Anna Paquin

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Anna Paquin
Ọjọ́ìbíAnna Hélène Paquin
24 Oṣù Keje 1982 (1982-07-24) (ọmọ ọdún 41)
Winnipeg, Manitoba, Canada
Ọmọ orílẹ̀-èdè
  • Canada
  • New Zealand
Ẹ̀kọ́Yunifásítì Kòlúmbíà
Iṣẹ́Òṣèrébinrin
Ìgbà iṣẹ́1993–títí di asikò yi
Olólùfẹ́
Stephen Moyer (m. 2010)
Àwọn ọmọ2

Anna Paquin /ˈpækwɪn/ PAK-win tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù kéje, ọdún 1982) jẹ́ òṣèrébinrin orílẹ̀-èdè New Zealand to gba Ebun Akademi Obinrin Osere Keji Didarajulo.[1]

Ìgbà èwe àti bí ó ṣe kẹ́kọ̀ọ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Anna Paquin sí Winnipeg, Manitoba, o jẹ́ ọmọ Mary Paquin (née Brophy) ati Brian Paquin.[2] Paquin lọ sí ile ẹ́kọ́ alakọbréẹ̀ Raphael House Rudolf Steiner School kí o tó tẹ̀sìwájú lo Hutt Intermediate School (1994-95), ti o si lo ile-iwe girama ti Wellington Girls' College, ó gba rẹ̀ ìwé-éri girama ni Windward School in ìlú Los Angeles.

Awọn Fíímù tí o tí Kópa[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ọdún Àkọ́ọ́lé Ipa Akìyésìí
1993 The Piano Flora McGrath
1996 Jane Eyre Young Jane Eyre
Fly Away Home Amy Alden
1997 Amistad Queen Isabella II of Spain
1998 Hurlyburly Donna
Laputa: Castle in the Sky Sheeta (voice) English dub
1999 A Walk on the Moon Alison Kantrowitz
She's All That Mackenzie Siler
It's the Rage Annabel Lee
2000 X-Men Marie / Rogue
Almost Famous Polexia Aphrodisia
Finding Forrester Claire Spence
2001 Buffalo Soldiers Robyn Lee
2002 Darkness Regina
25th Hour Mary D'Annunzio
2003 X2 Marie / Rogue
2005 Steamboy James Ray Steam (voice) English dub
The Squid and the Whale Lili
2006 X-Men: The Last Stand Marie / Rogue[3]
2007 Blue State Chloe Hamon Also executive producer
Mosaic Maggie (voice)
Trick 'r Treat Laurie
2010 The Romantics (film) Lila Hayes
Open House Jennie
2011 Scream 4 Rachel Cameo
Margaret Lisa Cohen
The Carrier Kim Short film
2013 Straight A's Katherine
Free Ride Christina Also producer
2014 X-Men: Days of Future Past Marie / Rogue Cameo; The Rogue Cut
2015 The Good Dinosaur Ramsey (voice)
2018 Furlough Lily Benson
The Parting Glass Colleen Àtí gẹ́ẹ́gẹ bí olóòtú
Tell It to the Bees Dr. Jean Markham
2019 The Irishman Peggy Sheeran
2021 American Underdog Brenda Warner

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Sayre, Will (July 5, 2022). "Anna Paquin's 5 Best Performances, Ranked". MovieWeb. Retrieved August 27, 2022. 
  2. "Anna Paquin. Biography, news, photos and videos". hellomagazine.com. January 1, 1970. Retrieved August 27, 2022. 
  3. Maher, Dani (June 1, 2022). "Anna Paquin on Flack, True Spirit, & Her Love Of Powerful Female Roles". Harper's Bazaar Australia. Retrieved August 27, 2022.