Octavia Spencer

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Octavia Spencer
"Hidden Figures" Screening at the White House (NHQ201612150008) (cropped).jpg
Spencer at the White House in 2016
Ọjọ́ìbíOctavia Lenora Spencer
Oṣù Kàrún 25, 1972 (1972-05-25) (ọmọ ọdún 48)
Montgomery, Alabama, U.S.
Iléẹ̀kọ́ gígaAuburn University
Iṣẹ́
  • Actress
  • author
  • producer
Ìgbà iṣẹ́1996–present
AwardsFull list

Octavia Lenora Spencer (ọjọ́ìbí May 25, 1972)[1] ni òṣeré, olùkọ̀wé àti olóòtú ará Amẹ́ríkà. Spencer ti gba ẹ̀bùn ọ̀pọ̀lọpọ̀ fún idọ́n ìṣerẹ́ rẹ̀, nínú wọn ni Ẹ̀bùn Akádẹ́mì kan, Ẹ̀bùn Golden Globe kan, àti Ẹ̀bùn Ẹgbẹ́ àwọn Òṣeré mẹ́ta.


Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Octavia Spencer Biography: Film Actress, Television Actress (1972–)". Biography.com. Archived from the original on August 11, 2016. Retrieved January 16, 2017.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)