David Mark
David Alechenu Bonaventure Mark | |
---|---|
Ààrẹ ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga Ọjọ́ kẹfà Oṣù kẹfà Ọdún 2007 | |
Deputy | Ike Ekweremadu |
Asíwájú | Ken Nnamani |
Constituency | Gúúsù Benue |
Ààrẹ ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà. | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga Oṣù kẹrin Ọdún 2003 | |
Gómínà Ìpínlẹ̀ Niger | |
In office Oṣù kínín 1984 – 1986 | |
Asíwájú | Awwal Ibrahim |
Arọ́pò | Garba Ali Mohammed |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Oṣù kẹrin 1948 Zungeru, Niger State[1] |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | PDP |
David Alechenu Bonaventure Mark (bíi ní Oṣù kẹrin Ọdún 1948) jẹ́ ológun tí ó ti fẹ̀hìntì àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú Ìpínlẹ̀ Benue ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin lẹ́yìn tí ó wọlé látàrí ètò ìdìbò ti oṣù kẹrin ọdún 2007 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[3] Ó jẹ́ ààrẹ ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin.[4][5]
Ìgbé ayé àti Èkó rè
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]A bí Mark si ìlú Otukpo ní ìpínlè Benue ni osù kerin odun 1948. O lo si ilé-ìwé St. Francis Catholic Practicing ko to look since ilé-ìwé àwon ologun. Léyìn náà, o tun lo kàwé ni Nigeria Defense Academy.[4] Wón so di 2nd Lieutenant ni odun 1970, wo si tun so di Captaini ni odun 1971, ótún padà di alaga Abandoned Properties implementation Committee ni iwo ilà oòrùn ni odun 1976.
Minisita
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Mark jé olori Ministry of Communication àti àwon èka rè: Nigerian Telecommunications Limited(NITEL) àti Nigerian Postal Service(NIPOST).
Aare ìgbìmò asofin agba ti Nàìjirià
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]A yan Mark gégé bi ààré ilé ìgbìmò asofin àgbà ti Naijiria ní ojó kefa, osu Kefa odun 2007. [6]
David tún díje fun Senato agbègbè Benue South lekan si ni osu kerin odun 2011, a si yan fun isejoba kerin.[7] David so pe idibo àwon eniyan ni o gbé depo, o si so fún àwon olutako rè láti sisé papò láti tún Nàìjíríà se.[5]
Nígbà ti àwon ilé ìgbìmò asofin un tún òfin Nàìjíríà se, Mark so fun àwon Senato tó kù rè láti fi àwon omo Nàìjirià si wajú ara won.[8]
Léyìn ìgbà ti àwon orílè-èdè United Kingdom satako si Nàìjirià, won si so pé wón ma se idaduro si àwon iranlowo ti wón un fun Nàìjirià. Mark so pe ki wón fi iranlowo won pa mó.[9]
Ni osu kesan odun 2018, Mark ni ipinu láti díje fun ipò ááre orílè-èdè Nàìjirià, o si yan Zainab Abdulkadir Kure ati Abba Ejemni si egbe ti o ma sé idari ipolongo ìdíje rè.[10]
Ìgbé ayé rè
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]O feran eré idaraya golf, tennis àti Squash.[11] O je Christieni, èyà Idoma sì ni èyà rè. O ni ìyàwó merin sí marun.>[12]
Mark ni ilé àti Helicopter ati ìbi ibalesi fún Helicopter. .[13]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Zungeru: The abandoned first capital city of Nigeria". Nigerian Tribune online (African Newspapers of Nigeria). 2007-10-28. http://www.tribune.com.ng/28102007/features.html. Retrieved 2007-11-03.
- ↑ Nkwazema, Stanley; Chuks Okocha and Juliana Taiwo (2007-11-02). "House Defies PDP, Elects Bankole Speaker". Thisday online (Leaders & Company). Archived from the original on 2007-11-03. https://web.archive.org/web/20071103162057/http://www.thisdayonline.com/nview.php?id=94039. Retrieved 2007-11-03.
- ↑ "Senator David Mark". National Assembly of Nigeria. Archived from the original on 2007-09-25. Retrieved 2007-11-03.
- ↑ 4.0 4.1 "Childhood". Senate President. Archived from the original on 22 December 2011. Retrieved 7 May 2012.
- ↑ 5.0 5.1 "Benue: David Mark in controversial re-election win". New Nigerian Politics. 10 April 2011. Archived from the original on 14 April 2011. https://web.archive.org/web/20110414014252/http://newnigerianpolitics.com/2011/04/10/benue-david-mark-in-controversial-re-election-win/. Retrieved 7 May 2012.
- ↑ Aziken, Emmanuel (2007-10-12). "Marked for Battle - Akume Battles Mark for Senate Presidency". Vanguard (AllAfrica Global Media). http://allafrica.com/stories/200710120133.html.
- ↑ Rotimi Akinwumi and Akinwunmi King (Apr 12, 2011). "Mark, Tinubu, Nnamani, others greet Ngige, as APGA rejects Anambra results". Daily Independent.
- ↑ "No Fixed Position On Constitution Review – David Mark". Zimbio. 27 April 2013. http://www.zimbio.com/Nigeria+Today/articles/_KV85aTyaJS/No+Fixed+Position+Constitution+Review+David.
- ↑ Fisher, Jonah (5 December 2011). "Nigerian leaders unite against same-sex marriages". BBC News. https://www.bbc.co.uk/news/world-africa-15992099.
- ↑ Itodo, Yemi (2018-09-12). "David Mark makes new appointments for his campaign organization". Daily Post Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-05-05.
- ↑ "Senate President Profile". Senate President. Archived from the original on 18 June 2012. Retrieved 7 May 2012.
- ↑ "Scam ATM Card Payment Money Transfers Example - David Mark". Consumer Fraud Reporting.
- ↑ "David Mark's House in Benue State Has a Helicopter Landing Space on its Roof". Archived from the original on 2016-08-14. Retrieved 2015-08-11. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)
- Pages using duplicate arguments in template calls
- Pages containing cite templates with deprecated parameters
- CS1 Èdè Gẹ̀ẹ́sì-language sources (en)
- Pages with citations using unsupported parameters
- Pages using infobox officeholder with unknown parameters
- Àwọn ọjọ́ìbí ní 1948
- Àwọn ènìyàn alààyè
- Àwọn Gómìnà Ìpínlẹ̀ Niger
- Àyọkà kúkurú