Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Berkelium, 97BkBerkelium |
---|
Pípè | |
---|
Ìhànsójú | silvery |
---|
nọ́mbà ìsújọ | [247] |
---|
Berkelium ní orí tábìlì àyè |
---|
|
Nọ́mbà átọ̀mù (Z) | 97 |
---|
Ẹgbẹ́ | group n/a |
---|
Àyè | àyè 7 |
---|
Àdìpọ̀ | Àdìpọ̀-f |
---|
Ẹ̀ka ẹ́límẹ́ntì | Actinide |
---|
Ìtò ẹ̀lẹ́ktrọ́nù | [Rn] 5f9 7s2 |
---|
Iye ẹ̀lẹ́ktrọ́nù lórí ìpele kọ̀ọ̀kan | 2, 8, 18, 32, 27, 8, 2 |
---|
Àwọn ohun ìní ara |
---|
Ìfarahàn at STP | solid |
---|
Ìgbà ìyọ́ | (beta) 1259 K (986 °C, 1807 °F) |
---|
Kíki (near r.t.) | (alpha) 14.78 g/cm3 (beta) 13.25 g/cm3 |
---|
Atomic properties |
---|
Oxidation states | +2, +3, +4, +5[1] |
---|
Electronegativity | Pauling scale: 1.3 |
---|
Atomic radius | empirical: 170 pm |
---|
Spectral lines of berkelium |
Other properties |
---|
Natural occurrence | synthetic |
---|
Crystal structure | hexagonal close-packed (hcp) |
---|
Thermal conductivity | 10 W/(m·K) |
---|
Magnetic ordering | no data |
---|
CAS Number | 7440-40-6 |
---|
Main isotopes of berkelium |
---|
|
Àdàkọ:Category-inline | references |
Bẹ́rkẹ́líọ̀m tabi Berkelium je apilese alasopapo to ni ami-idamo Bk ati nomba atomu 97. Gege bi apilese onide alagbararadio ninu eseese aktinidi, berkelium koko je sisopapo nipa didigbolu americium pelu awon igbonwo alpha (awon ioni helium), o si je sisoloruko fun Yunifasiti Kalifornia ni Berkeley. Berkelium ni apilese teyinuraniom karun to je sisopapo.
- ↑ Kovács, Attila; Dau, Phuong D.; Marçalo, Joaquim; Gibson, John K. (2018). "Pentavalent Curium, Berkelium, and Californium in Nitrate Complexes: Extending Actinide Chemistry and Oxidation States". Inorg. Chem. (American Chemical Society) 57 (15): 9453–9467. doi:10.1021/acs.inorgchem.8b01450. PMID 30040397.