayer ni ọjọ 29, óṣu December ni ọdun 1948. Awọn mejeji pinya ni ọdun 1948[3].
- Vittorio Gassman ni ọjọ 28, óṣu April ni ọdun 1952. Awọn mejeji pinya ni óṣu june ni ọdun 1954[3].
- Anthony Franciosa ni ọjọ kẹrin, óṣu May ni ọdun 1957. Awọn mejeji pinya ni ọjọ 18, óṣu November ni ọdun 1960[4].
- Gerry DeFord ni ọjọ mẹtala, óṣu January ni ọdun 2006[5].
Shelly Winters ku ni ọmọ ọdun marun lèèlogọrin ni ọjọ kẹrin óṣú january ni ọdun 2006 lórin aisan ọkan ni Rehabilitation Center ti Beverly Hills[6].
Ẹkọ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Shelley lọsi ilè iwè jew ti ilẹ jamaica nibi ti arabinrin naa ti kọ orin hebrew. Óṣere lobinrin naa kọ èrè siṣè ni ilè iwè tuntun ni New York[7].
Ami Ẹyẹ Ati Idanilọla
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ami Ẹyẹ Akademi
Ọdun | Ipó | Akọlè | Èsi | Ref(s) |
---|---|---|---|---|
1951 | Ami Ẹyẹ Akadẹmi gẹgẹbi Óṣere lobinrin to dara ju | A Place in the Sun | Wọn yan | [8] |
1959 | Ami Ẹyẹ Akademi gẹgẹbi Óṣere lobinrin to fun ni iran lọwọ julọ | The Diary of Anne Frank | pègèdè | |
1965 | A Patch of Blue | pègèdè | ||
1972 | The Poseidon Adventure | Wọn yan |
Ami Ẹyẹ Akademi Èrè Agbelewo ti Ilẹ British
Ọdun | Ipó | Akọlè | Èsi | Ref(s) |
---|---|---|---|---|
1972 | Ami Ẹyẹ BAFTA gẹgẹbi Óṣere lobinrin to dara ju ninu ipó iranilọwọ | The Poseidon Adventure | Wọn yan | [9] |
1977 | Next Stop, Greenwich Village | Wọn yan |
Ami Ẹyẹ ti Golden Globe
Ọdun | Ipó | Akọlẹ | Èsi | Ref(s) |
---|---|---|---|---|
1951 | A Place in the Sun | Wọn yan | [10] | |
1959 | The Diary of Anne Frank | Wọn yan | ||
1962 | Ami Ẹyẹ ti Golden Globe gẹgẹbi Óṣere lobinrin lori Motion Picture – Drama | Lolita | Wọn yan | |
1966 | rowspan=3 | Alfie | Wọn yan | |
1972 | Pègèdè | |||
1976 | Next Stop, Greenwich Village | Wọn yan |
Ami Ẹyẹ Primetime Emmy
Ọdun | Ipó | Akọlè | Èsi | Ref(s) |
---|---|---|---|---|
1964 | Ami Ẹyẹ Primetime Emmy gẹgẹbi Óṣere lobinrin to pegede julọ ninu Limited Series or Movie| rowspan=2|Bob Hope Presents the Chrysler Theatre | Pègèdè | [11] | |
1966 | Wọn yan | |||
1974 | Óṣere lobinrin to ranilọwọ julọ ninu – Comedy/Drama Series | McCloud NBC Sunday Mystery Movie | Wọn yan |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ https://archive.org/details/shelleyalsoknown00wint
- ↑ https://jwa.org/encyclopedia/article/winters-shelley
- ↑ 3.0 3.1 https://www.today.com/popculture/shelley-winters-dies-85-wbna10851769
- ↑ https://www.chicagotribune.com/news/ct-xpm-1989-08-21-8901060587-story.html
- ↑ https://www.closerweekly.com/posts/shelley-winters-the-life-career-and-loves-of-the-legendary-actress/
- ↑ https://www.nytimes.com/2006/01/15/nyregion/shelley-winters-toughtalking-oscar-winner-in-anne-frank-and-patch.html
- ↑ https://www.nytimes.com/1994/04/07/theater/actors-studio-to-teach-program-at-new-school.html
- ↑ "Shelley Winters, two-time Oscar winner, dies at 85". The Seattle Times. January 15, 2006. Retrieved July 10, 2022.
- ↑ "Shelley Winters – BAFTA Awards". British Academy of Film and Television Arts. Retrieved July 10, 2022.
- ↑ "Shelley Winters – Golden Globes". Hollywood Foreign Press Association. Retrieved July 10, 2022.
- ↑ "Shelley Winters – Emmy Awards". Academy of Television Arts & Sciences. Retrieved July 10, 2022.