Jump to content

Mercedes Ruehl

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Mercedes Ruehl
Ruehl in 2009
Ọjọ́ìbíMercedes J. Ruehl
28 Oṣù Kejì 1948 (1948-02-28) (ọmọ ọdún 76)
Jackson Heights, Queens
Ẹ̀kọ́College of New Rochelle
Pacific Conservatory of the Performing Arts
Iṣẹ́Actor
Ìgbà iṣẹ́1976–present
Olólùfẹ́
David Geiser
(m. 1999; died 2020)
Àwọn ọmọ2
Àwọn olùbátanPeter Ruehl (brother)

Mercedes Ruehl ni a bini ọjọ kèji dinlọgbọn óṣu february ni ọdun 1948 jẹ Óṣèrè lobinrin to gba Ebun Akademi bi Obinrin Osere Keji Didarajulo[1].

Igbèsi Àyè Àràbinrin naa[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ruehl ni a bisi Jackson Heights, Queens, New York City fun Mercedes J. Ruehl (Ólukọ) ati Vincent Ruehl (Agenti ti FBI)[2]. Babà óṣèrè lobinrin naa wa lati iràn German ati Irish, Iya rẹ wa lati iran Cuban ati Irish. Ruehl ni ó dàgbà si ilanà Catholic[3].

Óṣèrè lobinrin naa bẹrẹ irin àjó iṣẹ rẹ ni theatre pẹlu Ilè iṣẹ Denver Center Theatre. Ni ọdun 1999, Ruehl fẹ David Geiser ti ó jẹ painter. Óṣèrè gba ọmọ ọkunrin kan tọ ti órukọ rẹ njẹ Jake ti a bini ọdun 1995. David Geiser ku lójiji ninu órun rẹ ni ilè rẹ ni ọjọ kẹrin dinlógun óṣu October ni ọdun 2020 lori aisan ọkan[4][5].

Ẹkọ[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ruehl lọsi collegi ti New Rochelle ti ó si kàwè ja pẹlú BA lori èdè gẹẹsi ni ọdun 1969[6].

Ami Ẹyẹ ati Idanilọla[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ọdun Àkọlè Accolade Èsi
1989 Married to the Mob National Society of Film Critics Award, Best Supporting Actress Óṣèrè lóbinrin naa yègè
1991 The Fisher King Boston Society of Film Critics Award, Best Supporting Actress Óṣèrè lóbinrin naa yègè
Lost in Yonkers Drama Desk Award, Outstanding Actress in a Play Óṣèrè lóbinrin naa yègè
The Fisher King Los Angeles Film Critics Association Award, Best Supporting Actress Óṣèrè lóbinrin naa yègè
Lost in Yonkers Tony Award, Best Performance by a Leading Actress in a Play Óṣèrè lóbinrin naa yègè
The Fisher King Venice Film Festival Award, Best Lead Actress Óṣèrè lóbinrin naa yègè
1992 Academy Award, Best Supporting Actress Óṣèrè lóbinrin naa yègè
American Comedy Award, Funniest Supporting Actress in a Motion Picture Óṣèrè lóbinrin naa yègè
Chicago Film Critics Association Award, Best Supporting Actor Óṣèrè lóbinrin naa yègè
Dallas-Fort Worth Film Critics Association Award, Best Supporting Actress Óṣèrè lóbinrin naa yègè
Golden Globe Award, Best Supporting Actress in a Motion Picture Óṣèrè lóbinrin naa yègè
Saturn Award, Best Supporting Actress Óṣèrè lóbinrin naa yègè
1993 Boston Film Festival Award, Film Excellence award Óṣèrè lóbinrin naa yègè
1995 Indictment: The McMartin Trial CableACE Award, Best Actress in a Movie or Miniseries Wọn yan
The Rose Tattoo Drama Desk Award, Outstanding Actress in a Play Wọn yan
The Shadow Box Tony Award, Best Performance by a Featured Actress in a Play Wọn yan
2002 The Goat, or Who Is Sylvia? Tony Award, Best Performance by a Leading Actress in a Play Wọn yan
2006 Mom at Sixteen Prism Award, Performance in a Television Movie or Miniseries Wọn yan
2007 A Girl Like Me: The Gwen Araujo Story Imagen Foundation Award, Best Actress - Television Wọn yan

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]