Ayo Adeseun

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Ayoade Ademola Adeseun
Aṣojú àárín Ọ̀yọ́ ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà
Lọ́wọ́
Ó bọ́ sí orí àga
Oṣù karún, Ọdún 2011
Asíwájú Teslim Folarin
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́
Ìbí 1 Oṣù Kínní 1953 (1953-01-01) (ọmọ ọdún 64)
Ẹgbẹ́ olóṣèlú Action Congress of Nigeria (ACN)

Ayoade Ademola Adeseun (bíi ní Ọjọ́ kínín Oṣù kínín Ọdún 1953) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú ààrín Ọyọ́, ìpínlẹ̀ Ọyọ ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin láti ọdún 2011 sí 2015 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú Action Congress of Nigeria (ACN).[1][2][3]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]