Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Oṣù Kínní
Ọjọ́ 1 Oṣù Kínní: Ojo Ilominira ni Haiti (1804), Sudan (1956) ati Brunei (1984).
- [[]]
- [[]]
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1915 – John Henrik Clarke, olukowe itan ara Amerika (al. 1998)
- 1942 – Alassane Ouattara, former Prime Minister of Ivory Coast
- 1953 – Alpha Blondy, Ivorian reggae singer
- 1969 – Morris Chestnut, American actor
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1748 – Johann Bernoulli, Swiss mathematician (b. 1667)
- 1894 – Heinrich Rudolf Hertz, German physicist (b. 1857)
- 2005 – Shirley Chisholm (foto), oloselu ara Amerika (ib. 1924)
- [[]]
- [[]]
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1920 – Isaac Asimov, olukowe ara Amerika (al. 1992)
- 1940 – S. R. Srinivasa Varadhan, onimoisiro omo India ara Amerika
- 1968 – Cuba Gooding, Jr., osere ara Amerika
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1995 – Siad Barre, Aare ile Somalia (ib. 1919)
- 2016 – Frances Cress Welsing, oniwosan okan ati alakitiyan ara Amerika (ib. 1935)
- 1848 – Joseph Jenkins Roberts is sworn in as the first president of the independent African Republic of Liberia.
- 1961 – The United States severs diplomatic relations with Cuba.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 106 BC – Cicero, Roman statesman and philosopher (al. 43 BC)
- 1892 - J. R. R. Tolkien, olukowe ara Ilegeesi (al. 1973)
- 1901 – Ngô Đình Diệm, South Vietnamese politician (al. 1963)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1875 - Pierre Larousse, French editor (b. 1817)
- [[]]
Ọjọ́ 4 Oṣù Kínní: Ojo Ilominira ni Myanmar (1948); Ojo awon Ogoni
- 1642 – King Charles I of England sends soldiers to arrest members of Parliament, commencing England's slide into civil war.
- 1958 – Sputnik 1 ja sile si Aye lati ojuona-ayipo re.
- 1966 – A military coup takes place in Burkina Faso (nigbana bi Upper Volta), dissolving the National Parliament and leading to a new national constitution
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1643 – Sir Isaac Newton (aworan), English mathematician and natural philosopher (d. 1727)
- 1848 – Katsura Taro, Prime Minister of Japan (d. 1913)
- 1901 – C. L. R. James, Trinidadian writer and journalist (d. 1989)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1960 – Albert Camus, Algerian-born philosopher and Nobel laureate (b. 1913)
- 1961 – Erwin Schrödinger, Austrian physicist and Nobel laureate (b. 1887)
- 1965 – T. S. Eliot, American-born British Nobel laureate (b. 1888)
- [[]]
- [[]]
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1928 – Walter Mondale, olóṣẹ̀lú ará Amẹ́ríkà
- 1932 – Umberto Eco, olùkọ̀wé ará Itálíà
- 1938 – Ngũgĩ wa Thiong'o, olùkọ̀wé ará Kẹ́nyà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1933 – Calvin Coolidge, Ààrẹ 30k Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà (ib. 1872)
- 1943 – George Washington Carver, olùkọ́ni ará Amẹ́ríkà (ib. 1864)
- 1970 – Max Born, aṣefísíksì ọmọ jẹ́máni Brítánì (ib. 1882).
- [[]]
- [[]]
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1944 – Rolf M. Zinkernagel, Swiss immunologist, Nobel laureate
- 1933 – Oleg Makarov, Soviet cosmonaut (d. 2003)
- 1968 – John Singleton, American film director
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1884 – Gregor Johann Mendel, Austrian geneticist (b. 1822)
- 1918 – Georg Cantor, German mathematician (b. 1845)
- 1993 – Dizzy Gillespie, acclaimed jazz trumpet player (b. 1917)
- 1952 – Aare Harry Truman kede pe orile-ede Amerika ti sedagbasoke bombu haidrojin.
- 1993 – Jerry Rawlings di Aare orile-ede Ghana lati bere Igba Oselu Kerin.
- [[]]
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1891 - Zora Neale Hurston (fọ́tò), olukowe ara Amerika (al. 1960)
- 1934 – Tassos Papadopoulos, Aare ile Kipru (al. 2008)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1943 – Nikola Tesla, Serbian-born inventor and electrical engineer (b. 1856)
- [[]]
- 1912 – Ìdásílẹ̀ Kọ́ngrẹ́sì Ọlómọorílẹ̀-èdè Áfríkà (ANC).
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1942 – Stephen Hawking, onímọ̀ físíksì ará Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì.
- 1947 – David Bowie, olórin ará Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì.
- 1967 – R. Kelly, olórin ara Amẹ́ríkà.
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1324 - Marco Polo, viajante veneziano (n. 1254).
- 1642 – Galileo Galilei, Italian astronomer and scientist (b. 1564)
- 1996 – François Mitterrand, President of France (b. 1916)
- [[]]
- [[]]
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1913 – Richard Nixon, 37th President of the United States (al. 1994)
- 1922 – Ahmed Sékou Touré (fọ́tò), President of Guinea (al. 1984)
- 1922 – Har Gobind Khorana, Nobel laureate
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1961 – Emily Greene Balch, American writer, Nobel Peace Prize laureate (ib. 1867)
- 1998 – Kenichi Fukui, Japanese chemist, Nobel Prize in Chemistry laureate (ib. 1918)
- 2014 – Amiri Baraka, olukowe ara Amerika (ib. 1934)
- 49 SK – Juliu Késárì àti àwọ ọmo ogun re gba odò Rúbíkónì kọjá ní ìlòdì sí òfin Rómù, èyí bẹ̀rẹ̀ ogun abẹ́lé.
- 1920 – Àdéhùn Versailles bẹ̀rẹ̀ láti mú òpin bá Ogun Àgbáyé 1k.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1938 – Donald Knuth, aṣesáyẹ́nsì kọ̀mpútà ará Amẹ́ríkà
- 1949 – George Foreman, ajaẹ̀sẹ́ ará Amẹ́ríkà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1778 - Carl Linnaeus, aṣesáyẹ́nsì ará Swídìn
- 1951 – Yoshio Nishina, onímọ̀ físíksì ará Japan (ib. 1890)
- 1957 – Gabriela Mistral, olùkọ̀wé ará Tsílè (ib. 1889)
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1638 – Nicolas Steno (àwòrán), onímọ̀ jẹọ́lọ́jì ará Dẹ́nmárkì (al. 1686).
- 1755 – Alexander Hamilton, olóṣèlú àti ìkan nínú àwọn Baba Afilọ́lẹ̀ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà (al. 1804).
- 1971 – Mary J. Blige, akọrin ará Amẹ́ríkà.
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1928 – Thomas Hardy, olùkọ̀wé ará Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì (ib. 1840).
- 1966 – Lal Bahadur Shastri, Alákóso Àgbà kẹta orílẹ̀-èdè Índíà (ib. 1904).
- 1988 – Isidor Isaac Rabi, onímọ̀ físíksì àti ẹlẹ́bùn Nobel (ib. 1898).
- 1964 – Àwọn aṣágun ní Zanzibar (àsìá), bẹ̀rẹ̀ ìṣọ̀tẹ̀ tó únjẹ́ Ìjídìde Zanzibar, wọ́n sì kéde orílẹ̀òmìnira.
- 2010 – Ìwàrìrì-ilẹ̀ ní Haiti tó ṣelẹ̀ pa àwọn ènìyàn 230,000, ó sì pa ọ̀pọ̀ olúìlú Port-au-Prince run.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1940 – Rasaki Akanni Okoya, onísòwò ará Nàìjíríà
- 1944 – Joe Frazier, ajaese ará Amẹ́ríkà (al. 2011)
- 1948 – Khalid Abdul Muhammad, alakitiyan ará Amẹ́ríkà (al. 2001)
- 1952 – Walter Mosley, olùkọ̀wé ará Amẹ́ríkà.
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1965 – Lorraine Hansberry, olùkọ̀wé ará Amẹ́ríkà (ib. 1930),
- 1983 – Rebop Kwaku Baah, onílù ará Ghánà (ib. 1944).
- 1997 – Charles B. Huggins, ẹlẹ́bùn Nobel nínú Ìwòsàn ará Kánádà (ib. 1901).
- 1898 – Émile Zola ṣe àtẹ̀jáde "J'accuse...!"'(àwòrán), nínú ìwéìròyìn ní Paris láti tú àṣírí Ẹjọ́ Dreyfus.
- 1972 - Ìfipágbàjọba ológun ṣẹlẹ̀ ní Ghánà.
- 1990 – L. Douglas Wilder di ọmọ Áfríkà Amẹ́ríkà àkọ́kọ́ tọ́ jẹ́ dídìbòyàn bíi gómìnà ní USA nígbà tó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ bíi gómìnà ìpínlẹ̀ Virginia.
- 2001 – Ìwàrìrì-ilẹ̀ ní El Salvador pa àwọn ènìyàn 800.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1859 – Kostis Palamas, akọewì ará Gríìsì (al. 1943)
- 1924 – Paul Feyerabend, amòye ará Austria (al. 1994)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1941 – James Joyce, olùkòwé ará Írẹ́lándì (ib. 1882)
- 2010 – Teddy Pendergrass, akọrin R&B ará Amẹ́ríkà (ib. 1950)
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1875 – Albert Schweitzer, ẹlẹ́bùn Nobel ará Jẹ́mánì (al. 1965)
- 1901 – Alfred Tarski, onímọ̀ mathimátíkì ará Pólàndì (al. 1983)
- 1968 – LL Cool J, rapper ati òṣeré ará Amẹ́ríkà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1957 – Humphrey Bogart, òṣeré ará Amẹ́ríkà (ib. 1899)
- 1977 – Anthony Eden, Alákóso Àgbà ilẹ̀ Brítánì (ib. 1897)
- 1978 – Kurt Gödel, onímọ̀ mathimátíkì ará Austríà (ib. 1906)
- 1966 – Ìfipágbàjọba ológun ṣẹlẹ̀ ní Nàìjíríà fún ìgbà àkọ́kọ́.
- 1970 - Ogun Abẹ́lé Nàìjíríà wá sópin
- 2001 – Wikipedia, Wiki ọ̀fẹ́ àkóónú ẹnsiklopẹ́díà bẹ̀rẹ̀ lórí Internet.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1906 – Aristotle Onassis, ọmọ Gríìkì oníṣòwò (al. 1975)
- 1918 – Gamal Abdal Nasser, Ààrẹ ilẹ̀ Egypt (al. 1970)
- 1929 - Martin Luther King, Jr. (fọ́tò)), alákitiyan ará Amẹ́ríkà (al. 1968)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1919 – Rosa Luxemburg, kọ́múnístì ará Jẹ́mámì (ib. 1870)
- 1966 - Abubakar Tafawa Balewa, olóṣèlú ará Nàìjíríà (ib. 1912)
- 1966 - Ahmadu Bello, olóṣèlú ará Nàìjíríà (ib. 1910)
- 1966 - Ladoke Akintola, olóṣèlú ará Nàìjíríà (ib. 1910)
- 2003 – Ọkọ̀-àlọbọ̀ Òfurufú Columbia (fọ́tò) gbéra lọ fún ìránlọṣe STS-107 tí yíò di èyí tó ṣe gbèyìn. Columbia játúká ní ọjọ́ 16 lẹ́yìn náà nígbà tó únpadà wọ Ayé.
- 2006 – Ellen Johnson Sirleaf di Ààrẹ ilẹ̀ Liberia. Òhun ni obìnrin àkọ̀kọ̀ tó jẹ́ dídìbòyàn bíi olórí orílẹ̀-èdè ní Áfríkà.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1901 – Fulgencio Batista, Ààrẹ ilẹ̀ Kúbà (al. 1973)
- 1959 – Sade Adu, ọmọ Yorùbá akọrin ará Brítánì
- 1979 - Aaliyah, akọrin ará Amẹ́ríkà (al. 2001)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1794 – Edward Gibbon, akọ̀wéìtàn ará Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì (ib. 1737)
- 2001 – Laurent-Désiré Kabila, Ààrẹ ilẹ̀ OO Kongo (ib. 1939)
Ọjọ́ 17 Oṣù Kínní: Ọjọ́ Martin Luther King Jr. ní USA
- 2002 – Òkè Nyiragongo tújáde ní Kọ́ngọ 20 kilometres (12 mi) ní àríwá ìlú Goma, ó pa ilé 4,500 run, ó sì sọ àwọn ènìyàn bíi 120,000 di aláìnílé.
- 1991 – Àpapọ̀ ológun tí orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà léwájú gbógun ti Iraq.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1927 – Eartha Kitt, akorin ati òṣeré ará Amẹ́ríkà (al. 2008)
- 1931 – James Earl Jones', òṣeré ará Amẹ́ríkà
- 1942 – Muhammad Ali, ajaẹ̀sẹ́ ará Amẹ́ríkà
- 1964 – Michelle Obama, Ìyáàfin Àkọ́kọ́ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1961 – Patrice Lumumba, Alákóso Àgbà orílẹ̀-èdè Kóngò (ib. 1925)
- 2005 – Zhao Ziyang, Olórí ìjọba ilẹ̀ Ṣáínà (ib. 1919)
- 2002 – Ogun Abẹ́lé Siẹrra Léònè wá sópin.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1689 – Montesquieu, olùkọ̀wé ará Fránsì (al. 1755)
- 1925 – Gilles Deleuze, amòye ará Fránsì (al. 1995)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1878 – Antoine César Becquerel, onímọ̀ físíksì ará Fránsì (ib. 1788)
- 1936 – Rudyard Kipling, olùkọ̀wé ará Brítánì (ib. 1865)
- 2006 – Ọkọ́ ìwáàdí New Horizons gbéra láti NASA lọ fún ìránlọṣe àkọ́kọ́ sí Plútò.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1736 – James Watt, onímọ̀ sáyẹ́nsì ará Skọ́tlándì (al. 1819)
- 1809 – Edgar Allan Poe, olùkọ̀wé ará Amẹ́ríkà (al. 1849)
- 1918 – John H. Johnson (fọ́tò), atẹ̀wéjáde ará Amẹ́ríkà (al. 2005)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1851 – Esteban Echeverría, olùkọ̀wé ará Argentina (ib. 1805)
- 1865 – Pierre-Joseph Proudhon, amòye ará Fránsì (ib. 1809)
- 2009 - Barack Obama di Ààrẹ (àwòrán èdìdí) orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà; òhun ni aláwọ̀dúdú àkọ́kọ́ tó bọ́ sí ipò yí.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1873 – Johannes Vilhelm Jensen, ẹlẹ́bùn Nobel ará Dẹ́nmárkì (al. 1950)
- 1931 – David Lee, ẹlẹ́bùn Nobel ará Amẹ́ríkà
- 1950 – Mahamane Ousmane, Ààrẹ orílẹ̀-èdè Niger
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1973 – Amilcar Cabral, olóṣẹ̀lú ará Guinea Bissau ati Cape Verde (ib. 1924)
- 1983 – Garrincha, agbábọ́ọ́lù ẹlẹ́sẹ ará Brasil (ib. 1933)
- 1988 – Khan Abdul Ghaffar Khan, alákitiyan ọmọ Pashtun (ib. 1890)
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1912 – Konrad Emil Bloch, ẹlẹ́bùn Nobel ará Jẹ́mánì (al. 2000)
- 1950 – Billy Ocean, ọlọ́rin ará Trinidad ati Tobago
- 1963 – Hakeem Olajuwon, agbábáskẹ́tì ọmọ Nàìjíríà ará Amẹ́ríkà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1793 – Ọba Louis 16k ilẹ̀ Fránsì (àwòrán) (ib. 1754)
- 1924 – Vladimir Lenin, olórí USSR (ib. 1870)
- 1950 – George Orwell, olùkọ̀wé ará Brítánì (ib. 1903)
- 1824 – Àwọn Ashanti borí àwọn ajagun ará Brítánì ní Gold Coast.
- 1879 – Ogun Anglo àti Zulu: Ìjà Isandlwana – Àwọn ajagun Zulu borí àwọn ajagun ará Brítánì.
- 2006 – Evo Morales di Ààrẹ ilẹ̀ Bolivia, òhun ni ààrẹ ọmọ ilẹ̀ abínibí àkọ́kọ́.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1561 – Francis Bacon, amòye ará Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì (al. 1626)
- 1788 – George Gordon Byron, Baron Byron 6k, akọewì ará Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì (al. 1824)
- 1891 – Antonio Gramsci, amòye ará Itálíà (al. 1937)
- 1931 – Sam Cooke (fọ́tò), akọrin ará Amẹ́ríkà (al. 1964)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1922 – Fredrik Bajer, olóṣèlú àti ẹlẹ́bùn Nobel ará Dẹ́nmárkì (ib. 1837)
- 1922 – Camille Jordan, onímọ̀ mathimátíkì ará Fránsì (ib. 1838)
- 1973 – Lyndon B. Johnson, Ààrẹ 36k Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà (ib. 1908)
- 1994 – Telly Savalas, òṣeré ará Amẹ́ríkà (ib. 1924)
- 1656 – Blaise Pascal ṣàtẹ̀jáde àkọ́kọ́ nínú àwọn Lettres provinciales rẹ̀.
- 1719 – Ilẹ̀ọmọba Liechtenstein jẹ́ dídásílẹ̀ nínú Ilẹ̀ọbalúayé Rómù Mímọ́.
- 1967 – Ìsọ̀kan Sófíẹ́tì àti Ivory Coast ṣèdásílẹ̀ ìbáṣepọ̀ díplómáti.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1862 – David Hilbert, onímọ̀ mathimátíkì ará Jẹ́mánì (al. 1943)
- 1929 – John Charles Polanyi, ẹlẹ́bùn Nobel ará Kánádà
- 1930 – Derek Walcott (fọ́tò), ẹlẹ́bùn Nobel ará Ìwọ̀ọrùn Índísì
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1744 – Giambattista Vico, amòye ará Itálíà (ib. 1668)
- 2002 – Pierre Bourdieu, onímọ̀ ọ̀rọ̀-àwùjọ ará Fránsì (ib. 1930)
- 2002 – Robert Nozick, amòye ará Amẹ́ríkà (ib. 1938)
- 1862 – Bucharest di olúìlú Romania.
- 1943 – Ogun Àgbáyé 2k: Franklin D. Roosevelt àti Winston Churchill parí ìpàdé ní Casablanca.
- 1986 – Voyager 2 kọjá bíi 81,500 km (50,680 miles) lẹ́gbẹ̀ẹ́ Úránù.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1679 – Christian Wolff, amòye ará Jẹ́mánì (al. 1754)
- 1862 – Edith Wharton, olùkọ̀wé ará Amẹ́ríkà (al. 1937)
- 1916 – Rafael Caldera, Ààrẹ orílẹ̀-èdè Venezuela (al. 2009)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1965 – Winston Churchill, Alákóso Àgbà ilẹ̀ Brítánì (ib. 1874)
- 1966 – Homi J. Bhabha, onímọ̀ físíksì ará Índíà (b. 1909)
- 1993 – Thurgood Marshall (fọ́tò), Onídájọ́ Ilé-Ẹjọ́ Gígajùlọ Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà (ib. 1908)
- 1575 – Luanda, olúìlú Angola jẹ́ dídásílẹ̀ látọwọ́ olùtọ́ṣọ́nà ará Potogí Paulo Dias de Novais.
- 1924 – Àwọn Ìdíje Òlímpíkì Ìgbà Otútù àkọ́kọ́ bẹ̀rẹ̀ ní ẹsẹ̀ Mont Blanc ní Chamonix, Haute-Savoie, France, pẹ̀lú àwọn eléré orí pápá bíi 200 láti àwọn orílẹ̀-èdè 16.
- 1971 – Idi Amin Dada fipágbàjọba ológun lọ́wọ́ Ààrẹ Milton Obote, láti bẹ̀rẹ̀ ìjọba ológun ọdún mẹ́jọ ní Ùgándà.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1627 – Robert Boyle, onímọ̀ kẹ́místrì ará Írẹ́lándì (al. 1691)
- 1736 – Joseph Louis Lagrange, onímọ̀ mathimátíkì ọmọ Itálíà (al. 1813)
- 1938 – Etta James (fọ́tò), akọrin ará Amẹ́ríkà (al. 2012)
- 1942 – Eusébio, agbábọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀ Pọ́rtúgàl
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1947 – Al Capone, olórí agbájọ ìwà ọ̀daràn ará Amẹ́ríkà (ib. 1899)
- 1994 – Stephen Cole Kleene, onímọ̀ mathimátíkì ará Amẹ́ríkà (ib. 1909)
- 2005 – Manuel Lopes, olùkọ̀wé ará Cape Verde (ib. 1907)
- 1837 – Michigan is admitted as the 26th U.S. state.
- 1924 – St.Petersburg is renamed Leningrad
- 1965 – Hindi becomes the official language of India.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1925 – Paul Newman, American actor, (d. 2008)
- 1937 – Joseph Saidu Momoh, aare ile Sierra Leone (d. 2003)
- 1944 – Angela Davis, alakitiyan ara Amerika
- 1958 – Anita Baker, American singer
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1697 – Georg Mohr, Danish mathematician (b. 1640)
- 1979 – Nelson Rockefeller, 41st Vice President of the United States (b. 1908)
- 2020 – Kobe Bryant, agbaboolubasket ara Amerika (ib. 1978)
- 1996 – Colonel Ibrahim Baré Maïnassara deposed Mahamane Ousmane, the first democratically elected president of Niger, in a military coup d'état.
- [[]]
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1756 – Wolfgang Amadeus Mozart, Austrian composer (d. 1791)
- 1832 – Lewis Carroll, English author (d. 1898)
- 1944 – Peter Akinola, Nigerian religious leader
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1814 – Johann Gottlieb Fichte, German philosopher (b. 1762)
- 1972 – Mahalia Jackson, American singer (b. 1911)
- 2009 – R. Venkataraman, 8th President of India (b. 1910)
- [[]]
- [[]]
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1948 – Charles Taylor, Ààrẹ ilẹ̀ Làìbéríà 22ji tẹ́lẹ̀
- 1955 – Nicolas Sarkozy, Ààrẹ ilẹ̀ Faransé tẹ́lẹ̀
- 1976 – Rick Ross, akọrin rap ará Amẹ́ríkà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 814 – Charlemagne (ib. 742)
- 1960 – Zora Neale Hurston, olùkọ̀wé ará Amẹ́ríkà (ib. 1891)
- [[]]
- [[]]
- [[]]
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1860 – Anton Chekhov, Russian writer (d. 1904)
- 1944 – Yoweri Museveni, President of Uganda
- 1954 – Oprah Winfrey, American talk show host and actress
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1993 – Adetokunbo Ademola, Nigerian Chief Justice (b. 1906)
- [[]]
- 1933 – Adolf Hitler is sworn in as Chancellor of Germany.
- 1956 – American civil rights leader Martin Luther King, Jr.'s home is bombed in retaliation for the Montgomery Bus Boycott.
- 2000 – Off the coast of Ivory Coast, Kenya Airways Flight 431 crashes into the Atlantic Ocean, killing 169.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1882 – Franklin D. Roosevelt, 32nd President of the United States (d. 1945)
- 1930 – Gene Hackman, American actor
- 1951 – Phil Collins, English musician
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1948 – Mohandas Karamchand Gandhi, Father of Nation, India (b. 1869)
- 1969 – Dominique Pire, Belgian monk, Nobel laureate (b. 1910)
- 2006 – Coretta Scott King, American activist (b. 1927)
Ọjọ́ 31 Oṣù Kínní: Independence Day ni Nauru (1968)
- 1929 – Ìsọ̀kan Sófìẹ̀tì lé Leon Trotsky kúrò ní ìlú.
- 1950 – Ààrẹ Harry S. Truman polohungo ètò ìdàgbàsókè bọ́mbù háídrójìn.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1919 – Jackie Robinson (fọ́tò), agbá baseball ará Amẹ́ríkà (al. 1972)
- 1923 – Norman Mailer, American writer and journalist (al. 2007)
- 1925 – Benjamin Hooks, American civil rights activist (al. 2010)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1933 – John Galsworthy, English writer, Nobel laureate (ib. 1867)
- 1973 – Ragnar Anton Kittil Frisch, Norwegian economist, Nobel laureate (ib. 1895)
- 1981 – Cozy Cole, American jazz drummer (ib. 1909)