Pòtásíọ̀mù

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Pòtásíọ̀mù
19K
Na

K

Rb
árgọ̀nùpòtásíọ̀mùcalcium
Ìhànsójú
silvery gray


Potassium pearls under paraffin oil. The large pearl measures 0.5 cm. Below: spectral lines of potassium
Àwọn ìdámọ́ wíwọ́pọ̀
Orúkọ, àmì-ìdámọ́, nọ́mbà pòtásíọ̀mù, K, 19
Ìpèlóhùn /pɵˈtæsiəm/ po-TAS-ee-əm
Ẹ̀ka ẹ́límẹ̀nti mẹ́tàlì álkálì
Ẹgbẹ́, àsìkò, àdìpò 14, s
Ìwúwo átọ́mù 39.0983(1)
Ìtòléra ẹ̀lẹ́ktrónì [Ar] 4s1
2, 8, 8, 1
Ìtàn
Ìwárí Humphry Davy (1807)
Ìyàsọ́tọ̀ àkọ́kọ́ Humphry Davy (1807)
Physical properties
Phase solid
Density (near r.t.) 0.862 g·cm−3
Liquid density at m.p. 0.828 g·cm−3
Melting point 336.7 K, 63.5 °C, 146.3 °F
Boiling point 1032 K, 759 °C, 1398 °F
Critical point 2223 K, 16[1] MPa
Heat of fusion 2.33 kJ·mol−1
Heat of vaporization 76.9 kJ·mol−1
Molar heat capacity 29.6 J·mol−1·K−1
Atomic properties
Oxidation states +1
(strongly basic oxide)
Electronegativity 0.82 (Pauling scale)
Ionization energies
(more)
1st: 418.8 kJ·mol−1
2nd: 3052 kJ·mol−1
3rd: 4420 kJ·mol−1
Atomic radius 227 pm
Covalent radius 203±12 pm
Van der Waals radius 275 pm
Miscellanea
Crystal structure body-centered cubic
Pòtásíọ̀mù has a body-centered cubic crystal structure
Magnetic ordering paramagnetic[2]
Electrical resistivity (20 °C) 72 nΩ·m
Thermal conductivity 102.5 W·m−1·K−1
Thermal expansion (25 °C) 83.3 µm·m−1·K−1
Speed of sound (thin rod) (20 °C) 2000 m·s−1
Young's modulus 3.53 GPa
Shear modulus 1.3 GPa
Bulk modulus 3.1 GPa
Mohs hardness 0.4
Brinell hardness 0.363 MPa
CAS registry number 7440-09-7
Àwọn ísótòpù dídúró jùlọ
Main article: Àwọn ísótòpù pòtásíọ̀mù
iso NA half-life DM DE (MeV) DP
39K 93.26% 39K is stable with 20 neutrons
40K 0.012% 1.248(3)×109 y β 1.311 40Ca
ε 1.505 40Ar
β+ 1.505 40Ar
41K 6.73% 41K is stable with 22 neutrons
· r

Pòtásíọ̀mù je elimenti kemika kan to ni ami-idamo K (latinu ede Latini Tuntun fun kalium) ati nomba atomu 19. Potasiomu je metali alkali alawo fadaka-funfun didelowo to undi oksidi kiakia ninu afefe to si yirapo mo omi gigdigidi, eyi unfa igbona jade to sana si haidrojin to unbujade ninu iyirapo na, o si unjo bi awo lilaki.

Nitoripe potasiomu ati sodiomu jora ni isese kemika won, awon iyọ̀ won ko se e ya sira won nibere. O di odun 1702 ko to di pe won fun ra pe opo elimenti wa ninu awon iyo won,[3] eyi je mimufidaju ni odun 1807 nigba ti potasiomu ati sodiomu je yiya sotooto latinu awon iyọ̀ otooto pelu elektrolisisi. Potasiomu inu adaye wa ninu awon iyọ̀ oniioni nikan. Nitori eyi, o wa ninu omi okun (to je 0.04% potasiomu pelu iwuwo[4][5]), o si je apa opo awon alumoni.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Àdàkọ:RubberBible92nd
  2. Magnetic susceptibility of the elements and inorganic compounds, in Àdàkọ:RubberBible86th
  3. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named 1702Suspect
  4. Webb, D. A. (April 1939). "The Sodium and Potassium Content of Sea Water". The Journal of Experimental Biology: 183. http://jeb.biologists.org/content/16/2/178.full.pdf. 
  5. Anthoni, J. (2006). "Detailed composition of seawater at 3.5% salinity". seafriends.org.nz. Retrieved 23 September 2011.