Marcia Gay Harden
Appearance
Marcia Gay Harden | |
---|---|
Harden in 2013 | |
Ọjọ́ìbí | 14 Oṣù Kẹjọ 1959 La Jolla, California, U.S. |
Ẹ̀kọ́ | University of Texas, Austin (BA) New York University (MFA) |
Iṣẹ́ | Òṣérébinrin |
Ìgbà iṣẹ́ | 1979–present |
Olólùfẹ́ | Thaddaeus Scheel (m. 1996; div. 2012) |
Àwọn ọmọ | 3 |
Awards | Full list |
Marcia Gay Harden ni wọ́n bí ní ọjọ́ kerìnlá, oṣù kẹjo ọdún 1959 jẹ́ òṣèrébinrin Orílẹ̀ èdè America tó ti gba orisirisi ebún bi Ebun Akademi, ati Tony Award.[1]
Ìgbà èwe àti bí ó ṣe kẹ́kọ̀ọ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí sí La Jolla, California, omo-bíbi Beverly Harden (née Bushfield).[2] Harden parí ní ile eko girama ti Surrattsville, Clinton, Maryland ni odun 1976.O parí ni Yunifasiti Texas to wa ni olúlú Austin ni odun 1980. O keko gboye Masters of Fine Arts lati fásitì New York University's Tisch School of Arts ni odun 1988.[3]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Marcia Gay Harden". Dallas Museum of Art. March 15, 2018. Retrieved August 29, 2022.
- ↑ "- Turner Classic Movies". Turner Classic Movies. August 21, 2022. Retrieved August 29, 2022.
- ↑ https://www.backstage.com/magazine/article/character-studies-marcia-gay-harden-19705/
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |