Alumíníọ̀mù

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Alumíníọ̀mù
13Al
B

Al

Ga
magnésíọ̀mùalumíníọ̀mùsílíkọ́nù
Ìhànsójú
silvery gray metallic


Spectral lines of aluminium
Àwọn ìdámọ́ wíwọ́pọ̀
Orúkọ, àmì-ìdámọ́, nọ́mbà alumíníọ̀mù, Al, 13
Ìpèlóhùn UK /ˌæljʉˈmɪniəm/
AL-ew-MIN-ee-əm;

US /əˈljmɪnəm/
ə-LEW-mi-nəm

Ẹ̀ka ẹ́límẹ̀nti other metal
Ẹgbẹ́, àsìkò, àdìpò 133, p
Ìwúwo átọ́mù 26.9815386(13)
Ìtòléra ẹ̀lẹ́ktrónì [Ne] 3s2 3p1
2, 8, 3
Electron shells of aluminium (2, 8, 3)
Ìtàn
Ìwárí Hans Christian Ørsted[1] (1825)
Ìyàsọ́tọ̀ àkọ́kọ́ Friedrich Wöhler[2] (1827)
Named by Humphry Davy (1808)
Physical properties
Phase solid
Density (near r.t.) 2.70 g·cm−3
Liquid density at m.p. 2.375 g·cm−3
Melting point 933.47 K, 660.32 °C, 1220.58 °F
Boiling point 2792 K, 2519 °C, 4566 °F
Heat of fusion 10.71 kJ·mol−1
Heat of vaporization 294.0 kJ·mol−1
Molar heat capacity 24.200 J·mol−1·K−1
Vapor pressure
P (Pa) 1 10 100 1 k 10 k 100 k
at T (K) 1482 1632 1817 2054 2364 2790
Atomic properties
Oxidation states 3, 2[3], 1[4]
(amphoteric oxide)
Electronegativity 1.61 (Pauling scale)
Ionization energies
(more)
1st: 577.5 kJ·mol−1
2nd: 1816.7 kJ·mol−1
3rd: 2744.8 kJ·mol−1
Atomic radius 143 pm
Covalent radius 121±4 pm
Van der Waals radius 184 pm
Miscellanea
Crystal structure face-centered cubic
Alumíníọ̀mù has a face-centered cubic crystal structure
Magnetic ordering paramagnetic[5]
Electrical resistivity (20 °C) 28.2 nΩ·m
Thermal conductivity 237 W·m−1·K−1
Thermal expansion (25 °C) 23.1 µm·m−1·K−1
Speed of sound (thin rod) (r.t.) (rolled) 5,000 m·s−1
Young's modulus 70 GPa
Shear modulus 26 GPa
Bulk modulus 76 GPa
Poisson ratio 0.35
Mohs hardness 2.75
Vickers hardness 167 MPa
Brinell hardness 245 MPa
CAS registry number 7429-90-5
Àwọn ísótòpù dídúró jùlọ
Main article: Àwọn ísótòpù alumíníọ̀mù
iso NA half-life DM DE (MeV) DP
26Al trace 7.17×105 yr β+ 1.17 26Mg
ε - 26Mg
γ 1.8086 -
27Al 100% 27Al is stable with 14 neutrons
· r

Alumíníọ̀mù (UK: /ˌæljʊˈmɪniəm/  (Speaker Icon.svg listen) a-lew-MIN-ee-əm[6]) tabi aluminomu (US: /əˈluːmɪnəm/  (Speaker Icon.svg listen); e wo spelling labe) je apilese kemika kan ninu adipo boron to je funfun bi fadaka to se mo. O ni ami-idamo Al ati nomba atomu 13. Ko le yo ninu omi fun ra ara re. Aluminiomu je onide to po repetejulo ninu igbele Aye, ati iketa to po repetejulo nibe leyin oksijini ati silikoni. Ohun ni o je bi 8% bi iwuwo oju ile Aye. Aluminiomu ndarapomora mo awon kemika yioku kiakia gidigidi nitorie ko le da wa fun ra re gege bi onide. Bibeeko, a le ri ni didapo mo orisirisi awon alumoni bi 270.[7] Orisun aluminiomu ni adalu irin bauxite.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Bentor, Y. (12 February 2009). "Periodic Table: Aluminum". ChemicalElements.com. Retrieved 2012-03-06. 
  2. Wöhler, F. (1827). "Űber das Aluminium". Annalen der Physik und Chemie 11: 146–161. 
  3. Aluminium monoxide
  4. Aluminium iodide
  5. Lide, D. R. (2000). "Magnetic susceptibility of the elements and inorganic compounds". CRC Handbook of Chemistry and Physics (81st ed.). CRC Press. ISBN 0849304814. http://www-d0.fnal.gov/hardware/cal/lvps_info/engineering/elementmagn.pdf. 
  6. http://www.howjsay.com/index.php?word=aluminium
  7. Bassam Z. Shakhashiri. "Chemical of the Week: Aluminum". Science is Fun. Retrieved 2007-08-28.