Jump to content

Decolonise the Internet (Nigeria/Yorùbá Wikipedia)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Bí ó ṣe bẹ̀ré[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

àjọ jẹ́ àjọ kan tí ó ń mojú tó àṣà abínibí kan ní orílẹ̀-èdè agbáyé tí ó fìdí kalẹ̀ sí orílẹ̀-èdè Germany. Wọ́n ma ń gbé àṣà àti ìṣe orílẹ̀-èdè Germany lárugẹ jákè-jádò àgbáyé tí wọ́n sì ma ń tún ṣe alábàápín àṣà àti ibikíbi tí wọ́n bá ti dé láyé.

Àjọ Wikimedia User Group Nigeria (WUGN) náà jẹ́ ọ̀kan lára àwọn orísiríṣi ẹ̀ka Wikimedia Foundation Inc, tí ó kalẹ̀ sí agbègbè San Fransisco ní orílẹ̀-èdè USA tí ó jẹ́ àjọ tí kò dúró láti máa pawó sápò tí kìí sì ń ṣe ti ìjọba tí ó jẹ́ alákòóso gbogbo gbò fún àwọn ẹ̀ka wọn lágbàáyé ni wọ́n yọ̀nda fún ajọ Wikimedia Nigeria User Group lábẹ́ àkóso àṣẹ iṣẹ́ ọ̀fẹ́ wọn láti máa bá wọn polongo àwọn iṣẹ́ àkànṣe wọn gbogbo ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

Iṣẹ́ àkànṣe Decolonise the Internet[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ẹ̀Rọ ayélujára ni a rí gẹ́gẹ́ bí ohin èlò pàtàkì lásìkò yí, pàá pàá jùlọ ioa tí ó ń kó nínú ètò ìṣèlú àti ìṣe déédé láwùjọ wa gbogbo. Ní àsìkò àjàkálẹ̀ àrùn Covid-19 ní orílẹ̀ àgbáyé gbogbo, ẹ̀rọ ayélujára ni ó so wá pọ̀ tí ó sì fi ìfẹ́ wa síra wa rinlẹ̀ ṣi ṣin inú ọdún 2020. Ó yẹ kí á bèrè lọ́wọ́ ara wa ọ̀nà tí àwọn Artificial Intelligence, Algorithm àti àwọn bọ́ọ̀tì ṣe yí ìwòye wa padà nípa bí ayé ṣe ń lọ sí láì fi tẹ̀yà kankan ṣe. Èyí ni ó fàá ti àjọ Goethe ṣe gbé iṣẹ́ àkànṣe "Decolonise the Internet" kalẹ̀.

Ìdíje Decolonise the Internet[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ìdíje "Decolonise the internet" jẹ́ ìdíje kan tí a vbé kalẹ̀ láti fi bu ọlá fún awọn obìnrin tó fakọyọ jùlọ ní orílẹ̀-èdè àgbáyé pàá páà jùlọ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí a wà yí láì fi ti ẹ̀yà òun ẹ̀sìn ṣe. Bá kan náà ni a ń wá ẹni tí ó lè ṣe akọsílẹ̀ àwọn akòrí tuntun sí orí ìkanì Wikipedia.

The contest will focus on four Wikipedia projects namely: Ìdíje náà yóò dá lórí àwọn èdè mẹ́rin tí ó wà ní orílẹ̀-èdè.Nàìjíríà. Àwọn.ni:_

 1. Wikiledia Yorùbá
 2. Wikilefia Igbò
 3. Wikipedia Hausa àti
 4. Wikipedia Gẹ̀ẹ́sì.

Ìdíje náà yóò.wáyé láàrín 2nd sí 5th November 2020.

Àtòjọ Àwọn Àkòrí àwọn Obìnrin náà nìyí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 1. Dupsy Abiola
 2. Bilikis Adebiyi Abiola
 3. Ronke Ademiluyi
 4. Ọlájùmọ̀kẹ́ Adénọ́wọ̀
 5. Jackie Àìná
 6. Chief Tèmítọ́pẹ́ Àjàyí
 7. Nike Àkàndé
 8. Toyosi Akerele Ogunsiji
 9. Omoyemi Akerele
 10. Omowumi Akinifemisi
 11. Adenike Akinsemolu
 12. Folorunso Alakija
 13. Bolanle Austen-Peters
 14. Hannah Idowu Dideolu Awolowo
 15. Ibukun Oluwa Abiodun Awosika
 16. Quincy Olasumbo Ayodele
 17. Bunmi Banjo
 18. Banke Meshinda-Lawal
 19. Aduni Bankole
 20. Ola Brown
 21. Funke Bucknor-Obruthe
 22. Fola Coker
 23. Florence Ifeoluwa Otedola
 24. Shola David-Borha
 25. Bella Disu
 26. Temie Giwa-Tubosun
 27. Ade Hassan
 28. Amy Jadesimi
 29. Kehinde Kamson
 30. Alaba Lawson
 31. Ore Oluwalesi
 32. Lola Maja
 33. Abibatu Mogaji
 34. Tóún Òkèwálé Ṣónáìyà
 35. Ṣadé Ọkọ́ya
 36. Fúnkẹ́ Òpéke
 37. Tósìn Ọsìnọ́wò
 38. Fúnkẹ́ Òṣíbódù
 39. Roseline Òṣípìtàn
 40. Àlímọ́tù Péléwúrà
 41. Sahsa P
 42. Bọ́lá Ṣàgàyá
 43. Jọkẹ́ Silva
 44. Tẹ́ní
 45. Uduak Isong
 46. Ẹniọlá Badmus
 47. Adétóun Ògúnṣẹ̀yẹ
 48. Dúpẹ́ Olúṣọlá
 49. Témì Balógun
 50. Elizerbeth Abímbọ́lá Awoliyi
 51. Aríọlá Ọlásùnbọ̀ Sànyà
 52. Yétúndé Phillps
 53. Folashade Sherifat Jaji
 54. Folake Solanke
 55. Funmi Tejuosho
 56. Suzanne Iroche
 57. Lateefat Okunnu
 58. Titi Oyinsan
 59. Tonye Garrick
 60. Lara George
 61. Fifi Ejindu
 62. Olaoluwa Abagun
 63. Kemi Lala Akindoju
 64. Grace Alele-Williams
 65. josephine Anenih
 66. Oluwafunmilayo Olajumoke Atilade
 67. Ndid Nnoli-Edozien
 68. Olajumoke Adenowo
 69. Halima Tayo Alao
 70. Omotade Alalade
 71. Titilope Gbemisola Akosa
 72. Adetola Juyitan
 73. Ruka Sanusi
 74. Oby Ezekwesili
 75. Hauwa Ibrahim
 76. Ayesha Imam
 77. Mariama Keïta
 78. Ndid Nnoli-Edozien
 79. Jennifa Uchendu
 80. Nkiru Balonwu
 81. Jadesola Akande
 82. Aramide Sarumoh
 83. Olufunke Adeboye
 84. Adeola Olubamiji
 85. Deborah Ajakayie
 86. Mojisola Adeye
 87. Funke Abimbola
 88. Adeyinka Gladys Falusi
 89. Adenike Grange
 90. Simi Johnson
 91. Oluwatoyin Asojo
 92. Tejumade Alakija
 93. Sara Alade
 94. Ayo Ayoola-Amale
 95. Adejoke Ayoola
 96. Grace Ebun Delano
 97. Títílọlá Òbílàdé
 98. Jùmọ̀kẹ́ Odùwọlé
 99. Kate Okikiolu
 100. Margaret Ọládípọ̀
 101. Péjú Láyíwọlá
 102. Oluwayemisi Oluremi Obilade
 103. Ọmọ́wùmí Sadik
 104. Oyèrónkẹ́ Oyèwùmí
 105. Sophie Olúwọlé
 106. Yéwandé Olúbùmọ́
 107. Fúmi Ọlọ́níṣakin
 108. Grace Oladuni Taylor
 109. Ọláìtán Ṣóyanńwò
 110. Lindsey Abudei
 111. Ada Ehi
 112. Afro Candy
 113. Bella Alubo
 114. Amarachi
 115. Asikey
 116. Mercy Chinwo
 117. Nikki Laoye
 118. Demi Grace
 119. Maheeda
 120. Niniola
 121. Emma Nyra
 122. Sunkanmi Rehanat Alonge
 123. Temmie Ovwasa
 124. Yewande Omotoso
 125. Hafsat Abiola
 126. Smaranda Olarinde
 127. Iheoma Obibi
 128. Saudatu Mahdi
 129. Hadiza Bala Usman
 130. Oyinkansola Ayobami
 131. Nwando Achebe
 132. Cathrine Obianuju Acholonu
 133. Bisi Adeleye Fayemi
 134. Sandra Aguebor
 135. Judith Amaechi
 136. Nana Asma'u
 137. Joy Isi Bewaji
 138. Molara Ogundipe
 139. Julie Okoh
 140. Ayodele Olofintuade
 141. Chioma Opara
 142. Florence Ozor
 143. Yemisi Ransome Kuti
 144. Adanna Steinacker
 145. Bilikisu Yusuf
 146. Folashade Abugan
 147. Kemi Adekoya
 148. Aminat Adeniyi
 149. Sekinat Adesanya
 150. Florence Ajayi
 151. Airat Bakare
 152. Lola Akinmade Akerstrom
 153. Ebun Oyagbola
 154. Aduke Alakija
 155. Yewande Akinola
 156. Grace Oyelude
 157. Aderonke Kale
 158. Agness yewande Savage
 159. Remi Vaughan-Richard
 160. Ronke Odusanya
 161. Jumoke Odetola
 162. Kofoworola Ademola
 163. Dayo Amusa
 164. Abimbola Alao
 165. Uduak Archibong
 166. Sarah Jibril
 167. Leila Fowler
 168. Christie Ade Ajayi
 169. Abisoye Ajayi-Akinfolarin
 170. Uju Ohanenye
 171. Aishat Abubakar
 172. Olawunmi Banjo
 173. Sonya Clark
 174. Amina J. Mohammed- ígbákejì alaga fún Igbimọ gbogboogbo ti orilẹ-ede Agbaye
 175. Bilkisu Labaran
 176. Obianuju Ekeocha
 177. Iroro Tanshi
 178. Adeyinka Gladys Falusi
 179. Uko nkole