Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Pòtásíọ̀mù, 19 K Potassium pearls (in paraffin oil, ~5 mm each)
Pòtásíọ̀mù Pípè / p ə ˈ t æ s i ə m / (pə-TAS -ee-əm ) Ìhànsójú silvery gray Ìwúwo átọ̀mù A r, std (K) 39.0983(1) [ 1] Pòtásíọ̀mù ní orí tábìlì àyè
Nọ́mbà átọ̀mù (Z ) 19 Ẹgbẹ́ group 1 : H and alkali metalsÀyè àyè 4 Àdìpọ̀ Àdìpọ̀-s Ẹ̀ka ẹ́límẹ́ntì Alkali metal Ìtò ẹ̀lẹ́ktrọ́nù [Ar ] 4s1 Iye ẹ̀lẹ́ktrọ́nù lórí ìpele kọ̀ọ̀kan 2, 8, 8, 1 Àwọn ohun ìní ara Ìfarahàn at STP solid Ìgbà ìyọ́ 336.7 K (63.5 °C, 146.3 °F) Ígbà ìhó 1032 K (759 °C, 1398 °F) Kíki (near r.t. ) 0.862 g/cm3 when liquid (at m.p. ) 0.828 g/cm3 Critical point 2223 K, 16[ 2] MPa Heat of fusion 2.33 kJ/mol Heat of 76.9 kJ/mol Molar heat capacity 29.6 J/(mol·K) Atomic properties Oxidation states −1, +1 Àdàkọ:Infobox element/symbol-to-oxidation-state/comment Electronegativity Pauling scale: 0.82 energies Atomic radius empirical: 227 pm Covalent radius 203±12 pm Van der Waals radius 275 pm Color lines in a spectral range Spectral lines of pòtásíọ̀mùOther properties Natural occurrence primordial Crystal structure (bcc) Speed of sound thin rod 2000 m/s (at 20 °C) Thermal expansion 83.3 µm/(m·K) (at 25 °C) Thermal conductivity 102.5 W/(m·K) Electrical resistivity 72 n Ω·m (at 20 °C) Magnetic ordering paramagnetic[ 3] Young's modulus 3.53 GPa Shear modulus 1.3 GPa Bulk modulus 3.1 GPa Mohs hardness 0.4 Brinell hardness 0.363 MPa CAS Number 7440-09-7 History Discovery Humphry Davy (1807) First isolation Humphry Davy (1807) Main isotopes of pòtásíọ̀mù
Àdàkọ:Category-inline | references
Pòtásíọ̀mù je elimenti kemika kan to ni ami-idamo K (latinu ede Latini Tuntun fun kalium ) ati nomba atomu 19. Potasiomu je metali alkali alawo fadaka-funfun didelowo to undi oksidi kiakia ninu afefe to si yirapo mo omi gigdigidi, eyi unfa igbona jade to sana si haidrojin to unbujade ninu iyirapo na, o si unjo bi awo lilaki .
Nitoripe potasiomu ati sodiomu jora ni isese kemika won, awon iyọ̀ won ko se e ya sira won nibere. O di odun 1702 ko to di pe won fun ra pe opo elimenti wa ninu awon iyo won,[ 4] eyi je mimufidaju ni odun 1807 nigba ti potasiomu ati sodiomu je yiya sotooto latinu awon iyọ̀ otooto pelu elektrolisisi . Potasiomu inu adaye wa ninu awon iyọ̀ oniioni nikan. Nitori eyi, o wa ninu omi okun (to je 0.04% potasiomu pelu iwuwo[ 5] [ 6] ), o si je apa opo awon alumoni .
↑ Meija, Juris; Coplen, Tyler B.; Berglund, Michael; Brand, Willi A.; De Bièvre, Paul; Gröning, Manfred; Holden, Norman E.; Irrgeher, Johanna et al. (2016). "Atomic weights of the elements 2013 (IUPAC Technical Report)". Pure and Applied Chemistry 88 (3): 265–91. doi :10.1515/pac-2015-0305 .
↑ Àdàkọ:RubberBible92nd
↑ Magnetic susceptibility of the elements and inorganic compounds , in Àdàkọ:RubberBible86th
↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref>
tag; no text was provided for refs named 1702Suspect
↑ Webb, D. A. (April 1939). "The Sodium and Potassium Content of Sea Water" . The Journal of Experimental Biology : 183. Archived from the original on 2023-02-28. https://web.archive.org/web/20230228192154/https://journals.biologists.com/jeb/article-pdf/16/2/178/2199202/jexbio_16_2_178.pdf . Retrieved 2023-03-02 .
↑ Anthoni, J. (2006). "Detailed composition of seawater at 3.5% salinity" . seafriends.org.nz . Retrieved 23 September 2011 .