Árgọ̀nù

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Argon)
Jump to navigation Jump to search
Árgọ̀nù
18Ar
Ne

Ar

Kr
klorínìárgọ̀nùpotassium
Ìhànsójú
colorless gas exhibiting a lilac/violet glow when placed in a high voltage electric field
Vial containing a violet glowing gas

Spectral lines of argon
Àwọn ìdámọ́ wíwọ́pọ̀
Orúkọ, àmì-ìdámọ́, nọ́mbà árgọ̀nù, Ar, 18
Ìpèlóhùn /ˈɑrɡɒn/
Ẹ̀ka ẹ́límẹ̀nti noble gases
Ẹgbẹ́, àsìkò, àdìpò 183, p
Ìwúwo átọ́mù 39.948(1)
Ìtòléra ẹ̀lẹ́ktrónì [Ne] 3s2 3p6
2, 8, 8
Electron shells of argon (2, 8, 8)
Ìtàn
Ìwárí Lord Rayleigh and William Ramsay (1894)
Ìyàsọ́tọ̀ àkọ́kọ́ Lord Rayleigh and William Ramsay (1894)
Physical properties
Phase gas
Density (0 °C, 101.325 kPa)
1.784 g/L
Liquid density at b.p. 1.40 g·cm−3
Melting point 83.80 K, −189.35 °C, −308.83 °F
Boiling point 87.30 K, −185.85 °C, −302.53 °F
Triple point 83.8058 K (-189°C), 69 kPa
Critical point 150.87 K, 4.898 MPa
Heat of fusion 1.18 kJ·mol−1
Heat of vaporization 6.43 kJ·mol−1
Molar heat capacity 5R/2 = 20.786 J·mol−1·K−1
Vapor pressure
P (Pa) 1 10 100 1 k 10 k 100 k
at T (K)   47 53 61 71 87
Atomic properties
Oxidation states 0
Electronegativity no data (Pauling scale)
Ionization energies
(more)
1st: 1520.6 kJ·mol−1
2nd: 2665.8 kJ·mol−1
3rd: 3931 kJ·mol−1
Covalent radius 106±10 pm
Van der Waals radius 188 pm
Miscellanea
Crystal structure face-centered cubic
Árgọ̀nù has a face-centered cubic crystal structure
Magnetic ordering diamagnetic[1]
Thermal conductivity 17.72x10-3  W·m−1·K−1
Speed of sound (gas, 27 °C) 323 m·s−1
CAS registry number 7440–37–1
Àwọn ísótòpù dídúró jùlọ
Main article: Àwọn ísótòpù árgọ̀nù
iso NA half-life DM DE (MeV) DP
36Ar 0.337% 36Ar is stable with 18 neutrons
37Ar syn 35 d ε 0.813 37Cl
38Ar 0.063% 38Ar is stable with 20 neutrons
39Ar trace 269 y β 0.565 39K
40Ar 99.600% 40Ar is stable with 22 neutrons
41Ar syn 109.34 min β 2.49 41K
42Ar syn 32.9 y β 0.600 42K
· r

Árgọ̀nù je elimenti kemika kan to ni ami-idamo Ar ati nomba atomu 18. O wa ninu egbe 18 (awon efuufu abiire) lori tabili idasiko awon elimenti. Argonu ni efuufu keta to wopo julo ninu afefeayika Aye, ni 0.93% (9,300 ppm), eyi so di eyi to repete ni ona bi 23.8 bi ti efuufu inu afefeayika tto wopo julo to tele, eyun dioksidi karbonu (390 ppm), ati to po repete ni ona to to 500 bi ti efuufu abiire keji to wopo, eyun neonu (18 ppm). Bi gbogbo argonu yi lo je argonu-40 radiogeniki to wa lati ituka potassium-40 ninu igbele Aye. Ni agbalaaye, argonu-36 ni isotopu argonu to wopo julo, nitoripe o je isotopu argonu to je dida pelu stellar ikojonukleu irawo ninu awon supanofa (awon irawo akomonamona).


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Magnetic susceptibility of the elements and inorganic compounds, in Handbook of Chemistry and Physics 81st edition, CRC press.