Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Californium, 98CfCalifornium |
---|
Pípè | /ˌkælᵻˈfɔːrniəm/ (KAL-ə-FOR-nee-əm) |
---|
Ìhànsójú | silvery |
---|
nọ́mbà ìsújọ | [251] |
---|
Californium ní orí tábìlì àyè |
---|
|
Nọ́mbà átọ̀mù (Z) | 98 |
---|
Ẹgbẹ́ | group n/a |
---|
Àyè | àyè 7 |
---|
Àdìpọ̀ | Àdìpọ̀-f |
---|
Ẹ̀ka ẹ́límẹ́ntì | Actinide |
---|
Ìtò ẹ̀lẹ́ktrọ́nù | [Rn] 5f10 7s2 |
---|
Iye ẹ̀lẹ́ktrọ́nù lórí ìpele kọ̀ọ̀kan | 2, 8, 18, 32, 28, 8, 2 |
---|
Àwọn ohun ìní ara |
---|
Ìfarahàn at STP | solid |
---|
Ìgbà ìyọ́ | 1173 K (900 °C, 1652 °F) |
---|
Ígbà ìhó | 1743 K (1470 °C, 2678 °F) |
---|
Kíki (near r.t.) | 15.1 g/cm3 |
---|
Atomic properties |
---|
Oxidation states | +2, +3, +4, +5[3] |
---|
Electronegativity | Pauling scale: 1.3 |
---|
Spectral lines of californium |
Other properties |
---|
Natural occurrence | synthetic |
---|
CAS Number | 7440-71-3 |
---|
Main isotopes of californium |
---|
|
Àdàkọ:Category-inline | references |
Kalifọ́rníọ̀m tabi Californium je apilese kemika onide alagbaradio to ni ami-idamo Cf ati nomba atomu 98. Apilese yi koko je mimuwaye ni 1950 nipa didigbolu curium pelu awon igbonwo alpha (awon ioni helium) ni Yunifasiti Kalifornia ni Berkeley. Ohun ni apilese teyinuraniom kefa to je sisopapo. Californium ni ikan ninu awon apilese isulopo atomu gigajulo to je mimuwaye ni iye to se e won. O je sisoloruko fun ipinle ati yunifasiti Kalifornia.
- ↑ Kovács, Attila; Dau, Phuong D.; Marçalo, Joaquim; Gibson, John K. (2018). "Pentavalent Curium, Berkelium, and Californium in Nitrate Complexes: Extending Actinide Chemistry and Oxidation States". Inorg. Chem. (American Chemical Society) 57 (15): 9453–9467. doi:10.1021/acs.inorgchem.8b01450. PMID 30040397.