Renée Zellweger
Renée Zellweger | |
---|---|
Zellweger at the 60th Berlin International Film Festival in 2010 | |
Ọjọ́ìbí | Renée Kathleen Zellweger 25 Oṣù Kẹrin 1969 Katy, Texas, U.S. |
Ẹ̀kọ́ | University of Texas at Austin |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 1992–present |
Olólùfẹ́ | |
Alábàálòpọ̀ | Doyle Bramhall II (2012–2019) |
Awards | Full list |
Renée Kathleen Zellweger[1][2] ( /rəˈneɪ ˈzɛlwɛɡər/; ọjọ́-ìbí osu kerin ojo kaarundinlogbon, 1969) jẹ́ gbajúmọ̀ ọ̀ṣèrébìnri ọmọ Amẹ́ríkà tí ó ti gba àmìn-ẹ̀yẹ Ebun Akademi gẹ́gẹ́ bí amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ òṣèrébìnri tó dára jùlọ.
Wọ́n bíi ní ìlú Texas ní Zellweger, ó sìn kàwé gboyè nínú ìmọ̀ Lítíréṣọ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì, English literature ní University of Texas at Austin. Ní ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ rẹ̀, ó gbìyànjú láti kàwé gboyè nínú imọ̀ oníròyìn. Ṣùgbọ́n èyí yí padà nígbà tí ó kópa nínú eré orí ìtàgé ràǹpẹ̀ kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Dazed and Confused ní ilé-ìwé rẹ̀ lọ́dún 1993. Bẹ́ẹ̀ náà ló kópa nínú àwọn eré-ìtàgé tí àkọ́lé wọn ń jẹ́;Reality Bites àti “Love and a .45” lọ́dún 1994. Àwọn ipa pàtàkì tí ó kó nínú àwọn eré wọ̀nyí ló fi kópa nínú sinimá rẹ̀ àkọ́kọ́ tí wọ́n pè ní Texas Chainsaw Massacre: The Next Generation tí slasher film ṣe lọ́dún 1994. Ó di gbajúmọ̀ ìlúmọ̀ọ́ká nínú ipa tí ó kó nínú eré ìfẹ́ adẹ́rìnínpòṣónú tí wọ́n pè ní Jerry Maguire lọ́dún 1996, eré orí-ìtàgé, One True Thing lọ́dún 1998, àti eré adẹ́rìnínpòṣónú adúláwò Nurse Betty lọ́dún 2000, tí ó sìn gbàmì ẹ̀yẹ Golden Globe Award.[3]
Àtẹ àtòjọ àwọn sinimá rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Sinimá àkálẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Sinimá orí tẹlifíṣàn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year | Title | Role | Notes |
---|---|---|---|
1992 | A Taste for Killing | Mary Lou | Television film |
1993 | Murder in the Heartland | Barbara Von Busch | Miniseries; uncredited |
1994 | Shake, Rattle and Rock! | Susan Doyle | Television film |
2001 | King of the Hill | Tammy Duvall (voice) | Episode: "Ho, Yeah!" |
2008 | Living Proof | N/A | Television film; executive producer |
2019 | What/If | Anne Montgomery | Main cast |
2022 | The Thing About Pam | Pam Hupp | Limited series; also executive producer |
Orin
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Chicago: Music from the Miramax Motion Picture lọ́dun 2002
- Judy lọ́dún 2019
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Magazine, Editors of Time (2007-11-27). Time: Almanac 2008. ISBN 9781933821214. https://books.google.com/?id=dRIRAQAAMAAJ&q=%22Ren%C3%A9e+Kathleen+Zellweger%22&dq=%22Ren%C3%A9e+Kathleen+Zellweger%22.
- ↑ https://www.familysearch.org/ark:/61903/1:1:VDR9-CXB
- ↑ "Profile - Renée Zellweger and Ewan McGregor". The Seattle Times. January 3, 2007. http://www.seattletimes.com/entertainment/profile-rene-zellweger-and-ewan-mcgregor-miss-potter-co-stars/.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |