Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Oṣù Kàrún
Ọjọ́ 1 Oṣù Kàrún: Ọjọ́ àwọn Òṣìṣẹ́ Káàkiriayé
- 1852 – Owóníná pésò Filipínì bọ́ sí ìgboro.
- 1940 – Wọ́n fagilé Ìdíjé Òlímpíkì Ìgbà Oru 1940 nítorí ogun.
- 1948 – Orílẹ̀-èdè Olómìnira àwọn Ènìyàn Kòréà (Korea Àríwá) jẹ́ dídásílẹ̀, pẹ̀lú Kim Il-sung bíi olórí.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1852 – Santiago Ramón y Cajal, aṣesáyẹ́nsì ará Spéìn (al. 1934)
- 1919 – Mohammed Karim Lamrani, Alákóso Àgbà ilẹ̀ Mòrókò
- 1930 – Little Walter, akọri blues ará Amẹ́ríkà (al. 1968)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1976 – T.R.M. Howard, alákitiyan ẹ̀tọ́ aráàlú ará Amẹ́ríkà (ib. 1908)
- 1993 – Ranasinghe Premadasa, Ààrẹ ilẹ̀ Sri Lanka (ib. 1924)
- 1994 – Ayrton Senna (fọ́tò), awakọ̀ ìdíje ará Brasil (ib. 1960)
- 1611 – Bíbélì King James jẹ́ títẹ̀sìwé fún ìgbà àkọ́kọ́ ní London, England.
- 2004 – Ìparun ní Yelwa bá àwọn ada-ẹran bíi 630 ní Nigeria.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1843 – Elijah McCoy, oníhùmö ọmọ Kánádà (al. 1929)
- 1972 – Dwayne Johnson, ẹlẹ́mù àti òṣeré ará Amẹ́ríkà
- 1975 – David Beckham, agbábọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀ ará Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1519 – Leonardo da Vinci, oníhùmö àti akun-àwòrán ará Itálíà (ib. 1452)
- 1998 – Justin Fashanu, agbábọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀ ará Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì (ib. 1961)
- 2011 – Osama bin Laden, apaníra ará Saudi Arabia (ib. 1957)
- 1802 – Ìlú Washington, D.C. dí ìlú tó ní ìjọba.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1921 – Sugar Ray Robinson, ajaẹ̀ṣẹ́ ará Amẹ́ríkà (al. 1989)
- 1933 – James Brown (foto), akọrin ará Amẹ́ríkà (al. 2006)
- 1979 – Genevieve Nnaji, òṣeré ará Náìjíríà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1969 – Zakir Hussain, Ààrẹ ilẹ̀ Índíà 3k (ib. 1897)
- 2006 – Earl Woods, eléré-ìdárayá àti bàbá Tiger Woods (b. 1932)
- 2008 – Leopoldo Calvo Sotelo, Alákóso Àgbà ilẹ̀ Spéìn (b. 1926)
- 1904 – Orílẹ̀-èdè Amẹ̀ríkà bẹ̀rẹ̀ kíkọ́ Ìladò Panamá.
- 1959 – Àwọn Ẹ̀bùn Grammy wáyé fún ìgbà àkọ́kọ́.
- 1979 – Margaret Thatcher di obìnrin àkọ́kọ́ tó jẹ́ Alákóso Àgbà ilẹ̀ Brítánì.
- 2002 – Bàálù ìfòlókè EAS Airlines BAC 1-11-500 já bọ́ ní Kano, Nigeria lẹ́yìn ìgbàdíẹ̀ tó gbéra, àwọn ènìyàn tó tó 148 ni wọ́n kú.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1928 – Hosni Mubarak, Ààrẹ ilẹ̀ Egypti (al. 2020)
- 1930 – Katherine Jackson, ìyá àwọn ọmọ ẹbí Jackson olọ́rin
- 1953 – Oleta Adams, akọrin ará Amẹ́ríkà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 2012 – Rashidi Yekini, agbábọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀ ará Nàìjíríà (íb. 1963)
- 2014 – Jean-Paul Ngoupandé, Central African politician, Prime Minister of the Central African Republic (b. 1948)
- 2016 – Jean-Baptiste Bagaza, Burundian politician (b. 1946)
- 2006 – The government of Sudan signs an accord with the Sudan Liberation Army.
- 2007 – All 114 aboard Kenya Airways Flight 507 die when the pilots lose control of the plane and it crashes in Douala, Cameroon.
- 2010 – Goodluck Jonathan di Aare ile Naijiria leyin iku Umaru Musa Yar'Adua
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1813 – Søren Kierkegaard, Danish philosopher (d. 1855)
- 1818 – Karl Marx (foto), German political philosopher (d. 1883)
- 1989 – Chris Brown, American singer and actor
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1821 – Napoleon Bonaparte, olori ile Fransi (b. 1769)
- 2003 – Walter Sisulu, alákitiyan òṣèlú ará Gúúsù Áfríkà (ib. 1912)
- 2010 – Umaru Musa Yar'Adua, 12th president of Nigeria (b. 1951)
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1951 – Samuel Doe, Ààrẹ ilẹ̀ Làìbéríà (al. 1990)
- 1953 – Tony Blair, alákóso àgbà ilẹ̀ Brítánì (1997–2007)
- 1953 – Lynn Whitfield, òṣeré ará Amẹ́ríkà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1862 – Henry David Thoreau, olùkòwé ará Amẹ́ríkà (ib. 1817)
- 1992 – Marlene Dietrich, òṣeré ará Jẹ́mánì (ib. 1901)
- 1664 – Louis XIV of France inaugurates the Palace of Versailles.
- 1946 – Tokyo Telecommunications Engineering (later renamed Sony) is founded with around 20 employees.
- 1992 – The Space Shuttle Endeavour is launched on its first mission (STS-49).
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1840 – Pyotr Ilyich Tchaikovsky, Russian composer (d. 1893)
- 1861 – Rabindranath Tagore (foto), Indian writer, Nobel laureate (d. 1941)
- 1919 – Eva Perón, Argentine first lady (d. 1952)
- 1946 – Thelma Houston, American singer
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1946 – Herbert Macaulay, oloselu ara Naijiria (ib. 1864)
- 1998 – Allan McLeod Cormack, South African physicist, Nobel laureate (b. 1924)
- 1984 – The Soviet Union announces that it will boycott the 1984 Summer Olympics in Los Angeles, California.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1884 – Harry S. Truman, President of the United States (d. 1972)
- 1925 – Ali Hassan Mwinyi, President of Tanzania
- 1955 – Meles Zenawi, Ethiopian politician
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1794 – Antoine Lavoisier, French chemist (executed) (b. 1743)
- 1873 – John Stuart Mill, English philosopher (b. 1806)
- 1915 – Henry McNeal Turner, bísọ́ọ̀bù ará Amẹ́ríkà (ib. 1834)
- 1994 – Nelson Mandela di Ààrẹ ilẹ̀ Gúúsù Áfríkà
- 2001 – Ní Ghana àwọn alátìlẹ́yìn bọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀ kú nínú ìjàmbá tí à mọ̀ sí Accra Sports Stadium Disaster.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1927 – Manfred Eigen, German biophysicist
- 1939 – John Ogbu, onímọ̀ ẹ̀dá-ènìyàn ọmọ Nàìjíríà-Amẹ́ríkà (al. 2003)
- 1970 – Ghostface Killah, akọrin rap ará Amẹ́ríkà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1987 – Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀, olóṣèlú ará Nàìjíríà (ib. 1909)
- 1994 – Elias Motsoaledi, alákitiyan ará Gúúsù Áfríkà (ib. 1924)
- 2010 – Lena Horne, akọrin àti òṣeré ará Amẹ́ríkà (ib. 1917)
- [[]]
- 1994 - Nelson Mandela di Ààrẹ aláwọ̀dúdú àkọ́kọ́ orílẹ̀-èdè Gúúsù Áfríkà.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1878 – Gustav Stresemann, Chancellor of Germany (d. 1929)
- 1928 – Arnold Rüütel, President of Estonia
- 1942 – Youssouf Sambo Bâ, Burkinabé politician
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1989 – Woody Shaw, American jazz musician (b. 1944)
- [[]]
- 1820 – Ìfilọ́lẹ̀ HMS Beagle, ọkọ̀-ojúomi tó gbé Charles Darwin lọ sí ìrìn-àjò iṣẹ́ sáyẹ́nsì rẹ̀.
- 1927 – Ìdásílẹ̀ Akadẹ́mì Iṣẹ́ọnà Àwòrán Ìmúrìn àti Sayẹ́nsì.
- 1949 – Siam yí orúkọ oníbiṣẹ́ rẹ̀ sí Thailand fún ìgbà kejì. Orúkọ yìí ti jẹ́ lílò láti 1939 sùgbọ́n ó jẹ́ yíyípadà ní 1945.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1904 – Salvador Dalí, akun-àwòrán ará Spẹ́ìn (al. 1989)
- 1918 – Richard Feynman, aṣiṣẹ́ẹ̀dá ará Amẹ́ríkà (al. 1988)
- 1933 – Louis Farrakhan, olórí Nation of Islam ará Amẹ́ríkà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1934 – Blaise Diagne, olóṣèlú ará Sẹ̀nẹ̀gàl (ib. 1872)
- 1981 – Bob Marley (fọ́tò), olórin ará Jamáíkàn (ib. 1945)
- 1996 – Nnamdi Azikiwe, Ààrẹ Nàìjíríà àkọ́kọ́ (ib. 1904)
- 1881 – In North Africa, Tunisia becomes a French protectorate.
- 1965 – The Soviet spacecraft Luna 5 crashes on the Moon.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1937 – George Carlin (fọ́tò), aláwàdà ará Amẹ́ríkà (al. 2008)
- 1959 – Ving Rhames, òṣeré ará Amẹ́ríkà
- 1969 – Kim Fields, òṣeré ará Amẹ́ríkà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1801 – Nicholas Repnin, Russian statesman (b. 1734)
- 1986 – Alicia Moreau de Justo, Argentine human rights activist (b. 1885).
- 2006 – Hussein Maziq, Prime Minister of Libya (b. 1918)
- 1830 – Ecuador gba ìlómìnira látọwọ́ Gran Colombia.
- 1846 – Àwọn Ìpínlẹ̀ Àṣọ̀kan gbé ogun ti Mẹ́ksíkò.
- 1888 – Brasil pa okoẹrú run.
- 1950 – Ìyípo àkọ́kọ́ Ìdíje Àgbáyé Formula One wáyé ní Silverstone.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1914 – Joe Louis, ajẹ̀sẹ́ ará Amẹ́ríkà (al. 1981)
- 1950 – Manning Marable, ọ̀mọ̀wé ará Amẹ́ríkà (al. 2011)
- 1950 – Stevie Wonder (fọ́tò), olórin ará Amẹ́ríkà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1903 – Apolinario Mabini, Alákóso Àgbà Filipínì (ib. 1864)
- 1938 – Charles Edouard Guillaume, áṣiṣẹ́ẹ̀dá ará Swítsàlandì (ib. 1861)
- 2008 – Saad Al-Abdullah Al-Salim Al-Sabah, Sheikh ilẹ̀ Kùwáìtì (ib. 1930)
- 1607 – Jamestown, Virginia, Amẹ́ríkà jẹ́ títẹ̀dó gẹ́gẹ́ bíi ibi-àmúsìn Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì.
- 1963 – Kuwait dara pọ̀ mọ́ Àjọ àwọn Orílẹ̀-èdè.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1944 – George Lucas, olùdarí fílmù ará Amẹ́ríkà
- 1961 – Tim Roth, òṣeré ará Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì
- 1966 – Raphael Saadiq, akọrin ará Amẹ́ríkà (ọmọ ẹgbẹ́ olọ́rin Tony! Toni! Toné!)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1881 – Mary Seacole (àwòrán), ọlùtọ́jú aláìsàn ará Jamáíkà (ib. 1805)
- 1998 – Frank Sinatra, akọrin àti òṣeré ará Amẹ́ríkà (ib. 1915)
- 2015 – B.B. King, akọrin ará Amẹ́ríkà (ib. 1925)
Ọjọ́ 15 Oṣù Kàrún: Ọjọ́ Òmìnira ni Paraguay (1811)
- 1991 – Édith Cresson di alákóso àgbà ilẹ̀ Fránsì àkọ́kọ́ tó jẹ́ obìnrin.
- 1997 – Ọkọ̀-àlọbọ̀ Òfurufú Atlantis gbéra lórí STS-84 láti lọ fẹ̀gbẹ́ kan ibi-ìbùdó òfurufú Rọ́síà Mir.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1859 – Pierre Curie, onímọ̀ físíksì ará Fránsì (al. 1906)
- 1915 – Paul Samuelson, onímọ̀ òkòwò ará Amẹ́ríkà (al. 2009)
- 1965 – Raí, agbábọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀ ará Brasil
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1991 – Amadou Hampâté Bâ, olùkọ̀wé ará Málì (ib. c. 1900)
- 1993 – Salah Ahmed Ibrahim, olùkọ̀wé ará Sudan (ib. 1933)
- 2013 – Henrique Rosa, Ààrẹ ilẹ̀ Guinea-Bissau (ib. 1946)
- 1929 – Ní Hollywood, California, àwọn Ẹ̀bùn Akadẹ́mì àkọ́kọ́ jẹ́ pínpín.
- 2005 – Kuwait ṣòfin láti gba àwọn obìnrin láyè láti kópa nínú ìdìbò.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1931 – Natwar Singh, olóṣèlú ará Índíà
- 1966 – Janet Jackson (fọ́tò), akọrin ará Amẹ́ríkà
- 1968 – Ralph Tresvant, akọrin ará Amẹ́ríkà (New Edition)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1977 – Modibo Keita, Ààrẹ ilẹ̀ Málì àkọ́kọ́ (ib. 1915)
- 1979 – A. Philip Randolph, alákitiyan ẹ̀tọ́ aráàlú ará Amẹ́ríkà (ib. 1889)
- 1990 – Sammy Davis, Jr., onífàájì ará Amẹ́ríkà (ib. 1925)
- 1792 – Ìdásílẹ̀ Ilé Pàṣípàrọ̀ Owó New York.
- 1994 – Malawi ṣe ìdìbòyàn pẹ̀lú ẹgbẹ́ ọ̀ṣèlú púpọ̀ fún ìgbà àkọ́kọ́.
- 1997 – Àwọn ajagun Laurent Kabila wọ Kinshasa. Zaire yí orúkọ ibiṣẹ́ rẹ̀ padà sí Orílẹ̀-èdè Olómìnira Olóṣèlúaráìlú ilẹ̀ Kóngò (Àsìá).
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1936 – Dennis Hopper, òṣeré ará Amẹ́ríkà (al. 2010)
- 1956 – Sugar Ray Leonard, ajẹ̀sẹ́ ará Amẹ́ríkà
- 1966 – Hill Harper, òṣeré ará Amẹ́ríkà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1987 – Gunnar Myrdal, aṣiṣẹ́òkòwò ará Swídìn (ib. 1898)
- 2007 – T.K. Doraiswamy, olùkọ̀wé ará Índíà (ib. 1921)
- 2012 – Donna Summer, akọrin ará Amẹ́ríkà (ib. 1948)
Ọjọ́ 18 Oṣù Kàrún: Ọjọ́ Àsìá ní Hàítì
- 1900 – Orílẹ̀-èdè Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan sọ ilẹ̀ Tonga ibiàbò wọn.
- 2005 – Fọ́tò kejì tí wọ́n yà pẹ̀lú Tẹ́lískópù Òfurufú Hubble fihàn dájúdájú pé Plútò ní òṣùpá méjì míràn: Nix àti Hydra.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1872 – Bertrand Russell, amóye àti aṣiṣéonísirò ará Brítánì (al. 1970)
- 1912 – Walter Sisulu, alákitiyan òṣèlú ará Gúúsù Áfríkà (al. 2003)
- 1923 – Hugh Shearer, Alákósò Àgbà ará Jamáíkà (al. 2004)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1922 – Charles Louis Alphonse Laveran, oníṣègùn ará Fránsì (ib. 1845)
- 1955 – Mary McLeod Bethune (fọ́tò), olùkọ́ni àti alákitiyan ará Amẹ́ríkà (ib. 1875)
- 2004 – Elvin Jones, onílú jazz ará Amẹ́ríkà (ib. 1927)
- 1971 – Mars 2 jẹ́ fífilọ́lẹ̀ látọwọ́ Ìṣọ̀kan Sòfíẹ́tì.
- 1991 – Àwọn ará Kroatíà dìbò fún ìlómìnira.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1881 – Mustafa Kemal Atatürk, Ààrẹ ilẹ̀ Túrkì 1k (al. 1938)
- 1925 – Malcolm X (fọ́tò), alákitiyan ẹ̀tọ́ aráàlú ará Amẹ́ríkà (al. 1965)
- 1930 – Lorraine Hansberry, akọeré ará Amẹ́ríkà (al. 1965)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1864 – Nathaniel Hawthorne, olùkòwé ará Amẹ́ríkà (ib. 1804)
- 1989 – C. L. R. James, olùkọ̀wé ará Trínídàd àti Tòbágò (ib. 1901)
- 1994 – Jacqueline Kennedy Onassis, Ìyáàfin Àkọ́kọ́ Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà 1961-1963 (b. 1929)
Ọjọ́ 20 Oṣù Kàrún: Independence Day ni Cuba (1902) ati East Timor (2002)
- 526 – An earthquake kills about 300,000 people in Syria and Antiochia.
- [[]]
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1946 – Cher, American singer & actress
- 1952 – Roger Milla, Cameroonian footballer and manager
- 1972 – Busta Rhymes, American rapper and actor
Àwọn aláìsí lóòní...
- 2002 – Stephen Jay Gould, American paleontologist (b. 1941)
- 2005 – Paul Ricoeur, French philosopher (b. 1913)
- 2015 – Femi Robinson, Nigerian actor and playwright (b. 1940)
- 1851 – Oko ẹrú jẹ́ fífòfindè ní Kòlómbìà.
- 1904 – Fédération Internationale de Football Association (FIFA) jẹ́ dídásílẹ̀ ní Paris.
- 1991 – Mengistu Haile Mariam (fọ́tò), ààrẹ Orílẹ̀-èdè Olómìnira Olóṣèlú Ará ilẹ̀ Ethiópíà, sá kúrò ní Ethiopia, èyí mú òpin wá sí Ogun Abẹ́lé Ethiopia.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1688 – Alexander Pope, akọewì ọmọ Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì (al. 1744)
- 1941 – Ronald Isley, àkọrin ará Amẹ́ríkà (The Isley Brothers)
- 1972 – The Notorious B.I.G., rapper ará Amẹ́ríkà (al. 1997)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1670 – Niccolo Zucchi, atòràwọ̀ ará Itálíà (ib. 1586)
- 1964 – James Franck, ẹlẹ́bùn Nobel ará Jẹ́mánì (ib. 1882)
- 1991 – Rajiv Gandhi, Alákóso Àgbà ilẹ̀ Índíà (ib. 1944)
- 334 BC – The Macedonian army of Alexander the Great defeats Darius III of Persia in the Battle of the Granicus.
- 1990 – North and South Yemen are unified to create the Republic of Yemen.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1859 – Arthur Conan Doyle, British physician and writer (al. 1930)
- 1970 – Naomi Campbell, English model
- 1974 – Garba Lawal, Nigerian footballer
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1885 – Victor Hugo, French author (ib. 1802)
- 1967 – Langston Hughes (fọ́tò), American writer (ib. 1902)
- 1983 – Albert Claude, Belgian biologist, Nobel laureate in Medicine (ib. 1899)
- 1568 – The Netherlands declare their independence from Spain.
- 1995 – The first version of the Java programming language is released.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1707 – Carolus Linnaeus, Swedish botanist (d. 1778)
- 1973 – Maxwell, American singer-songwriter and producer
- 1986 – Ryan Coogler, American film director and screenwriter
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1857 – Augustin Louis Cauchy, French mathematician (b. 1789)
- 2009 – Roh Moo-hyun, 16th President of the Republic of Korea (b. 1946)
- 2017 – Roger Moore, English actor (b. 1927)
Ọjọ́ 24 Oṣù Kàrún: Ojọ́ Òmìnira ni Eritrea (1993)
- 1832 – Ilẹ̀-ọba Gírísì àkọ́kọ́ jẹ́ fífilọ́lẹ̀ ní London.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1938 – Prince Buster, olórin ará Jamaíkà (al. 2016)
- 1941 – Bob Dylan (foto), olórin ará Amẹ́ríkà
- 1944 – Patti LaBelle, akọrin ará Amẹ́ríkà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1543 – Nicolaus Copernicus, onímọ̀ ìràwọ̀ ará Pólándì (ib. 1473)
- 1974 – Duke Ellington, olórin ará Amẹ́ríkà (ib. 1899)
- 1992 – Hitoshi Ogawa, awakọ̀sáré ará Jèpánì (b. 1956)
Ọjọ́ 25 Oṣù Kàrún: Independence Day ni Jordan (1946); Africa Day (African Union)
- 1963 – In Addis Ababa, Ethiopia, the Organisation of African Unity is established.
- 1997 – A military coup in Sierra Leone replaces President Ahmad Tejan Kabbah with Major Johnny Paul Koromah.
- 2011 – Oprah Winfrey airs her last show, ending her twenty five year run of The Oprah Winfrey Show.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1925 – Shehu Shagari, Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
- 1970 – Octavia Spencer, American actress
- 1975 – Lauryn Hill, American singer
Àwọn aláìsí lóòní...
- 2009 - Ivan van Sertima, olukowe ara Guyana (ib. 1935)
- [[]]
Ọjọ́ 26 Oṣù Kàrún: Ọjọ́ Ìlómìnira ní Georgia(1918) àti Guyana (1966)
- 1983 – Ìmínlẹ̀ kíkan ìtóbi iye 7.7 ṣẹlẹ̀ ní Japan, èyí fa tsunami, tó fa ikú pa ènìyàn 104 àti tó pa ẹgbẹẹ̀gbẹ̀rún ènìyàn lára.
- 2008 – Àgbàrá ṣẹlẹ̀ ní apáìlàòrùn àti apágúsù Ṣáínà tó fa ikú ènìyàn 148 tó sì jẹ́ kí àwọn ènìyàn 1.3 ó kúrò nílé wọn.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1926 – Miles Davis, afọnfèrè, olórí ẹgbẹ́-alùlù àti akórinjọ ará Amẹ́ríkà (al. 1991)
- 1929 – J.F. Ade Ajayi, akọìtàn ará Nàìjíríà (al. 2014)
- 1949 – Pam Grier (foto), òṣeré ará Amẹ́ríkà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1976 – Martin Heidegger, amòye ará Jẹ́mánì (ib. 1889)
- 2002 – Mamo Wolde, asáré ará Ethiópíà (ib. 1932)
Ọjọ́ 27 Oṣù Kàrún: Ojo awon Omode ni Nigeria
- 1967 - Ìdásílẹ̀ àwọn Ìpínlẹ̀ Rivers, Èkó, Kwara, Kano, Kaduna àti Cross River ní Nàìjíríà
- 1999 – The International Criminal Tribunal for the former Yugoslavia in The Hague, Netherlands indicts Slobodan Milošević and four others for war crimes and crimes against humanity committed in Kosovo.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1860 – Manuel Teixeira Gomes, 7th President of Portugal (d. 1941)
- 1936 – Louis Gossett Jr., American actor
- 1971 – Lisa Lopes, American singer (TLC) (d. 2002)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1964 – Jawaharlal Nehru, Indian politician (b. 1889)
- 1986 – Isma'il Raji al-Faruqi, Palestinian-born philosopher (b. 1921)
- 1987 – John Howard Northrop, American chemist, Nobel laureate (b. 1891)
- 1936 – Alan Turing fi On Computable Numbers sílẹ̀ fún ìtẹ̀jáde.
- 1964 – Ìdásílẹ̀ Àgbájọ Ìtúsílẹ̀ Palẹstínì.
- 1975 – Àwọn orìlẹ̀-èdè mẹ́ẹ̀dógún Ìwọ̀òrùn Áfríkà tọwọ́bọ̀wé sí Àdéhùn ìlú Èkó láti ṣèdásílẹ̀ Àgbàjọ Òkòwò àwọn Orílẹ̀-èdè Ìwọòrùn Áfríkà (Àsìá).
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1912 – Patrick White, olùkọ̀wé ará Australíà (al. 1990)
- 1936 – Betty Shabazz, Alákitiyan ará Amẹ́ríkà (al. 1997)
- 1944 – Gladys Knight, akọrin R&B àti soul ará Amẹ́ríkà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1953 – Hori Tatsuo, olùkọ̀wé ará Japan (ib. 1904)
- 2003 – Ilya Prigogine, aṣiṣẹ́olóògùn ará Bẹ́ljíọ̀m (ib. 1917)
- 2010 – Gary Coleman, òṣeré ará Amẹ́ríkà (ib. 1968)
Ọjọ́ 29 Oṣù Kàrún: Ọjọ́ Òṣèlú ní Nàìjíríà
- 1973 – Tom Bradley jẹ́ dídìbòyàn bíi aláwọ̀dúdú àkọ́kọ́ baálẹ̀ Los Angeles, California.
- 1990 – Iléaṣòfin Rọ́síà dídìbòyàn Boris Yeltsin bí Ààrẹ Rọ́síà Sófìẹ̀tì.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1917 – John F. Kennedy (fọ́tò), Ààrẹ 35k Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà (al. 1963)
- 1926 – Abdoulaye Wade, Ààrẹ ilẹ̀ Sẹ̀nẹ̀gàl
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1958 – Juan Ramón Jiménez, olùkọ̀wé ará Spéìn (ib. 1881)
- 2010 – Dennis Hopper, òṣeré ará Amẹ́ríkà (ib. 1936)
- 1966 – Won fikupa Alakoso Agba orile-ede Kongo tele Evariste Kimba ati awon oloselu bi melo kan ni Kinshasa leyin ase latowo Aare Joseph Mobutu.
- 1967 – Agbègbè Apáìlàoòrùn Nàìjíríà pe ra won ni olominira gege bi Orile-ede Biafra, eyi lo fa ibere ogun abele ni Nàìjíríà.
- 1998 – Iminle to lagbara to 6.6 lori iwon Richter sele ni apa-ariwa Afghanistan, o fikupa 5,000 eniyan.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1814 – Mikhail Bakunin, alaifejoba ara Russia (al. 1876)
- 1908 – Hannes Alfvén, onimofisiksi ara Sweden (al. 1995)
- 1974 – Big L, akorin rap ara Amerika (al. 1999)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1778 – Voltaire, onimoye ati akowe ara Fransi (ib. 1694)
- 1960 – Boris Pasternak, akowe ara Russia, elebun Nobel (ib. 1890)
- 1964 – Oba Akinyele, Olubadan (ib. 1882)
- 1279 BC – Rámésè 2k (Ẹni Únlá ti ìran-ọba 19k) di Fáráò ilẹ̀ Ẹ́gíptì Ayéijọ́un.
- 1910 – Ìdásílẹ̀ Ìṣọ̀kan ilẹ̀ Gúsù Áfríkà.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1916 – Hubert Ògúndé, òṣeré ará Nàìjíríà (al. 1990)
- 1930 – Clint Eastwood, òṣeré àti olùdarí fílmù ará Amẹ́ríkà
- 1945 – Laurent Gbagbo, Ààrẹ ìkẹrin ilẹ̀ Kót Dìfuà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1832 – Évariste Galois, onímọ̀ matimátííkì (ib. 1811)
- 1983 – Jack Dempsey, ajẹ̀ṣẹ́ ará Amẹ́ríkà (ib. 1895)