Jump to content

Fay Bainter

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Fay Bainter
Bainter in 1950
Ọjọ́ìbíFay Okell Bainter
(1893-12-07)Oṣù Kejìlá 7, 1893
Los Angeles, California, U.S.[1]
AláìsíApril 16, 1968(1968-04-16) (ọmọ ọdún 74)
Los Angeles, California, U.S.
Resting placeArlington National Cemetery
Iṣẹ́Actress, Singer
Ìgbà iṣẹ́1910–1961
Olólùfẹ́
Reginald Venable
(m. 1921; his death 1964)
Àwọn ọmọ1

Fay Okell Bainter (December 7, 1893 – April 16, 1968) jẹ́ òṣèré orí ìtàgè ni orílé èdè Améríkà.[2] Óò gbà àmi ẹ̀yẹ ni Akádẹ́mì fún ẹni tí ó ń ṣe amúgbálẹ́gbẹ́ fún Olu òṣèré inú eré tí àkọlé rẹ ń ni Jezebel ní ọdún 1938, ó sí gbà Àmi ẹyẹ Irawọ ní Hollywood Walk of Fame ní ọdún na. Fay Bainter jẹ́ òṣèrée tó gba Ẹ̀bùn Akádẹ́mì gẹgẹ bí obìnrin Òṣèré Kejì tí ó Didarajulo.

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ Ayé[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwòrán ti Fay Bainter láti ọwọ́ Robert Henri ní (1918)

Wọ́n bí Sí Los Angeles ní California, ó sí jẹ́ ọmọ bíbí Charles F. Bainter àti Mary Okell. Ní ọdún 1910, o jẹ́ òṣèré orí ìtàgè tí o má ń lọ káàkàkiri. Ní ọdún 1908 ni ó kọ́kọ́ ṣe afihan ará rẹ nínú eré ori ìtàgè tí àkọlé rẹ ń jẹ́ The county Chairman ní orí ìtàgè kàn ní Morosco ni Burbank, ní ìlú California, lẹyìn èyí ni ó jáde sí Broadway tí o kópa nínú eré kàn tí àkọlé rẹ ń jẹ́ "The Rose Of Panama" tí ọ jẹ Celine Marinter ní ọdún 1912. Lẹyìn ìgbà yìí óò ti ṣe oríṣi àwọn eré ori ìtàgè lọ́pọ̀ yanturu ní ìlú New York, àwọn àkọlé eré náà sì ni "East Is West, The he Willow Tree, and Dodsworth (play). Ní ọdún 1926, ó wà nínú eré kàn tí ó ṣe Waiter Abel tí àkọlé eré náà sì ń jẹ Enemy èyí tí ó jẹ́ eré Broadway kàn tí Channing Pollock kọ.

Ìgbé ayé[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Fay Bainter àti Reginald Venable ṣe ìgbéyàwó ní oṣù kẹfà ọdún 1921 ni Riverside ní California.[3] Àwọn méjèèjì sí ní ọmọ ọkùnrin kàn tí wón sọ ní Reginald Venable Jr. ní (1926-1974) tí ọmọ náà sì jẹ́ òṣèré Bainter jẹ́ ẹgbọn fún òṣeré tí amò sí Dorothy Burgess Reginald Venable jẹ́ Agbófínro fún orílé èdè Améríkà. Wọ́n sìn Fay àti ọkọ rẹ sí itẹ́ òkú Arlington National Cemetery.[4]

Ìgbé ayé[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Fay Bainter àti Reginald Venable ṣe ìgbéyàwó ní oṣù kẹfà ọdún 1921 ni Riverside ní California.[3] Àwọn méjèèjì sí ní ọmọ ọkùnrin kàn tí wón sọ ní Reginald Venable Jr. ní (1926-1974) tí ọmọ náà sì jẹ́ òṣèré Bainter jẹ́ ẹgbọn fún òṣeré tí amò sí Dorothy Burgess Reginald Venable jẹ́ Agbófínro fún orílé èdè Améríkà. Wọ́n sìn Fay àti ọkọ rẹ sí itẹ́ òkú Arlington National Cemetery.[5]

Àwọn eré rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Films
Year Title Role Notes
1934 This Side of Heaven Francene Turner
1937 Quality Street Susan Throssel
1937 The Soldier and the Lady Strogoff's Mother
1937 Make Way for Tomorrow Anita Cooper
1938 White Banners Hannah Parmalee Nominated – Academy Award for Best Actress
1938 Jezebel Aunt Belle Massey Academy Award for Best Supporting Actress
1938 Mother Carey's Chickens Mrs. Margaret Carey
1938 The Arkansas Traveler Mrs. Martha Allen
1938 Shining Hour, TheThe Shining Hour Hannah Linden
1939 Yes, My Darling Daughter Ann "Annie" Murray
1939 The Lady and the Mob Hattie Leonard
1939 Daughters Courageous Nancy "Nan" Masters
1939 Our Neighbors – The Carters Ellen Carter
1940 Young Tom Edison Mrs. Samuel (Nancy) Edison
1940 Our Town Mrs. Julia Hersey Gibbs
1940 Bill of Divorcement, AA Bill of Divorcement Margaret "Meg" Fairfield
1940 Maryland Charlotte Danfield
1941 Babes on Broadway Miss "Jonesy" Jones
1942 Woman of the Year Ellen Whitcomb
1942 War Against Mrs. Hadley, TheThe War Against Mrs. Hadley Stella Hadley
1942 Journey for Margaret Trudy Strauss
1942 Mrs. Wiggs of the Cabbage Patch Mrs. Elvira Wiggs
1943 Human Comedy, TheThe Human Comedy Mrs. Macauley
1943 Presenting Lily Mars Mrs. Thornway
1943 Salute to the Marines Jennie Bailey
1943 Cry 'Havoc' Captain Alice Marsh
1944 Heavenly Body, TheThe Heavenly Body Margaret Sibyll
1944 Dark Waters Aunt Emily
1944 Three Is a Family Frances Whittaker
1945 State Fair Melissa Frake
1946 Kid from Brooklyn, TheThe Kid from Brooklyn Mrs. E. Winthrop LeMoyne
1946 Virginian, TheThe Virginian Mrs. Taylor
1947 Deep Valley Ellie Saul
1947 Secret Life of Walter Mitty, TheThe Secret Life of Walter Mitty Mrs. Eunice Mitty
1948 Give My Regards to Broadway Fay Norwick
1948 June Bride Paula Winthrop
1951 Close to My Heart Mrs. Morrow
1953 President's Lady, TheThe President's Lady Mrs. Donaldson
1961 Children's Hour, TheThe Children's Hour Mrs. Amelia Tilford Laurel Award for Top Female Supporting Performance (2nd place)
Nominated – Academy Award for Best Supporting Actress
Nominated – Golden Globe Award for Best Supporting Actress – Motion Picture

Àwọn Àfihàn rè lorí Rẹ́díò[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Year Program Episode/source
1946 Suspense 180/“The Lucky Lady”
1952 Theatre Guild on the Air "The Search"[6]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Fay Bainter". The Montreal Gazette: p. 35. Apr 18, 1968. https://news.google.com/newspapers?id=oAIuAAAAIBAJ&pg=4447,4238367. 
  2. Obituary Variety, April 24, 1968.
  3. 3.0 3.1 Los Angeles Times, November 24, 1921, "Marriage Of Star Is Declared – Wedding of Fay Bainter and Navy Man Revealed by Mother of Actress", p. 17.
  4. Arlington National Cemetery
  5. Arlington National Cemetery
  6. Kirby, Walter (March 16, 1952). "Better Radio Programs for the Week". The Decatur Daily Review. p. 44. https://www.newspapers.com/clip/2470060/the_decatur_daily_review/.  open access publication - free to read

Fún Àkàsíwaju si[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Alistair, Rupert (2018). "Fay Bainter". The Name Below the Title : 65 Classic Movie Character Actors from Hollywood's Golden Age (softcover) (First ed.). Great Britain: Independently published. pp. 22–25. ISBN 978-1-7200-3837-5.