Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Juliette Binoche (ìpè Faransé: [ʒyljɛt binɔʃ] ; tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹsàn-án oṣù kẹ́ta, ọdún 1964) jẹ́ Òṣèrè àti Oníjó Faransé. Ó ṣe àfihàn ní fíìmù bíi ọgọ́ta tí wọ́n pè é sí àti wí pé ó tún jẹ́ ẹni tó gba àwọn àwọ́ọ̀dù bíi Àwọ́ọ̀dù Akadẹ́mì, British Academy Film Award , Silver Bear , Cannes Film Festival Award , Volpi Cup àti César .
Binoche bẹ̀rẹ sí ní má kọ́ bí wọ́n ṣe máa ń ṣe eré ní ọ̀dọ́ . Lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré tó ṣe lórí ìtàgé, orúkọ rẹ̀ wa nínu fíìmù tí gbogbo ènìyàn mọ̀ síauteur tí Jean-Luc Godard jẹ́ atọ́kùn rẹ̀ (Hail Mary , 1985), Jacques Doillon (Family Life , 1985), ati André Téchiné ; tí eré ìgbẹ̀yìn yìí jẹ́ kó di gbajúgbajà ní Faransé tí ó fi jẹ́ kí ó di olórí Òṣèrè ní eré oníṣe Rendez-vous (1985). Eré àkọ́kọ́ tó jẹ́ ti Gẹ̀ẹ́sì tó ṣe The Unbearable Lightness of Being (1988), tí eré yìí jẹ́ kó di ènìyàn tí àwọn ènìyàn púpọ̀ wá mọ̀. Lẹ́yìn náà eré tó kópa Krzysztof Kieślowski tí orúko eré náà ń jẹ́ Three Colours: Blue (1993).
Nígbà ọdún 2000, Ó ti wà nípò ẹni tó ti ṣe àṣeyọrí tí kò dẹ̀ fẹ́ kó bọ. Bí ó ṣe ń ṣe eré Gẹ̀ẹ́sì náà lọ ń ṣe ti Faransé. Ní ọdún 2010, Ó gba àwọ́ọ̀dù fún Òṣèrè tó dára jùlọ lóbìnrin ní Cannes Film Festival fún ipa rẹ́ gẹ́gẹ́ bí Abbas Kiarostami ní eré tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Certified Copy . Wọ́n tún fún ní àwọ́ọ̀dù Maureen O'Hara Award ní Kerry Film Festival ní ọdún 2010, àwọ́ọ̀dù tó jẹ́ wí pé obìnrin tó bá ṣe àṣeyọrí ní isẹ́ Òṣèrè nìkan ló má fún .[ 1]
Year
Title
Role
Director
Notes
1983
Liberty belle
Girl at the rally
Pascal Kané
1985
Le Meilleur de la vie
Veronique's friend
Renaud Victor
Farewell Blaireau
Brigitte
Bob Decout
Rendez-vous
Nina/Anne Larrieux
André Téchiné
Family Life
Natacha
Jacques Doillon
Nanas, Les Les Nanas
Antoinette
Annick Lanoë
Hail Mary
Juliette
Jean-Luc Godard
1986
Mauvais Sang
Anna
Leos Carax
My Brother-in-Law Killed My Sister
Esther Bouloire
Jacques Rouffio
1988
Unbearable Lightness of Being, The The Unbearable Lightness of Being
Tereza
Philip Kaufman
1989
tour de manège, Un Un tour de manège
Elsa
Pierre Pradinas
1991
Amants du Pont-Neuf, Les Les Amants du Pont-Neuf
Michèle Stalens
Leos Carax
1992
Damage
Anna Barton
Louis Malle
Emily Brontë's Wuthering Heights
Cathy Linton / Catherine Earnshaw
Peter Kosminsky
1993
Three Colors: Blue
Julie Vignon de Courcy
Krzysztof Kieślowski
1994
Three Colors: White
Julie Vignon de Courcy
Three Colors: Red
Julie Vignon de Courcy
1995
Horseman on the Roof, The The Horseman on the Roof
Pauline de Théus
Jean-Paul Rappeneau
1996
English Patient, The The English Patient
Hana
Anthony Minghella
Couch in New York, A A Couch in New York
Beatrice Saulnier
Chantal Akerman
1998
Alice and Martin
Alice
André Téchiné
1999
Children of the Century
George Sand
Diane Kurys
2000
Chocolat
Vianne Rocher
Lasse Hallström
Code Unknown
Anne Laurent
Michael Haneke
Widow of Saint-Pierre, The The Widow of Saint-Pierre
Pauline
Patrice Leconte
2002
Jet Lag
Rose
Danièle Thompson
2004
In My Country
Anna Malan
John Boorman
2005
Mary
Marie Palesi/Mary Magdalene
Abel Ferrara
Bee Season
Miriam
Scott McGehee
Caché
Anne Laurent
Michael Haneke
2006
Breaking and Entering
Amira
Anthony Minghella
Few Days in September, A A Few Days in September
Irène Montano
Santiago Amigorena
Paris, je t'aime
Suzanne
Nobuhiro Suwa
Segment: "Place des Victoires"
2007
Dan in Real Life
Marie
Peter Hedges
Disengagement
Ana
Amos Gitai
Flight of the Red Balloon
Suzanne
Hou Hsiao-hsien
2008
Paris
Elise
Cédric Klapisch
Summer Hours
Adrienne
Olivier Assayas
Shirin
Woman in audience
Abbas Kiarostami
2010
Certified Copy
Elle
2011
The Son of No One
Loren Bridges
Dito Montiel
Elles
Anne
Małgorzata Szumowska
2012
Cosmopolis
Didi Fancher
David Cronenberg
Another Woman's Life
Marie Speranski
Sylvie Testud
An Open Heart
Mila
Marion Laine
2013
Camille Claudel 1915
Camille Claudel
Bruno Dumont
A Thousand Times Good Night
Rebecca
Erik Poppe
2014
Words and Pictures
Dina Delsanto
Fred Schepisi
Godzilla
Sandra Brody
Gareth Edwards
Clouds of Sils Maria
Maria Enders
Olivier Assayas
2015
The 33
María Segovia
Patricia Riggen
7 Letters
Elle
Eric Khoo
Segment "Cinema"; cameo[ 2]
Endless Night
Josephine Peary
Isabel Coixet
The Wait
Anna
Piero Messina
2016
Slack Bay
Aude Van Peteghem
Bruno Dumont
Polina
Liria Elsaj
Valérie Müller
Angelin Preljocaj
2017
Ghost in the Shell
Dr. Ouelet
Rupert Sanders
Baby Bumps
Mado
Noémie Saglio
Let the Sunshine In
Isabelle
Claire Denis
2018
High Life
Dr. Dibs
Vision
Jeanne
Naomi Kawase
Non-Fiction
Selena
Olivier Assayas
2019
Who You Think I Am
Claire Millaud
Safy Nebbou
The Truth
Lumir
Hirokazu Kore-eda
2020
How to Be a Good Wife
Paulette Van der Beck
Martin Provost
2021
Between Two Worlds
Marianne Winckler
Emmanuel Carrère
2022
Both Sides of the Blade
Sara
Claire Denis
Paradise Highway
Sally
Anna Gutto
1936–1950 1951–1975 1976–2000 2001–present