Sódíọ̀mù

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Sodiomu)
Jump to navigation Jump to search

Sódíọ̀mù
11Na
Li

Na

K
nẹ́ọ̀nùsódíọ̀mùmagnésíọ̀mù
Ìhànsójú
silvery white metallic


Spectral lines of sodium
Àwọn ìdámọ́ wíwọ́pọ̀
Orúkọ, àmì-ìdámọ́, nọ́mbà sódíọ̀mù, Na, 11
Ìpèlóhùn /ˈsdiəm/ SOH-dee-əm
Ẹ̀ka ẹ́límẹ̀nti mẹ́tàlì álkálì
Ẹgbẹ́, àsìkò, àdìpò 13, s
Ìwúwo átọ́mù 22.98976928(2)
Ìtòléra ẹ̀lẹ́ktrónì [Ne] 3s1
2,8,1
Electron shells of sodium (2,8,1)
Ìtàn
Ìwárí Humphry Davy (1807)
Ìyàsọ́tọ̀ àkọ́kọ́ Humphry Davy (1807)
Physical properties
Phase solid
Density (near r.t.) 0.968 g·cm−3
Liquid density at m.p. 0.927 g·cm−3
Melting point 370.87 K, 97.72 °C, 207.9 °F
Boiling point 1156 K, 883 °C, 1621 °F
Critical point (extrapolated)
2573 K, 35 MPa
Heat of fusion 2.60 kJ·mol−1
Heat of vaporization 97.42 kJ·mol−1
Molar heat capacity 28.230 J·mol−1·K−1
Vapor pressure
P (Pa) 1 10 100 1 k 10 k 100 k
at T (K) 554 617 697 802 946 1153
Atomic properties
Oxidation states +1, -1
(strongly basic oxide)
Electronegativity 0.93 (Pauling scale)
Ionization energies
(more)
1st: 495.8 kJ·mol−1
2nd: 4562 kJ·mol−1
3rd: 6910.3 kJ·mol−1
Atomic radius 186 pm
Covalent radius 166±9 pm
Van der Waals radius 227 pm
Miscellanea
Crystal structure body-centered cubic
Sódíọ̀mù has a body-centered cubic crystal structure
Magnetic ordering paramagnetic
Electrical resistivity (20 °C) 47.7 nΩ·m
Thermal conductivity 142 W·m−1·K−1
Thermal expansion (25 °C) 71 µm·m−1·K−1
Speed of sound (thin rod) (20 °C) 3200 m·s−1
Young's modulus 10 GPa
Shear modulus 3.3 GPa
Bulk modulus 6.3 GPa
Mohs hardness 0.5
Brinell hardness 0.69 MPa
CAS registry number 7440-23-5
Àwọn ísótòpù dídúró jùlọ
Main article: Àwọn ísótòpù sódíọ̀mù
iso NA half-life DM DE (MeV) DP

Àdàkọ:Infobox element/isotopes decay3 (2 2 1)

23Na 100% 23Na is stable with 12 neutrons
· r

Sódíọ̀mù jẹ́ ẹ́límẹ̀ntì kẹ́míkà kan tó ní àmí-ìdámọ̀ Na (láti Látìnì: [natrium] error: {{lang}}: text has italic markup (help)) lórí tábìlì ìdásìkò àwọn ẹ́límẹ̀ntì àti nọ́mbà átọ̀mù 11. O je metali riro, alawo fadaka funfun to untete sedarapo, beesini o je ikan ninu awon metali alkali; Isotopu re nikan to fesemule ni 23Na. Metali yi ko da wa fun ra ara re nikan ni idaye, sugbon be o wa ni adapo; o koko je pipinsoto latowo Humphry Davy ni 1807 pelu elektrolisisi haidroksidi sodiumu. Sodiomu ni elimenti ikefa to gbale julo ninu ipele-igbele Aye, o si wa ninu opo awon alumoni bi feldspar, sodalaiti ati iyo okuta. Opo awon iyo sodiomu ni won je yiyo somi daada, be sini sodiomu won ti je yiyo jade latowo omi to fi je pe kloridi ati sodiomu ni awon elimenti to wopo ni wuwo ninu awon omi okun Ile-Aye.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]