Jump to content

Jo Van Fleet

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àdàkọ:Use mdy dates

Jo Van Fleet
Van Fleet, c. 1955
Ọjọ́ìbíCatherine Josephine Van Fleet[1]
(1915-12-29)Oṣù Kejìlá 29, 1915
Oakland, California, U.S.
AláìsíJune 10, 1996(1996-06-10) (ọmọ ọdún 80)
Jamaica, New York, U.S.
Iṣẹ́Actress
Ìgbà iṣẹ́1944–1986
Olólùfẹ́
William G. Bales
(m. 1946; his death 1990)
Àwọn ọmọ1

Catherine Josephine Van Fleet (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kọkọ̀ndílọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá, ọdún 1915[1] tí ó sì fi ayé lè ní Ọjọ́ kẹwàá oṣù kẹfà, ọdún 1996) jẹ́ Òṣèrè orí-ìtàgé, fíìmù àti Tẹlẹfísọ̀n Amẹ́ríkà. Ní gbogbo ìgbà pípẹ́ tó fi ṣe eré, níbi ọdún ogójì, ó sáábà máa ń kópa ẹni tó ju ọjọ́ orí ẹ̀ lọ. Van Fleet gba Tony Award ní ọdún 1954 fún ipa rẹ̀ ní Broadway tí The Trip to bountiful sẹ àti wí pé n tún gba àwọ́ọ̀dù Akadẹ́mì fún Òṣèrè tó ṣe igi lọ́gbà èyí fún olórí Òṣèrè ní

East of Eden.[2]

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 "The Birth of Cathrin Vanfleet [sic]sic]", online database of California birth records, 1905-1995; californiabirthindex.org. Retrieved September 2, 2015.
  2. Vallance, Tom. "Obituary: Jo Van Fleet", The Independent (London), June 20, 1996. Retrieved November 21, 2013.