Bẹ́rílíọ̀mù

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Bẹ́rílíọ̀mù
4Be
-

Be

Mg
lítíọ̀mù‎bẹ́rílíọ̀mùbórọ̀nù
Ìhànsójú
white-gray metallic
Àwọn ìdámọ́ wíwọ́pọ̀
Orúkọ, àmì-ìdámọ́, nọ́mbà bẹ́rílíọ̀mù, Be, 4
Ìpèlóhùn /bəˈrɪliəm/ bə-RIL-ee-əm
Ẹ̀ka ẹ́límẹ̀nti mẹ́tàlì alkalínì ilẹ̀
Ẹgbẹ́, àsìkò, àdìpò 22, s
Ìwúwo átọ́mù 9.012182(3)
Ìtòléra ẹ̀lẹ́ktrónì [He] 2s2
2, 2
Electron shells of beryllium (2, 2)
Ìtàn
Ìwárí Louis Nicolas Vauquelin (1797)
Ìyàsọ́tọ̀ àkọ́kọ́ Friedrich Wöhler & Antoine Bussy (1828)
Physical properties
Phase solid
Density (near r.t.) 1.85 g·cm−3
Liquid density at m.p. 1.690 g·cm−3
Melting point 1560 K, 1287 °C, 2349 °F
Boiling point 2742 K, 2469 °C, 4476 °F
Heat of fusion 12.2 kJ·mol−1
Heat of vaporization 297 kJ·mol−1
Molar heat capacity 16.443 J·mol−1·K−1
Vapor pressure
P (Pa) 1 10 100 1 k 10 k 100 k
at T (K) 1462 1608 1791 2023 2327 2742
Atomic properties
Oxidation states 2, 1[1]
(amphoteric oxide)
Electronegativity 1.57 (Pauling scale)
Ionization energies
(more)
1st: 899.5 kJ·mol−1
2nd: 1757.1 kJ·mol−1
3rd: 14848.7 kJ·mol−1
Atomic radius 112 pm
Covalent radius 96±3 pm
Van der Waals radius 153 pm
Miscellanea
Crystal structure hexagonal
Bẹ́rílíọ̀mù has a hexagonal crystal structure
Magnetic ordering diamagnetic
Electrical resistivity (20 °C) 36 nΩ·m
Thermal conductivity 200 W·m−1·K−1
Thermal expansion (25 °C) 11.3 µm·m−1·K−1
Speed of sound (thin rod) (r.t.) 12870[2] m·s−1
Young's modulus 287 GPa
Shear modulus 132 GPa
Bulk modulus 130 GPa
Poisson ratio 0.032
Mohs hardness 5.5
Vickers hardness 1670 MPa
Brinell hardness 600 MPa
CAS registry number 7440-41-7
Àwọn ísótòpù dídúró jùlọ
Main article: Àwọn ísótòpù bẹ́rílíọ̀mù
iso NA half-life DM DE (MeV) DP
7Be trace 53.12 d ε 0.862 7Li
γ 0.477 -
9Be 100% 9Be is stable with 5 neutrons
10Be trace 1.36×106 y β 0.556 10B
· r

Bẹ́rílíọ̀mù ni ẹ́límẹ̀ntì kẹ́míkà tó ní àmì-ìdámọ̀ Be àti nọ́mbà átọ̀mù 4. Nítorípé bẹ́rílíọ̀mù yíówù tó bá jẹ́ kíkódájọpọ̀ ní inú àwọn ìràwọ̀ kì í pẹ́ tí ó fi túká, nítoríẹ̀ ó jẹ́ ẹ́límẹ̀ntì tó sọ̀wọ́n gidigidi ní àgbàlá-ayé ati ní Ilẹ̀-Ayé. Ó jẹ́ ẹ́límẹ̀ntì olójú-ìsopọ̀ mẹ́jì tó ṣe é rí nínú ìdàpọ̀ mọ́ àwọn ẹ́límẹ̀ntì míràn nìkan nínú àwọn àlúmọ́nì. Àwọn òkúta iyebíye pàtàkì kan tí wọ́n ní bẹ́rílíọ̀mù nínú ni bẹ́rìlì (òkúta odò, ẹ́míràldì) àti bẹ́rìlìoníwúrà. Tó bá dá wà, ó jẹ́ ẹ́límẹ̀ntì mẹ́tàlì alkalínì ilẹ̀ tó ní àwọ̀ irin-idẹ, tó lágbára, fífúyẹ́ àti rírún wẹ́wẹ́.

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Beryllium: Beryllium(I) Hydride compound data" (PDF). bernath.uwaterloo.ca. Retrieved 2007-12-10. 
  2. Àdàkọ:RubberBible86th